October Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ewu Tí Gbogbo Òbí Ń Kọminú Lé Lórí Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Yín Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Mú Kí Ilé Yín Jẹ́ Ibi Ààbò Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dá Ìjíròrò Dúró Kó Tó Dọ̀rọ̀ Ẹ̀yìn? Kí Ni Kí N Ṣe Bí Mo Bá Lọ Gbé Nílùú Tí Àṣà Tàbí Èdè Wọn Yàtọ̀ Sí Tèmi? Kí Ni Kí N Ṣe Báwọn Òbí Mi Bá Ń Jiyàn? Wá Ìmọ̀ràn Tó Dáa Gbà Jẹ́ Kí Ilé Rẹ Jẹ́ Ilé Aláyọ̀ Lo Àṣẹ Rẹ Gẹ́gẹ́ Bí Òbí Jẹ́ Kí Ìlànà Wà Tí Ìdílé Gbọ́dọ̀ Máa Tẹ̀ Lé Jẹ́ Kí Olúkúlùkù Mọ Iṣẹ́ Táá Máa Ṣe Nínú Ilé Máa Gbọ́ Àwọn Ọmọ Ẹ Lágbọ̀ọ́yé Jẹ́ Káwọn Ọmọ Rí Ẹ̀kọ́ Kọ́ Lára Ẹ Ṣé Ìjọsìn Ọlọ́run Máa Ń Mú Kéèyàn Láyọ̀? Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ Sẹ́ni Tó Bá Kú? “Àpéjọ Àgbègbè “Máa Tọ Kristi Lẹ́yìn!” Ti Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà