ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g05 2/8 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Jí!—2005
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àìfararọ Tó Láǹfààní, Àìfararọ Tó Lewu
    Jí!—1998
  • Àníyàn Ṣíṣe Ń Da Aráyé Ríborìbo!
    Jí!—2005
  • Àníyàn Ṣíṣe Ohun Tó Ń Fà Á àti Ọṣẹ́ Tó Máa Ń Ṣe
    Jí!—2005
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2020
Àwọn Míì
Jí!—2005
g05 2/8 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

February 8, 2005

Ìtura Fáwọn Tó Ń Ṣàníyàn!

Ọ̀pọ̀ ògbógi gbà pé ṣíṣàníyàn léwu gidigidi fún ìlera ara. Kí ni díẹ̀ lára àwọn ohun tó ń fa àníyàn ṣíṣe? Kà nípa àwọn nǹkan díẹ̀ tó lè ràn ọ́ lọ́wọ́ tí àníyàn ṣíṣe ò fi ní dá ọ lágara.

3 Àníyàn Ṣíṣe Ń Da Aráyé Ríborìbo!

4 Àníyàn Ṣíṣe Ohun Tó Ń Fà Á àti Ọṣẹ́ Tó Máa Ń Ṣe

7 Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Àníyàn Ṣíṣe Dá Ọ Lágara

12 Ǹjẹ́ O Mọ̀?

13 Ayé Ń Lọ À Ń Tọ̀ Ọ́ Lọ̀rọ̀ Àwọn Dókítà

15 Ìdààmú Àwọn Dókítà

18 Ibo Lọ̀rọ̀ Iṣẹ́ Ìṣègùn Máa Já sí Lọ́jọ́ Iwájú?

24 Aṣọ Hanbok Aṣọ Àwọn Ará Korea

29 Bí Wọ́n Ṣe Borí Jìnnìjìnnì Tó Bá Wọn Nígbà Táwọn Apániláyà Yin Bọ́ǹbù

32 Ọ̀kan Pàtàkì Ni Ìwé Náà Jẹ́ Fáwọn Ọ̀dọ́ Ọ̀

Ẹ Máa Wáyè Gbọ́ Tàwọn Ọmọ 22

Kí ló yẹ káwọn òbí ṣe kí wọ́n lè máa ráyè gbọ́ tàwọn ọmọ wọn?

Kí Ni Kí N Ṣe Bí Àwọn Míì Bá Fọ̀rọ̀ Wọn Lọ̀ Mí? 26

Ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀dọ́ ni wọ́n ń fẹ́ ẹni táwọn lè fọ̀rọ̀ pa mọ́ sí lọ́wọ́. Ṣùgbọ́n kí ló yẹ kó o ṣe bó o bá rí i pé ìṣòro tí ọ̀rẹ́ rẹ ń fi lọ̀ ẹ́ ti kọjá agbára ẹ?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́