Atọ́ka Àwọn Àkòrí
Àkíyèsí: Àwọn nọ́ńbà tó wà níwájú ọ̀rọ̀ kọ̀ọ̀kan ló sọ ibi tá a ti lè rí àlàyé nípa kókó ọ̀rọ̀ náà. Nọ́ńbà àkọ́kọ́ tọ́ka sí orí, èkejì sì tọ́ka sí ìpínrọ̀. Bí àpẹẹrẹ, “akéde: 10:4-5” ni kókó àkọ́kọ́ lábẹ́ àkòrí náà, “Àfojúsùn.” Èyí túmọ̀ sí pé tẹ́ ẹ bá fẹ́ mọ ibi tá a ṣàlàyé nípa ohun tí akéde kan lè fi ṣe àfojúsùn rẹ̀, ẹ máa rí i ní Orí 10, ìpínrọ̀ 4 àti 5.
Àdúgbò tí wọ́n ti ń sọ èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀: 9:35-44
àwùjọ àtàwọn tí kò tíì di àwùjọ: 9:42-44
kíkọ́ èdè: 10:10
tí onílé bá ń sọ èdè tó yàtọ̀: 9:38-41
Àfojúsùn
akéde: 10:4-5
àwọn ilé ẹ̀kọ́ ètò Ọlọ́run: 10:17-18
ìdí tó fi ṣe pàtàkì: 10:24-26
iṣẹ́ alábòójútó àyíká: 10:16
iṣẹ́ ìkọ́lé: 10:21-23
iṣẹ́ ìsìn aṣáájú-ọ̀nà: 10:11-14
iṣẹ́ ìsìn Bẹ́tẹ́lì: 10:19-20
kíkọ́ èdè míì: 10:10
míṣọ́nnárì tó ń sìn ní pápá: 10:15
mọ ohun tó o lè ṣe: 8:37
sísìn níbi tí wọ́n ti nílò oníwàásù púpọ̀ sí i: 10:6-9
Àìgbọ́ra-ẹni-yé
èyí tó lágbára: 14:13-20
pẹ́ẹ́pẹ̀ẹ̀pẹ́: 14:5-6
Akéde
(Wo Akéde ìjọ; Akéde tí kò tíì ṣèrìbọmi)
Akéde ìjọ
(Tún wo Akéde tí kò tíì ṣèrìbọmi)
ohun tó gbọ́dọ̀ kúnjú ìwọ̀n rẹ̀: 8:8
ọ̀dọ́: 8:13-14
ríran akéde kọ̀ọ̀kan lọ́wọ́: 5:28-29, 33; 7:21; 9:7, 15, 19
tí ara wọn ò le: 8:29
tó kó lọ sí ìjọ míì: 8:30
tuntun: 8:5-6
Akéde tí kò tíì ṣèrìbọmi
bó o ṣe lè kúnjú ìwọ̀n: 8:6-12
ìwà àìtọ́: 14:38-40
kíkọ́ tàbí títún Gbọ̀ngàn Ìjọba ṣe: 11:17
ọmọdé: 8:13-15
Àkọsílẹ̀ Akéde Ìjọ: 5:44; 8:10, 30
Alábòójútó (àwọn)
(Wo Alàgbà)
Alábòójútó àyíká
àwùjọ: 9:44
dídámọ̀ràn ìjọ tuntun: 7:22
ìbẹ̀wò alábòójútó àyíká: 5:41-48
ṣíṣe alábòójútó àyíká lálejò: 5:50
tó o bá fẹ́ mú iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ gbòòrò sí i: 10:6, 10, 16, 20
Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn: 5:28, 32; 9:31, 37, 45
Alàgbà
àgbàlagbà tàbí ẹni tára rẹ̀ kò le: 5:23-24
àwùjọ àtàwọn tó fẹ́ di àwùjọ: 9:42-44
bó o ṣe lè kúnjú ìwọ̀n: 5:22
ìfọwọ́sowópọ̀ láàárín àwọn alàgbà: 5:21
ìpàdé àwọn alàgbà: 5:37
ìwà wa sí àwọn alàgbà: 3:14; 5:38-39
ìyànsípò wọn bá ìlànà Ọlọ́run mu: 4:8
mímú kí ìjọ wà ní mímọ́: 14:19-40
ohun tí wọ́n kúnjú ìwọ̀n ká tó yàn wọ́n: 5:4-20
olùṣọ́ àgùntàn: 5:1-3; 14:7-12
Àpéjọ agbègbè: 7:25-27
Àpéjọ (àwọn)
(Wo Àpéjọ àyíká)
Àpéjọ àyíká
bá a ṣe ń ṣètò àpéjọ: 5:49
ibi tá a ti máa ń ṣe é: 11:18
ìnáwó: 12:8-11
Arábìnrin (àwọn)
àwọn ilé ẹ̀kọ́ ètò Ọlọ́run: 10:17-18
bí kò bá sí arákùnrin tó tóótun: 6:9; 7:23
iṣẹ́ ìkọ́lé: 10:21
Aṣáájú-ọ̀nà: 10:11-14
Aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe: 10:11, 14, 17-18
Aṣáájú-ọ̀nà olùrànlọ́wọ́: 10:11-12
Aṣọ wíwọ̀ àti ìmúra
àwọn tó lẹ́rù iṣẹ́: 6:9
ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́: 6:5
iṣẹ́ ìwàásù: 13:12
nígbà ìgbafẹ́: 13:14
tá a bá lọ sí Bẹ́tẹ́lì: 13:13
Aṣojú orílé-iṣẹ́: 5:55-56
Àsọyé fún gbogbo èèyàn: 7:5-10
Àwòfiṣàpẹẹrẹ
ohun tó túmọ̀ sí: 6:9
Àwọn àjọ tá à ń lò: 4:12
Àwọn aláìní: 12:12-15
Àwọn ọmọ
bí àwọn ọ̀dọ́kùnrin ṣe lè kúnjú ìwọ̀n láti di ìránṣẹ́: 6:14
ìpàdé ìjọ (àwọn): 7:2; 11:13-14
iléèwé: 13:22-24
ìtẹ̀síwájú nípa tẹ̀mí: 8:13-15; 10:26; ojú ìwé 179-181
ṣíṣèrànwọ́ fún àwọn òbí àtàwọn òbí àgbà tí ara wọn ò le: 12:14
tí wọ́n bá hùwà àìtọ́: 14:37
Àwùjọ tí akéde kọ̀ọ̀kan wà
alábòójútó: 5:29-34
ìpàdé iṣẹ́ ìsìn pápá: 7:20-21
ojúṣe ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́: 6:12
ṣíṣe ìmọ́tótó Gbọ̀ngàn Ìjọba: 11:7
yíyan àwọn akéde sí àwùjọ: 5:35
Dídi òjíṣẹ́: 8:3
Eré ìtura àti eré ìnàjú: 13:15-21
Ètò Ìsìnkú: 11:10-11
Ètò Jèhófà
apá ti òkè ọ̀run: 1:8-13
Ẹ̀ka ọ́fíìsì
ìmúra àti aṣọ wa tá a bá ń lọ sí ẹ̀ka ọ́fíìsì: 13:13
ojúṣe àwọn tó ń bójú tó ẹ̀ka ọ́fíìsì: 4:13
ọrẹ tá à ń fi ránṣẹ́: 12:2-4
tá ò bá lè kàn sí ẹ̀ka ọ́fíìsì: 17:15-17
“Ẹrú olóòótọ́ àti olóye”
bá a ṣe ń fi hàn pé a fọkàn tán ẹrú náà: 3:12-15
bá a ṣe lè mọ ẹrú náà: 3:4-6
fífi ara wa sábẹ́ rẹ̀: 15:7
Fífi owó ṣètìlẹyìn
àyíká: 12:8-11
Gbígba ẹni tá a yọ lẹ́gbẹ́ pa dà; Ìgbàpadà: 14:34-36
Gbọ̀ngàn Àpéjọ: 11:18-21
Gbọ̀ngàn Ìjọba
ibi ìkówèésí: 7:19
ìjọ tó ju ẹyọ kan lọ: 11:8-9
ìmọ́tótó àti àtúnṣe: 11:7-8
ìyàsímímọ́: 11:4
kíkọ́ gbọ̀ngàn ìjọba: 10:21-23; 11:4-5, 15-17
lílò fún àwọn ohun àkànṣe: 11:10-11
Ìdẹwò, àdánwò: 13:4-5; 17:4-19
Ìfilọ̀
akéde tí kò tíì ṣèrìbọmi: 8:12; 14:39-40
ìbáwí: 14:24
ìgbàpadà: 14:36
ìyọlẹ́gbẹ́: 14:29
mímú ara ẹni kúrò lẹ́gbẹ́: 14:33
ọrẹ: 12:6
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé: 7:14-18
Ìgbéyàwó: 11:10-11
Ìgbìmọ̀
Alárinà Ilé Ìwòsàn: 5:40
Ìgbìmọ̀ Iṣẹ́ Ìsìn Ìjọ: 5:35
ìgbẹ́jọ́: 14:21-28, 34-37
Orílẹ̀-èdè: 5:53
Tó Ń Bójú Tó Gbọ̀ngàn Ìjọba: 11:8
Ìgbìmọ̀ Alárinà Ilé Ìwòsàn àti Àwùjọ Tó Ń Bẹ Àwọn Aláìsàn Wò: 5:40
Ìgbìmọ̀ iṣẹ́ ìsìn
Ìgbìmọ̀ Iṣẹ́ Ìsìn Ìjọ: 5:35
Ìgbìmọ̀ Olùdarí
bá a ṣe lè fi hàn pé a fọkàn tán an: 3:12-15
bá a ṣe lè mọ ìgbìmọ̀ olùdarí: 3:1-6
ìdí tó fi yẹ ká máa tẹ̀ lé ìtọ́ni ìgbìmọ̀ náà: 3:9-11; 4:9-11
Ìgbìmọ̀ ìgbẹ́jọ́: 14:21-28, 34-37
Ìjọ
(Tún wo Gbọ̀ngàn Ìjọba; Ìpàdé)
a ṣètò wọn lọ́nà ti Ọlọ́run: 1:3; 4:4-11
ìṣọ̀kan: 13:28-30
tuntun àti kékeré: 7:22-23
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
dídarí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sínú ètò Ọlọ́run: 9:20-21
ìdí tí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì fi ṣe pàtàkì: 9:16-17
ríròyìn ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: 8:26
rírọ akẹ́kọ̀ọ́ láti máa wàásù lọ́nà àìjẹ́-bí-àṣà: 8:5
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́: 7:11-13
Ìmọ́tótó
Gbọ̀ngàn Ìjọba: 11:7-8
nínú ìwà, nínú ìjọsìn: 13:6-7
nípa tara: 13:8-12
Ìpàdé
alàgbà (àwọn): 5:37
àpéjọ agbègbè: 7:25-26
àpéjọ àyíká: 7:24
àsọyé fún gbogbo èèyàn: 7:5-10
àwọn ọmọ Ísírẹ́lì: 11:1
àwọn ọmọdé tó wá: 11:13
bí ìjọba bá fòfin de: 17:15-17
bó ṣe ṣe pàtàkì: 3:12; 7:4, 27; 15:7
ìdí tá a fi ń ṣe é: 7:1-2
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: 7:17
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́: 7:11-13
Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́: 7:14-19
ìpolówó ọjà níbẹ̀: 13:27
iṣẹ́ ìsìn pápá: 7:20-21; 9:45
nígbà ìbẹ̀wò alábòójútó àyíká: 5:43, 47
olùtọ́jú èrò: 11:14
ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní: 7:3; 11:2
tí arábìnrin bá darí: 7:23
Ìpínlẹ̀ ìwàásù
àkọsílẹ̀: 9:31
àwùjọ àti ti ara ẹni: 9:31-34
èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀: 9:36-37
Ipò iwájú
àwọn aláṣẹ ìlú: 15:11
nínú ètò Jèhófà: 1:9-10; 2:5, 9-10; 15:1-2
nínú ìdílé: 15:9-10
Ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́
bó o ṣe lè di: 6:14
fi ìmọrírì hàn fún: 6:1-2, 15
ìtóótun: 6:3-6
Ìrántí Ikú Kristi: 7:28-30
Ìrànwọ́ nígbà àjálù: 12:15; 16:11
Ìrìbọmi
akéde tí kò tíì ṣèrìbọmi: ojú ìwé 182-184
dídi òjíṣẹ́: 8:3
ìbéèrè tá a máa ń bí àwọn tó fẹ́ ṣèrìbọmi: ojú ìwé 185-207
ìtumọ̀ ìrìbọmi: 8:16-18
láwọn àpéjọ àyíká àti ti agbègbè: 7:24, 26
ọmọdé: ojú ìwé 179-181
Ìròyìn
alábòójútó àyíká: 5:46, 50; 9:44
bá ò bá sí nílé: 8:30
ìdí tó fi ṣe pàtàkì: 8:19-22, 31-36
Iṣẹ́ ìkọ́lé: 10:21-23
Ẹgbẹ́ Tó Ń Kọ́lé: 10:23
ìránṣẹ́ ìkọ́lé: 10:23
ìránṣẹ́ ìkọ́lé nílẹ̀ òkèèrè: 10:23
olùyọ̀ǹda lẹ́nu iṣẹ́ ìkọ́lé: 10:23
