Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Tún wo orí ìkànnì wa:
Irú Èèyàn Wo ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà?
Kí Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Gbọ́?
Irú Èèyàn Wo Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 1
Kí Nìdí Tí A Fi Ń Jẹ́ Orúkọ Náà, Ẹlẹ́rìí Jèhófà? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 2
Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé: Ṣé Ẹlẹ́sìn Pùròtẹ́sítáǹtì Ni Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà? Ilé Ìṣọ́, 11/1/2009
Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye (Ìgbìmọ̀ Olùdarí)
‘Ẹ Máa Ka Irú Àwọn Ènìyàn Bẹ́ẹ̀ Sí Ẹni Ọ̀wọ́n’ Ilé Ìṣọ́, 10/15/2015
Ìbùkún Jèhófà Mú Kí Ìgbésí Ayé Mi Túbọ̀ Nítumọ̀ Ilé Ìṣọ́, 9/15/2015
Ìfẹ́ Tí Mo Ní fún Ọlọ́run Látìbẹ̀rẹ̀ Mú Kí N Lè Fara Dà Á Ilé Ìṣọ́, 5/15/2015
“Ẹ Máa Rántí Àwọn Tí Ń Mú Ipò Iwájú Láàárín Yín” A Ṣètò Wa, orí 3
Ó “Mọ Ọ̀nà” Náà Ilé Ìṣọ́, 12/15/2014
Baba Kú àmọ́, Baba Kù Ilé Ìṣọ́, 7/15/2014
Ta Ni Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 19
Ọ̀nà Wo Ni Ìgbìmọ̀ Olùdarí Gbà Ń Ṣiṣẹ́ Lónìí? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 20
Ǹjẹ́ Ò Ń Fòye Mọ Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Ọlọ́run Ń Tọ́ Wa Sọ́nà? Ilé Ìṣọ́, 4/15/2011
Ìfẹ́ So Wá Pọ̀—Ìròyìn Ìpàdé Ọdọọdún (§ Ìgbìmọ̀ Olùdarí) Ilé Ìṣọ́, 6/15/2010
“Awuyewuye Tí Kì Í Ṣe Kékeré Ti Wáyé” Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, orí 13
“A Ti Dé Orí Ìf ìmọ̀ṣọ̀kan” Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, orí 14
Ẹni Àmì Òróró
Ṣé Wàá “Máa Bá A Nìṣó Ní Ṣíṣọ́nà”? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2015
Àgùntàn Mìíràn
Jẹ́ Kí Ìrètí Tá A Ní Máa Fún Ẹ Láyọ̀ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2012
Agbo Kan, Olùṣọ́ Àgùntàn Kan Ilé Ìṣọ́, 3/15/2010
Ọlọ́run Ló Fún Aráyé Ní Ìrètí Ìyè Àìnípẹ̀kun Lórí Ilẹ̀ Ayé
Ṣé Ìyè Àìnípẹ̀kun Lórí Ilẹ̀ Ayé Jẹ́ Ìrètí Tó Wà Fáwọn Kristẹni?
Ọlọ́run Kà Wọ́n Sẹ́ni Tó Yẹ Láti Ṣamọ̀nà Lọ Sáwọn Ìsun Omi Ìyè Ilé Ìṣọ́, 1/15/2008
Ẹ Dúró Lọ́nà Pípé Pẹ̀lú Ìgbàgbọ́ Tó Fìdí Múlẹ̀: ‘Ẹ Wò Ó! Ogunlọ́gọ̀ Ńlá Náà!’ Ilé Ìṣọ́, 5/15/2001
Ìpìlẹ̀ Ayé Tuntun Náà Ni A Ń Fi Lélẹ̀ Nísinsìnyí Ọlọ́run Bìkítà, apá 11
Ìsìn Tòótọ́
Kí Nìdí Tó O Fi Mọyì Ìjọsìn Mímọ́? Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 9/2017
Bá A Ṣe Lè Fi Kún Ẹwà Párádísè Tẹ̀mí Ilé Ìṣọ́, 7/15/2015
Ìjọsìn Tó Ní Ìtẹ́wọ́gbà Ọlọ́run Bíbélì Fi Kọ́ni, orí 15
“Máa Rí Adùn Jèhófà” Ilé Ìṣọ́, 2/15/2014
Ọba Náà Yọ́ Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Mọ́ Nípa Tẹ̀mí Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 10
Àwọn Kristẹni Tòótọ́ Bọ̀wọ̀ fún Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ilé Ìṣọ́, 1/15/2012
Fi Hàn Pé Ojúlówó Ọmọlẹ́yìn Kristi Ni Ẹ́ Ilé Ìṣọ́, 1/15/2010
Àwọn Wo Ló Ń Fi Ògo fún Ọlọ́run Lónìí? Ilé Ìṣọ́, 10/1/2004
Fífarawé Ọlọ́run Òtítọ́ Ilé Ìṣọ́, 8/1/2003
Ẹ Máa Yọ̀ Nínú Ìmọ̀ Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 7/1/2001
“Bí Ọlọ́run Bá Wà fún Wa, Ta Ni Yóò Wà Lòdì sí Wa?” Ilé Ìṣọ́, 6/1/2001
Ìsìn Kristẹni Tòótọ́ Ti Borí! Ilé Ìṣọ́, 4/1/2001
Kí Ni Párádísè Tẹ̀mí? Ilé Ìṣọ́, 3/1/2001
Ìṣọ̀kan Àwa Kristẹni
“Jèhófà Ọlọ́run Wa, Jèhófà Kan Ṣoṣo Ni” Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 6/2016
Báwo Lo Ṣe Lè Pa Kún Ìṣọ̀kan Tó Wà Láàárín Àwa Kristẹni? Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 3/2016
Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Ìjọba Ọlọ́run Ilé Ìṣọ́, 7/15/2015
Ẹgbẹ́ Ará Tó Wà Níṣọ̀kan A Ṣètò Wa, orí 16
Bá A Ṣe Lè La Òpin Ayé Ògbólógbòó Yìí Já Pa Pọ̀ Ilé Ìṣọ́, 12/15/2014
Àwọn “Olùgbé Fún Ìgbà Díẹ̀” Ń Sin Jèhófà Ní Ìṣọ̀kan Ilé Ìṣọ́, 12/15/2012
Ẹ Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Rere Gbilẹ̀ Nínú Ìjọ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2012
Ǹjẹ́ O Máa Ń Mú Ipò Iwájú Nínú Bíbọlá fún Àwọn Tá A Jọ Jẹ́ Onígbàgbọ́? Ilé Ìṣọ́, 10/15/2010
Ìṣọ̀kan La Fi Ń Dá Ìsìn Tòótọ́ Mọ̀ Ilé Ìṣọ́, 9/15/2010
Kí Ló Ń Mú Káwọn Èèyàn Kan Wà Níṣọ̀kan Kárí Ayé? Ilé Ìṣọ́, 12/1/2007
“Ẹ Máa Ṣe Ohun Gbogbo Láìsí Ìkùnsínú” Ilé Ìṣọ́, 7/15/2006
“Ẹ Ní Ìfẹ́ni Oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ fún Ara Yín” Ilé Ìṣọ́, 10/1/2004
Ẹ Máa “Fi Ẹnu Kan” Yin Ọlọ́run Lógo Ilé Ìṣọ́, 9/1/2004
Ìsìn Kristẹni Tòótọ́ Ń Gbèrú Ilé Ìṣọ́, 3/1/2004
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ǹjẹ́ Ìṣọ̀kan Kristẹni Ń Béèrè Pé Kí Ìpinnu Àwọn Kristẹni Dọ́gba? Jí!, 5/8/2003
“Arákùnrin Ni Gbogbo Yín” Ilé Ìṣọ́, 6/15/2000
Ìtàn Wa
Ọgọ́rùn-ún Ọdún Kìíní
17 Bí Ẹ̀sìn Kristẹni Ṣe Gbilẹ̀ Àfikún Ìsọfúnni
Ìsìn Kristẹni Dé Éṣíà Kékeré Ilé Ìṣọ́, 8/15/2007
Àwọn Kristẹni Ìjímìjí àti Òfin Mósè Ilé Ìṣọ́, 3/15/2003
“Ọ̀rọ̀ Jèhófà Ń Bá A Lọ Ní Gbígbilẹ̀” Ilé Ìṣọ́, 4/1/2001
Ìtàn Wa Lóde Òní
Tún wo ìwé:
Látinú Àpamọ́ Wa: “Ìgbà Wo La Tún Máa Ṣe Àpéjọ Míì?” Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 8/2017
Látinú Àpamọ́ Wa: “Kò Sí Ọ̀nà Tó Burú Jù Tàbí Jìn Jù” Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 2/2017
Látinú Àpamọ́ Wa: “Àwọn Tá A Fa Iṣẹ́ Náà Lé Lọ́wọ́” Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 5/2016
Látinú Àpamọ́ Wa: “Ohunkóhun Ò Gbọ́dọ̀ Dí Yín Lọ́wọ́!” Ilé Ìṣọ́, 11/15/2015
Látinú Àpamọ́ Wa: “Jèhófà Mú Yín Wá sí Ilẹ̀ Faransé Láti Kẹ́kọ̀ọ́ Òtítọ́” Ilé Ìṣọ́, 8/15/2015
Látinú Àpamọ́ Wa: “Àkókò Tá A Mọyì Jù Lọ” Ilé Ìṣọ́, 2/15/2015
Látinú Àpamọ́ Wa: Ẹ̀kọ́ Òtítọ́ Dé Ilẹ̀ Japan Ilé Ìṣọ́, 11/15/2014
Àwòkẹ́kọ̀ọ́ “Eureka” Mú Kí Ọ̀pọ̀ Rí Ẹ̀kọ́ Òtítọ́ Ilé Ìṣọ́, 8/15/2014
Ọgọ́rùn-ún Ọdún Rèé Tá A Ti Ń Polongo Ìjọba Ọlọ́run! Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 8/2014
Látinú Àpamọ́ Wa: ‘Ìkórè Ṣì Pọ̀’ Ilé Ìṣọ́, 5/15/2014
Látinú Àpamọ́ Wa: “Ohun Mánigbàgbé” Tó Bọ́ Sákòókò Ilé Ìṣọ́, 2/15/2013
Látinú Àpamọ́ Wa: ‘Ìwàásù Tí Wọn Kò Gbọ́ Irú Rẹ̀ Rí’ Ilé Ìṣọ́, 11/15/2012
Látinú Àpamọ́ Wa: Ẹ Jẹ́ Ká Bá Àwọn Arìnrìn-Àjò Ìsìn Lọ Sóde Ẹ̀rí Ilé Ìṣọ́, 8/15/2012
“Mo Wà Pẹ̀lú Yín” Ilé Ìṣọ́, 8/15/2012
Látinú Àpamọ́ Wa: “Ojoojúmọ́ Ni Iṣẹ́ Apínwèé-Ìsìn-Kiri Túbọ̀ Ń Gbádùn Mọ́ Mi” Ilé Ìṣọ́, 5/15/2012
Látinú Àpamọ́ Wa: ‘Wọ́n Ń Fi Mí Ṣe Ìran Wò’ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2012
Wọ́n Fi Ìgboyà Polongo Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run! Ilé Ìṣọ́, 2/15/2012
Látinú Àpamọ́ Wa: Bá A Ṣe Ń Tọ́jú Àwọn Ohun Tá A Ti Lò Látijọ́ Ilé Ìṣọ́, 1/15/2012
Báwo Ni A Ṣe Wá Mọ Òtítọ́ Tí Bíbélì Fi Kọ́ni? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 3
Bẹ́tẹ́lì Tó Wà Ní Brooklyn Ti Pé Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ilé Ìṣọ́, 5/1/2009
“Ẹ Jẹ́ Ká Fi Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Wé Ara Wọn” Ilé Ìṣọ́, 8/15/2006
À Ń Rìn ní Ọ̀nà Ìmọ́lẹ̀ Tó Túbọ̀ Ń Mọ́lẹ̀ Sí I Ilé Ìṣọ́, 2/15/2006
Ẹ Dúró Lọ́nà Pípé Pẹ̀lú Ìgbàgbọ́ Tó Fìdí Múlẹ̀: ‘Ẹ Wò Ó! Ogunlọ́gọ̀ Ńlá Náà!’ Ilé Ìṣọ́, 5/15/2001
Ẹ Dúró Lọ́nà Pípé Pẹ̀lú Ìgbàgbọ́ Tó Fìdí Múlẹ̀: “Iṣẹ́ Àgbàyanu Kan” Ilé Ìṣọ́, 1/15/2001
Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn Ni Wọ́n Ra Ilé Iṣẹ́ Àkọ́kọ́ Jí!, 1/8/2001
Ṣíṣiṣẹ́ Nínú “Pápá” Ṣáájú Ìkórè Ilé Ìṣọ́, 10/15/2000
Ìròyìn Orílẹ̀-Èdè
