Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Sún Mọ́ Jèhófà
Ibi Tá A Ti Mú Àwọn Àwòrán: ▪ Ojú ìwé 49: Nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda Anglo-Australian Observatory, David Malin ló ya fọ́tò rẹ̀ ▪ Ojú ìwé 174: U.S. Fish & Wildlife Service, Washington, D.C./Wyman Meinzer ▪ Ojú ìwé 243: © J. Heidecker/VIREO
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.
A Tẹ̀ Ẹ́ ní May 2024
Yoruba (cl-YR)
© 2002, 2014, 2024
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA