Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
March 8, 2000
Ìfiniṣẹrú Lóde Òní—Òpin Rẹ̀ Dé Tán!
Ẹgbàágbèje èèyàn, pàápàá jù lọ àwọn obìnrin àti àwọn ọmọdé, ni àwọn èèyàn ń lò bí ẹrú. Báwo ni àṣà ìfiniṣẹrú yìí yóò ṣe kásẹ̀ ńlẹ̀?
9 Ìfiniṣẹrú Lóde Òní—Òpin Rẹ̀ Dé Tán!
17 Gbígbẹ̀mí Ara Ẹni—Ìṣòro Ńlá Tó Ń Yọ́ Kẹ́lẹ́ Ṣọṣẹ́
19 Gbogbo Èèyàn Ló Ń Fẹ́ Láti Wà Láàyè
26 Ǹjẹ́ Wọ́n Á Gba Òmìnira Ẹ̀rí-Ọkàn Láyè Fàlàlà ní Mẹ́síkò?
28 Ìyàtọ̀ Tó Wà Láàárín Ọlọ́rọ̀ àti Tálákà Ń Pọ̀ Sí I
29 Wíwo Ayé
32 “Ó Yẹ Kí N Gbẹ́kẹ̀ Lé Ọlọ́run”
Kí Ló Dé Táwọn Ọ̀rẹ́ Mi Fi Máa Ń Ṣe Nǹkan Tó Dùn Mí? 13
Nígbà míì, àwọn ọ̀rẹ́ máa ń kẹ̀yìn síra. Báwo lèyí ṣe ń ṣẹlẹ̀? Kí lo lè ṣe sí i?
Ìgbàgbọ́ oréfèé túmọ̀ sí yíyára gba nǹkan gbọ́ láìjanpata, láìwádìí. Ó yẹ ká gbé ìgbàgbọ́ karí ẹ̀rí tó dájú. Èwo ni Bíbélì tì lẹ́yìn?
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Láti òkè lápá ọ̀tún: FỌ́TÒ ÀJỌ UN 148000/Jean Pierre Laffont; ÌPARAPỌ̀ ÀWỌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ/ J.P. LAFFONT; J.R. Ripper/RF2; J.R. Ripper/RF2; FỌ́TÒ ÀJỌ UN 152227 tí John Isaac yà
ÌPARAPỌ̀ ÀWỌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ/J.P. LAFFONT
Àwòrán tí Albrecht Dürer yà/Dover Publications, Inc.