Jọ́jíà Ìwé Ọdọọdún Ìwé Ọdọọdún—2017
Myanmar (Burma) Ìwé Ọdọọdún—2013
Orílẹ̀-Èdè Dominican Ìwé Ọdọọdún—2015
Sierra Leone àti Guinea Ìwé Ọdọọdún—2014
Ogun Àgbáyé Kejì àti Ìpakúpa Ìjọba Násì
Jèhófà Dáàbò Bò Wọ́n Lábẹ́ Òjìji Àwọn Òkè Ńlá Ilé Ìṣọ́, 12/15/2013
“Kí Ni Àmì Onígun Mẹ́ta Aláwọ̀ Àlùkò Náà Dúró Fún?” Ilé Ìṣọ́, 2/15/2006
Ìgbà Tí Àìfọhùn Bá Túmọ̀ Sí Àjọgbà Ilé Ìṣọ́, 9/1/2000
Wọ́n Dúró Ṣinṣin Láìbẹ̀rù Nígbà Tí Ìjọba Násì Ń Pọ́n Wọn Lójú Ilé Ìṣọ́, 4/1/2000
Ìjọ Kristẹni
Bí Ara Ẹ Ṣe Lè Mọlé Nínú Ìjọ Tó O Wà Báyìí Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 11/2017
A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà A Ṣètò Wa, orí 1
Bá A Ṣe Ṣètò Ìjọ àti Bá A Ṣe Ń Darí Rẹ̀ A Ṣètò Wa, orí 4
Ǹjẹ́ Ó Dá Ẹ Lójú Pé O Wà Nínú Òtítọ́? Kí Nìdí? Ilé Ìṣọ́, 9/15/2014
Bí O Ṣe Lè Jàǹfààní Látinú Àwùjọ Tí Ò Ń Dara Pọ̀ Mọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2012
Kí Nìdí tí Ọlọ́run Fi Ní Ètò Kan? Ìròyìn Ayọ̀, ẹ̀kọ́ 14
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Ní Ètò Kan Tó Gbé Kalẹ̀? Ilé Ìṣọ́, 6/1/2011
Kí A Gbé Ìjọ Ró (§ Má Ṣe Kúrò Nínú Ìjọ Ọlọ́run) Ilé Ìṣọ́, 4/15/2007
Àwọn Ohun Rere Inú Ètò Jèhófà Ni Kó o Máa Fiyè Sí Ilé Ìṣọ́, 7/15/2006
Títẹ̀síwájú sí Ìṣẹ́gun Ìkẹyìn! Ilé Ìṣọ́, 6/1/2001
Máa Bá Ètò Àjọ Jèhófà Rìn Ilé Ìṣọ́, 1/15/2001
Kòṣeémánìí Lètò Àjọ Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 1/1/2000
Ìpàdé
Fi Ọ̀yàyà Kí Wọn Káàbọ̀ Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 4/2017
Bá A Ṣe Lè Máa Dáhùn Lọ́nà Tó Gbéṣẹ́ Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 10/2016
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Pé Jọ Láti Jọ́sìn? Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 4/2016
Àwọn Ìpàdé Tó Ń ‘Ru Wá Sókè Sí Ìfẹ́ àti Sí Àwọn Iṣẹ́ Àtàtà’ A Ṣètò Wa, orí 7
Bí A Ṣe Ń Pàdé Pọ̀ Láti Jọ́sìn Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 16
Ǹjẹ́ O Máa Ń Wo Ojú Pátákó Ìsọfúnni? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 4/2013
Jèhófà Ń Kó Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Aláyọ̀ Jọ Ilé Ìṣọ́, 9/15/2012
Kí Lo Máa Rí Láwọn Ìpàdé Wa? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 5
Kí Là Ń Kọ́ Láwọn Ìpàdé Wa? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 7
Ọ̀nà Wo Ló Dára Jù Láti Gbà Múra Ìpàdé Ìjọ Sílẹ̀? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 9
Kí Nìdí Tí A Fi Ń Lọ sí Àwọn Àpéjọ Ńlá? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 11
Ọ̀nà Tó Dára Láti Gbádùn Àwọn Orin Ìjọba Ọlọ́run Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 12/2011
Jẹ́ Onítara fún Ilé Jèhófà! Ilé Ìṣọ́, 6/15/2009
“Ìgbà Dídákẹ́” Ilé Ìṣọ́, 5/15/2009
A Fi Tọ̀yàyàtọ̀yàyà Pè Ẹ́ Ilé Ìṣọ́, 2/1/2009
Bá A Ṣe Lè Máa Fọ̀wọ̀ Hàn fún Àwọn Àpéjọ Wa Tó Jẹ́ Mímọ́ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2006
Máa Yin Jèhófà “ní Àárín Ìjọ” Ilé Ìṣọ́, 9/1/2003
Ẹ Má Ṣe Dẹ́kun Pípàdé Pọ̀ Ilé Ìṣọ́, 11/15/2002
“Ẹ Máa Fiyè sí Bí Ẹ Ṣe Ń Fetí Sílẹ̀” Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ǹjẹ́ Ó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Lọ Sáwọn Ìpàdé Ìjọ? Jí!, 3/8/2001
Bí Jèhófà Ṣe Ń Ṣamọ̀nà Wa Ilé Ìṣọ́, 3/15/2000
Ìtọ́ni Nípa Bí A Ó Ṣe Máa Darí Ìpàdé
“Àwòrán Yìí Mà Dara Gan-an O!” Ilé Ìṣọ́, 7/15/2013
Máa Yin Jèhófà “ní Àárín Ìjọ” (§ Iṣẹ́ Àwọn Tó Ń Darí Ìpàdé) Ilé Ìṣọ́, 9/1/2003
Ìpàdé fún Iṣẹ́ Ìsìn Pápá
A Ò Ní Máa Jíròrò Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Ojoojúmọ́ Ní Ìpàdé fún Iṣẹ́ Ìsìn Pápá Mọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 2/2011
Bá A Ṣe Lè Kọ́ Àwọn Ẹni Tuntun Láti Máa Wàásù Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2010
Ìpàdé fún Iṣẹ́ Ìsìn Pápá Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 8/2009
Bá A Ṣe Lè Jàǹfààní Tó Kún Rẹ́rẹ́ Nínú Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Pápá Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2006
Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Dámọ̀ràn fún Lílò Lóde Ẹ̀rí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 1/2005
Awọn Ìnasẹ̀-Ọ̀rọ̀ Fún Lílò Ninu Iṣẹ́-Ìsìn Pápá Awọn Ìjíròrò Bibeli
Bí O Ṣe Lè Dáhùnpadà sí Awọn Ọ̀rọ̀ Tí Ó Lè Bẹ́gidínà Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀pọ̀ Awọn Ìjíròrò Bibeli
Ìrántí Ikú Kristi
Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Bíbélì, ẹ̀kọ́ 87
Ẹ Kí Àwọn Tá A Pè Káàbọ̀ Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 3/2016
Látinú Àpamọ́ Wa: “Àkókò Tá A Mọyì Jù Lọ” Ilé Ìṣọ́, 2/15/2015
Ìdí Tí A Fi Ń Lọ Síbi Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa Ilé Ìṣọ́, 1/15/2015
Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa—Ìrántí Ikú Kristi Tá A Ń Ṣe Láti Bọlá fún Ọlọ́run Bíbélì Fi Kọ́ni, Àfikún
Àwọn Ìpàdé Tó Ń ‘Ru Wá Sókè Sí Ìfẹ́ àti Sí Àwọn Iṣẹ́ Àtàtà’ (§ Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa) A Ṣètò Wa, orí 7
Àsè Alẹ́ Ìṣe-ìrántí Ọkùnrin Títóbilọ́lá Jù Lọ, orí 114
Ohun Tó Yẹ Ká Mọ̀ Nípa Gbígba Ara Olúwa Ilé Ìṣọ́, 4/1/2008
Báwo Ni Wọ́n Ṣe Ṣayẹyẹ Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2004
Bí A Ṣe Lè Rántí Jèhófà àti Ọmọ Rẹ̀ Olùkọ́, orí 37
