Ojú ìwé 2
Ẹranko Ọlọ́pọlọ-Pípé Lásán Ni Ènìyàn Bí? 3-11
Kí ní ń tìdí gbígbàgbọ́ pé inú ẹranko ni a ti hú yọ jáde? Báwo ni ènìyàn ṣe yàtọ̀ sí ẹranko tó? Ìyàtọ̀ wo ló wà nínú pé a gbà gbọ́ nínú ẹfolúṣọ̀n tàbí nínú ìṣẹ̀dá?
Bí O Ṣe Lè Yẹra fún Àwọn Ewu Àkókò Ìsinmi 15
Ìmúrasílẹ̀ wo ni ó yẹ? Kí ló lè mú kí a gbádùn ìsinmi?
Ìlérí Tí Mo Múra Tán Láti Mú Ṣẹ 20
Kà nípa ìlérí tí sójà ilẹ̀ Soviet kan ṣe ní ohun tí ó lé ní 50 ọdún sẹ́yìn àti àwọn ìdánwò tí ó ti forí tì láti mú un ṣẹ.