Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí:
Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká nígbàgbọ́ ní ipòkípò tá a bá wà? (Máàkù 11:22)
Àwọn àǹfààní wo la máa rí tá a bá ń ṣàṣàrò lórí àwọn àfiwé ọ̀rọ̀ nípa Jèhófà? (Sm. 28:7; Lúùkù 11:11-13; Diu. 32:4; Sm. 23:1)
Báwo la ṣe lè mú kí ìgbàgbọ́ wa túbọ̀ lágbára? (Máàkù 9:24)
Kí ni “ẹ̀ṣẹ̀ tí ó máa ń wé mọ́ wa pẹ̀lú ìrọ̀rùn,” báwo la sì ṣe lè yẹra fún un? (Héb. 12:1)
Kí ló mú kó dá wa lójú pé Jèhófà máa san ẹ̀san fún àwọn tí ìgbàgbọ́ wọn bá jinlẹ̀? (Héb. 11:6)