Àwọn Ibi Ìjọsìn Wa
Ibi Ìjọsìn Wa Rèé Ilé Ìṣọ́, 7/15/2015
Bá A Ṣe Ṣètò Àwọn Ibi Ìjọsìn Wa A Ṣètò Wa, orí 11
Kí La Lè Ṣe Láti Máa Tọ́jú Gbọ̀ngàn Ìjọba Wa? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 26
Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè: Kí ni Gbọ̀ngàn Ìjọba? Ilé Ìṣọ́, 5/1/2010
Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Èèyàn Tó Mọ́ Tónítóní ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 8 ¶18
Mímú Kí Ibi Ìjọsìn Wa Wà ní Ipò Tó Bójú Mu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 8/2003
Ìṣètò Tuntun fún Àwọn Ibi Ìkówèésí Tó Wà Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 2/2003
Kíkọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba
Bá A Ṣe Ṣètò Àwọn Ibi Ìjọsìn Wa (§ Bí A Ṣe Ń Kọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba) A Ṣètò Wa, orí 11
Àwọn Ilé Tá À Ń Kọ́ Ń Bọlá fún Jèhófà Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 19
Kí Nìdí Tá A Fi Ń Kọ́ Àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba, Báwo La sì Ṣe Ń Kọ́ Wọn? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 25
Bá A Ṣe Ń Kọ́ Ilé Tó Ń Fìyìn fún Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 2/1/2008
Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Ń Jùmọ̀ Kọ́lé fún Ìyìn Rẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2006
Ètò Kíkọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba Kárí Ayé Láwọn Orílẹ̀-Èdè Mélòó Kan Nílẹ̀ Yúróòpù Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 7/2003
Ètò Kíkọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba Ń Tẹ̀ Síwájú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 1/2003
Orin Tá À Ń Lò Nínú Ìjọsìn Tòótọ́
Máa Fi Ayọ̀ Kọrin! Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 11/2017
Àwọn Orin Ìjọba Ọlọ́run Máa Ń Jẹ́ Ká Nígboyà Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 4/2017
Àwọn Orin Tuntun Tí A Ó Máa Lò Nínú Ìjọsìn! Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 12/2014
Ọ̀nà Tó Dára Láti Gbádùn Àwọn Orin Ìjọba Ọlọ́run Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 12/2011
Kọrin Sí Jèhófà! Ilé Ìṣọ́, 12/15/2010
Ọwọ́ Tí Dáfídì Ọba Fi Mú Orin Kíkọ Ilé Ìṣọ́, 12/1/2009
Orin Tí Ń Múnú Ọlọ́run Dùn Ilé Ìṣọ́, 6/1/2000
Àwọn Ilé Ẹ̀kọ́ Ètò Ọlọ́run
Bí A Ṣe Ń Dá Àwọn Òjíṣẹ́ Ìjọba Náà Lẹ́kọ̀ọ́ Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 17
Àwọn Ilé Ẹ̀kọ́ Ètò Ọlọ́run—Ẹ̀rí Pé Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Wa Ilé Ìṣọ́, 9/15/2012
Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì
