Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?
Ibi Tá A Ti Mú Àwọn Àwòrán:
◼ Ojú ìwé 24 àti 25: Fọ́tò WHO tí Edouard Boubat yà
◼ Ojú ìwé 88 àti 89: Bọ́ǹbù tó bú gbàù: Ó wá látinú fọ́tò USAF; Àwòrán ọmọ tébi ń pa: Ó wá látinú fọ́tò WHO tí W. Cutting yà
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn, jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wá láti inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ. Níbi tí NW bá ti tẹ̀ lé àyọlò, ó fi hàn pé ìtumọ̀ náà wá láti inú Bíbélì New World Translation of the Holy Scriptures—With References
A Tẹ̀ Ẹ́ ní September 2013
Yoruba (bh-YR)
© 2005, 2013
Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania