Ojú ìwé 2
Àwọn Obìnrin Kí Ló Wà Níwájú fún Wọn? 3-14
Nígbà púpọ̀ ni àwọn obìnrin ti ń jìyà ìyàsọ́tọ̀ àti ìwà ipá. Ṣùgbọ́n láìpẹ́, ipò wọn yóò yí padà lọ́nà kíkọyọyọ.
Òbéjé Lẹ́nu Ọ̀nà Wa 16
Ṣíṣàyẹ̀wò ẹran omi kan tó ṣàrà ọ̀tọ̀.
Àwọn Ẹ̀mí Èṣù Ha Wà ní Tòótọ́ Bí? 18
Ǹjẹ́ àwọn ẹ̀mí èṣù wà? Kí ni Bíbélì wí?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
ÀWỌN FỌ́TÒ Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Lápá òsì lókè àti lápá ọ̀tún nísàlẹ̀: Godo-Foto
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda onínúure Dókítà Tony Preen