Àwọn Ilé Ẹ̀kọ́ Ètò Ọlọ́run—Ẹ̀rí Pé Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Wa (§ Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì) Ilé Ìṣọ́, 9/15/2012
Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì—Ọgọ́ta Ọdún Rèé Tó Ti Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn Níṣẹ́ Míṣọ́nnárì Ilé Ìṣọ́, 6/15/2003
Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere Ìjọba Ọlọ́run
Tí wọ́n ń pè ní Ilé Ẹ̀kọ́ Bíbélì fún Àwọn Àpọ́n àti Ilé Ẹ̀kọ́ Bíbélì fún Àwọn Tọkọtaya tẹ́lẹ̀
Ilé Ẹ̀kọ́ Kan Táwọn Tó Jáde Níbẹ̀ Ń Ṣe Àwọn Èèyàn Láǹfààní Jákèjádò Ayé Ilé Ìṣọ́, 11/15/2006
Akéde
Àwọn Òjíṣẹ́ Tó Ń Wàásù Ìhìn Rere A Ṣètò Wa, orí 8
Ṣègbọràn sí Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn tí Jèhófà Yàn Ilé Ìṣọ́, 11/15/2013
“Ẹ Ní Ẹ̀mí Ìkanisí fún Àwọn Tí Ń Ṣiṣẹ́ Kára Láàárín Yín” Ilé Ìṣọ́, 6/15/2011
Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Di Akéde Ìjọba Ọlọ́run Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 1/2008
Ẹ Máa Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Tẹrí Ba Fáwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Onífẹ̀ẹ́ Ilé Ìṣọ́, 4/1/2007
Ẹ Máa Bọlá fún Àwọn Tó Ní Ọlá Àṣẹ Lórí Yín Ilé Ìṣọ́, 6/15/2000
Obìnrin
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 1/2017
Ọ̀rọ̀ Àpọ́nlé Tó Ń Tuni Lára! Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 11/2016
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣó Yẹ Kí Àwọn Obìnrin Jẹ́ Òjíṣẹ́? Jí!, 10/2010
“Kí Ìfẹ́ Jèhófà Ṣẹ” (Àpótí: Ǹjẹ́ Àwọn Obìnrin Lè Jẹ́ Òjíṣẹ́?) Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, orí 22
Ojú Wo Ni Ọlọ́run àti Kristi Fi Ń Wo Àwọn Obìnrin? Jí!, 1/2008
Ọkùnrin àti Obìnrin Ipò Iyì Ni Ọlọ́run Fi Kálukú Wọn Sí Ilé Ìṣọ́, 1/15/2007
Àwọn Obìnrin Tó Mú Inú Jèhófà Dùn Ilé Ìṣọ́, 11/1/2003
Bíbo Orí
Ìgbà Wo Ló Yẹ Kí Obìnrin Máa Borí, Kí sì Nìdí? ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ Àfikún
Àwọn Àgbàlagbà
Tún wo Ọjọ́ Ogbó lábẹ́ Ìlera Ara àti Ọpọlọ
Jọ́sìn Jèhófà ní “Àwọn Ọjọ́ Oníyọnu” Ilé Ìṣọ́, 7/15/2015
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Bọ̀wọ̀ fún Àwọn Àgbàlagbà? Ilé Ìṣọ́, 5/15/2010
Jèhófà Ń Ṣìkẹ́ Àwọn Ìránṣẹ́ Rẹ̀ Tó Jẹ́ Àgbàlagbà Ilé Ìṣọ́, 8/15/2008
Ọlọ́run Mọyì Àwọn Arúgbó Ilé Ìṣọ́, 6/1/2006
“Ọ̀dọ̀ Jèhófà Ni Ìrànlọ́wọ́ Mi Ti Wá”: Ohun Tó Ń Mú Kí Ọjọ́ Ogbó Jẹ́ “Adé Ẹwà” Ilé Ìṣọ́, 1/15/2005
Ǹjẹ́ O Mọyì Àwọn Àgbàlagbà Tẹ́ Ẹ Jọ Jẹ́ Onígbàgbọ́? Ilé Ìṣọ́, 9/1/2003
Ojú Tí Wọ́n Fi Ń Wo Àwọn Arúgbó Ń Yí Padà Jí!, 9/8/2001
Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò-Kíkún
