July Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí “Mo Kàn Ní Kí N gba Ohun Tí Wọ́n Fi Ránṣẹ́ Sí Mi Ni” Ìdí Tí Àwọn Kan Fi Ń hùwà Ipá Ǹjẹ́ Ìgbà Kan Ń bọ̀ Tí Àwọn Apániláyà Ò Ní Sí mọ́? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Rí Ọ̀rẹ́ Tí Ọ̀rọ̀ Wa Bára Mu? Bí Mo Ṣe Jáwọ́ Nínú Ìwà Jàgídíjàgan Ìrìn Àjò Síbi Tí Wọ́n Ti Ń ṣe Òwò Ẹrú Ǹjẹ́ Ètè Rẹ Jẹ́ “Ohun Èlò Tí ó Ṣeyebíye”? Ìdí Tó Fi Yẹ Kó O Máa Ṣọ́ Ẹnu Rẹ Kí Nìdí Tí Wọ́n fi Kórìíra Ojúlówó Àwọn Ọmọlẹ́yìn Jésù? Ṣé Ibi Gbogbo Ni Ọlọ́run Wà? Kí Ló Dé Témi Ò fi Mọ Nǹkan Kan Ṣe? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Káwọn Èèyàn Ní Èrò Tó Dáa Nípa Mi Nígbà Tí Wọ́n Bá Kọ́kọ́ Rí Mi? Ǹjẹ́ Ó Wù Ẹ́ Láti Lóye Bíbélì?