Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Orí
2 Ṣé Òótọ́ Ni Pé O Lè “Sún Mọ́ Ọlọ́run”? 16
3 “Mímọ́, Mímọ́, Mímọ́ Ni Jèhófà” 26
APÁ 1 ‘Agbára Rẹ̀ Ń Bani Lẹ́rù’
5 Agbára Ìṣẹ̀dá—“Aṣẹ̀dá Ọ̀run àti Ayé” 47
6 Agbára Ìparun—“Jagunjagun Tó Lágbára Ni Jèhófà” 57
7 Agbára Ààbò—“Ọlọ́run Ni Ibi Ààbò Wa” 67
8 Agbára Ìmúbọ̀sípò—Jèhófà “Ń Sọ Ohun Gbogbo Di Tuntun” 77
9 “Kristi Ni Agbára Ọlọ́run” 87
10 “Ẹ Máa Fara Wé Ọlọ́run” Bẹ́ Ẹ Ṣe Ń Lo Agbára 97
APÁ 2 “Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ìdájọ́ Òdodo”
11 “Ó Ń Ṣe Ìdájọ́ Òdodo ní Gbogbo Ọ̀nà Rẹ̀” 108
12 “Ṣé Ọlọ́run Jẹ́ Aláìṣòdodo Ni?” 118
14 Jèhófà Pèsè “Ìràpadà ní Pàṣípààrọ̀ fún Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Èèyàn” 138
15 Jésù “Fìdí Ìdájọ́ Òdodo Múlẹ̀ ní Ayé” 148
16 Máa “Ṣe Ìdájọ́ Òdodo” Bó O Ṣe Ń Bá Ọlọ́run Rìn 158
17 “Ọgbọ́n . . . Ọlọ́run Mà Jinlẹ̀ O!” 169
18 Ọgbọ́n Wà Nínú “Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run” 179
19 “Ọgbọ́n Ọlọ́run Nínú Àṣírí Mímọ́” Kan 189
20 “Ọlọ́gbọ́n Ni”—Síbẹ̀ Ó Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ 199
21 Jésù Fi “Ọgbọ́n Ọlọ́run” Hàn 209
22 Ṣé Ò Ń Jẹ́ Kí “Ọgbọ́n Tó Wá Láti Òkè” Darí Rẹ? 219
23 “Òun Ló Kọ́kọ́ Nífẹ̀ẹ́ Wa” 231
24 Kò Sóhun Tó Lè “Yà Wá Kúrò Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run” 240
26 Ọlọ́run Tó “Ṣe Tán Láti Dárí Jini” 260
28 “Ìwọ Nìkan Ni Adúróṣinṣin” 280