ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g99 9/8 ojú ìwé 2
  • Ojú ìwé 2

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ojú ìwé 2
  • Jí!—1999
  • Ìsọ̀rí
  • Ṣópin Ti Dé Bá Ẹ̀rù Ohun Ìjà Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé Tó Ń Bà Wá Ni? 3-11
  • Ojú Ìwòye Bíbéli 12
  • Sísin Ọlọ́run ní Bèbè Ikú 14
Jí!—1999
g99 9/8 ojú ìwé 2

Ojú ìwé 2

Ṣópin Ti Dé Bá Ẹ̀rù Ohun Ìjà Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé Tó Ń Bà Wá Ni? 3-11

Nígbà tí Ọ̀tẹ̀ Abẹ́lẹ̀ parí, ọ̀pọ̀ èèyàn ló dunnú pé aráyé ti bọ́ nínú bíbẹ̀rù ogun ọ̀gbálẹ̀gbáràwé. Àmọ́, ọ̀wọ́ àwọn àpilẹ̀kọ yìí gbé díẹ̀ lára ìdí tí ewu tó so mọ́ ohun ìjà ọ̀gbálẹ̀gbáràwé fi pọ̀ ju bí ọ̀pọ̀ èèyàn ṣe rò lọ.

Ojú Ìwòye Bíbéli 12

Kí Ni Ojúṣe Ẹni Rere Nílùú?

Sísin Ọlọ́run ní Bèbè Ikú 14

Wọ́n fòòró ẹ̀mí rẹ̀, wọ́n sì fi í sẹ́wọ̀n àti àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ fún ọ̀pọ̀ ọdún ṣùgbọ́n ó fara dà á. Ka ìtàn tí ń gbéni ró nípa ọkùnrin ará Áfíríkà yìí.

[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]

Àwòrán ìbúgbàù tó wà lẹ́yìn ìwé: UNITED NATIONS/PHOTO BY SYGMA

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́