olùyọ̀ǹda tó ń yàwòrán ilé tó sì ń kọ́ ọ: 10:23
Iṣẹ́ ilé ìwé: 13:22-24
Iṣẹ́ ìsìn Bẹ́tẹ́lì: 10:19-20
Iṣẹ́ oúnjẹ òòjọ́: 13:25-26
Ìṣọ̀kan
kárí ayé: 16:6-11
lábẹ́ ìdarí Kristi: 2:9-11; 4:10-11
ohun tó jẹ́ ká wà níṣọ̀kan: 1:6-7; 13:28-29
wíwà níṣọ̀kan nígbà gbogbo: 17:20
Ìtẹríba
(Wo Ipò iwájú)
Ìwà àìtọ́
(Wo Mímú ara ẹni kúrò lẹ́gbẹ́; Ìyọlẹ́gbẹ́; Sísàmì sí àwọn tó ń rìn ségesège; Àìgbọ́ra-ẹni-yé; Ìgbàpadà)
akéde tí kò tíì ṣèrìbọmi: 14:38-40
bá a bá ṣẹ Kristẹni ẹlẹgbẹ́ wa: 14:5-6, 13-20
èyí tó burú jáì: 14:21-33
ìfilọ̀ nípa: 14:24, 29, 33, 39-40
ọmọdé: 14:37
Ìwé
àdúgbò tí wọ́n ti ń sọ èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀: 9:36, 38
bá a ṣe ń lò ó fún ìwàásù: 9:22-23
bá a ṣe ń rówó tẹ̀ ẹ́: 12:2-4
bá a ṣe ń gba ìwé: 12:16
Ìyàsímímọ́ àti ìrìbọmi
(Wo Ìrìbọmi)
Ìyọlẹ́gbẹ́: 14:25-29
Jèhófà Ọlọ́run
bó o ṣe lè sún mọ́ ọn: 17:1-3
Ọba Aláṣẹ Ayé Àtọ̀run: 15:1-4
Jésù Kristi
Àlùfáà Àgbà: 2:4
Olùràpadà: 2:3
Olùṣọ́ Àgùntàn Àtàtà: 2:6; 5:1
wà lábẹ́ Jèhófà: 15:5
JW.ORG: 9:24-25
Kristẹni aláìṣiṣẹ́mọ́: 8:26; 14:32
Lílọ síbi tí wọ́n ti nílò oníwàásù púpọ̀ sí i: 10:6-9
Mímú ara ẹni kúrò lẹ́gbẹ́: 14:30-33
Olùṣekòkáárí ìgbìmọ̀ àwọn alàgbà
àwọn tó fẹ́ ṣèrìbọmi: 8:18; ojú ìwé 208-212
ìbẹ̀wò alábòójútó àyíká: 5:42-44
Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Ìṣẹ́ Òjíṣẹ́: 7:18
ojúṣe rẹ̀: 5:26
yíyẹ àkáǹtì wò: 12:7
Olùtọ́jú èrò: 11:14
Ọrẹ: 3:13; 11:6-7, 15; 12:2-11
Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa: 7:28-30
Sísàmì sí àwọn tó ń rìn ségesège: 14:9-12
Wíwàásù ìhìn rere
àdúgbò tí wọ́n ti ń sọ èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀: 9:35-44
àṣẹ Ọlọ́run: 8:2
àwọn ọ̀dọ́: 8:13-15
bó o ṣe lè kúnjú ìwọ̀n: 8:6-9, 13-15
ìdí tó fi ṣe pàtàkì: 9:5-8; 10:1-2
ìjẹ́rìí àjẹ́pọ̀: 9:45-46
ilé-dé-ilé: 9:3-9
ìmúra: 13:12
ìpadàbẹ̀wò: 9:14-15
ìpàdé iṣẹ́ ìsìn pápá: 7:20-21
ìpínlẹ̀ ìwàásù: 9:30-34
ìrànlọ́wọ́ látọ̀dọ̀ àwọn míì: 5:28-29, 33; 7:21; 9:7, 15, 19
iṣẹ́ alábòójútó iṣẹ́ ìsìn: 5:28
ìwé: 9:22-23
lábẹ́ ìfòfindè: 17:13-18
láìjẹ́ bí àṣà: 9:26-29
lílo ìkànnì jw.org: 9:24-25
mímú ipò iwájú: 5:3, 17, 29-33; 6:4
níbi tí èrò pọ̀ sí: 9:11-12
ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní: 8:1-2; 9:1, 4
sọ fún akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pé kó máa wàásù láìjẹ́ bí àṣà: 8:5