Ǹjẹ́ Ó Wù Ẹ́ Láti Lóye Bíbélì?
● Ẹgbẹẹgbẹ̀rún èèyàn ló ti lóye Bíbélì nípasẹ̀ ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì náà, Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? Díẹ̀ rèé lára àkòrí mọ́kàndínlógún tó wà nínú ìwé náà:
“Kí Ni Òtítọ́ Nípa Irú Ẹni Tí Ọlọ́run Jẹ́?”
“Ta Ni Jésù Kristi?”
“Ibo Làwọn Òkú Wà?”
“Ṣé ‘Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn’ La Wà Yìí?”
“Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé?”
“Ohun Tó O Lè Ṣe Kí Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀”
Tó o bá fẹ́ kí ẹnì kan máa wá kọ́ ẹ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tó o sì fẹ́ gba ẹ̀dà ìwé yìí, kọ̀wé sínú fọ́ọ̀mù tó wà nísàlẹ̀ yìí, kó o sì fi ránṣẹ́ sí àdírẹ́sì tó bá yẹ lára èyí tá a tò sí ojú ewé 5 nínú ìwé ìròyìn yìí.
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 32]
□ Mo fẹ́ gba ẹ̀dà kan ìwé yìí.
Kọ èdè tó o fẹ́.
□ Ẹ jọ̀wọ́, ẹ wá máa kọ́ mi lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì inú ilé lọ́fẹ̀ẹ́.