Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October–December 2007
Gba Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Ewu!
Léyìí tí àwọn tó ń dọdẹ àwọn ọmọdé nítorí àtibá wọn ṣèṣekúṣe ti wá pọ̀ lóde báyìí, àfi káwọn òbí yáa mọ bí wọ́n ṣe lè dáàbò bo àwọn ọmọ wọn. Àwọn àpilẹ̀kọ mẹ́ta tó ṣáájú nínú ìwé ìròyìn yìí lè ràn yín lọ́wọ́.
3 Ewu Tí Gbogbo Òbí Ń Kọminú Lé Lórí
4 Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Yín
9 Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Mú Kí Ilé Yín Jẹ́ Ibi Ààbò
21 Ọ̀nà 1 Wá Ìmọ̀ràn Tó Dáa Gbà
22 Ọ̀nà 2 Jẹ́ Kí Ilé Rẹ Jẹ́ Ilé Aláyọ̀
23 Ọ̀nà 3 Lo Àṣẹ Rẹ Gẹ́gẹ́ Bí Òbí
24 Ọ̀nà 4 Jẹ́ Kí Ìlànà Wà Tí Ìdílé Gbọ́dọ̀ Máa Tẹ̀ Lé
25 Ọ̀nà 5 Jẹ́ Kí Olúkúlùkù Mọ Iṣẹ́ Táá Máa Ṣe Nínú Ilé
26 Ọ̀nà 6 Máa Gbọ́ Àwọn Ọmọ Ẹ Lágbọ̀ọ́yé
27 Ọ̀nà 7 Jẹ́ Káwọn Ọmọ Rí Ẹ̀kọ́ Kọ́ Lára Ẹ
32 “Àpéjọ Àgbègbè “Máa Tọ Kristi Lẹ́yìn!” Ti Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ Sẹ́ni Tó Bá Kú? 30
Àwọn kan ṣì gbà gbọ́ pé òkú kì í sùn lọ́rùn. Àmọ́, kí ni Bíbélì sọ nípa ohun tó máa ń ṣẹlẹ̀ sẹ́ni tó bá kú?