Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 8, 2001
Ìrànwọ́ fún Àwọn Obìnrin Tọ́kọ Wọn Ń Lù
Kárí ayé, àwọn obìnrin kan máa ń jẹ palaba ìyà lọ́wọ́ àwọn ọkọ wọn. Wọn tiẹ̀ ń pa àwọn mìíràn pàápàá. Báwo làwọn obìnrin ṣe lè dáàbò bo ara wọn?
3 “Bóyá Ó Máa Yí Padà Lọ́tẹ̀ Yìí”
5 Kí Ló Dé Táwọn Ọkùnrin Kan Fi Máa Ń Lu Ìyàwó Wọn?
9 Ìrànwọ́ fún Àwọn Obìnrin Tí Ọkọ Wọn Ń Lù
11 “Bí Àlá Ló Máa Ń Rí Lójú Mi Nígbà Míì!”
15 Ohun Tó Ń mú Káyé Sú Àwọn Èèyàn Kan
28 Màmá Àtàwọn Ọmọbìnrin Rẹ̀ Mẹ́wàá
30 ‘Òfo ni Àyẹ̀wò Ọ̀hún Já Sí’
31 Ènìyàn Ti Fìyà Jẹ Ènìyàn Ẹlẹgbẹ́ Rẹ̀
32 Báwo Ló Ṣe Yẹ Káwọn Òbí Máa Bá Àwọn Ọmọ Wọn Wí?
Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Gbẹ̀san?
Ṣé Lílò Tí Ọlọ́run Ń Lo Agbára Rẹ̀ Láti Pa Àwọn Ẹni Ibi Run Tọ̀nà?