Jèhófà Máa Jẹ́ Kí Àwọn Ìpinnu Rẹ Yọrí Sí Rere Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 7/2017
Àwọn Ọ̀nà Tó O Fi Lè Mú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Gbòòrò Sí I A Ṣètò Wa, orí 10
Máa Ṣìkẹ́ Àǹfààní Tó O Ní Láti Jẹ́ Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ Pẹ̀lú Jèhófà! Ilé Ìṣọ́, 10/15/2014
Ẹ Máa Rántí Àwọn Tó Ń Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún Ilé Ìṣọ́, 9/15/2014
Ìgbẹ́kẹ̀lé Nínú Jèhófà Mú Èrè Wá Ilé Ìṣọ́, 10/15/2013
O Lè Sin Jèhófà Kó O Má Sì Kábàámọ̀ Ilé Ìṣọ́, 1/15/2013
Lo Ipò Nǹkan Tó Ń Yí Padà Lọ́nà Tó Dáa Ilé Ìṣọ́, 3/1/2003
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Kí Lẹ Máa Fi Ìgbésí Ayé Yín Ṣe? Ìgbésí Ayé Yín
Kí Ló Dé Tí Wọn Kò Bímọ? Ilé Ìṣọ́, 8/1/2000
Aṣáájú-Ọ̀nà
Ṣé O Lè Gbìyànjú Rẹ̀ Wò fún Ọdún Kan? Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 7/2016
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Iṣẹ́ Ìsìn Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 7/2016
Iṣẹ́ Ìsìn Aṣáájú-Ọ̀nà Máa Jẹ́ Kó O Túbọ̀ Sún Mọ́ Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 9/15/2013
Kí Ni Aṣáájú-Ọ̀nà? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 13
Àwọn Ilé Ẹ̀kọ́ Tó Wà Fáwọn Aṣáájú-ọ̀nà Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 14
Àpótí Ìbéèrè: Kí la lè ṣe láti ran àwọn aṣáájú-ọ̀nà lọ́wọ́? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2010
“O Lè Ṣe Aṣáájú-Ọ̀nà!” Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2010
O Lè Di Ọlọ́rọ̀! Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2008
Wọ́n Yan Ohun Tó Sàn Jù Ṣé Wàá Fara Wé Wọn? Ilé Ìṣọ́, 1/15/2008
Ṣé Wàá Gba Ẹnu Ọ̀nà “Ńlá Tí Ń Ṣamọ̀nà sí Ìgbòkègbodò” Wọlé? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 6/2007
Ẹ Ní Ẹ̀mí Aṣáájú Ọ̀nà Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 8/2004
Iṣẹ́ Ìsìn ní Bẹ́tẹ́lì
Ibo Là Ń Pè Ní Bẹ́tẹ́lì? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 21
Kí Là Ń Ṣe ní Àwọn Ẹ̀ka Ọ́fí ìsì Wa? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 22
Gbogbo Èèyàn La Pè! Ilé Ìṣọ́, 8/15/2010
Ǹjẹ́ O Lè Yọ̀ǹda Ara Rẹ? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 4/2003
Èyí Ha Lè Jẹ́ Iṣẹ́ Tó Dára Jù Lọ fún Ọ Bí? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2001
Iṣẹ́ Míṣọ́nnárì
Béèyàn Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí Lẹ́nu Iṣẹ́ Míṣọ́nnárì Ilé Ìṣọ́, 9/1/2009
Nínàgà fún Àǹfààní Iṣẹ́ Ìsìn
Bí Àwọn Alàgbà Ṣe Ń Kọ́ Àwọn Míì Kí Wọ́n Lè Tóótun Ilé Ìṣọ́, 4/15/2015
‘Pa Dà Kí O sì Fún Àwọn Arákùnrin Rẹ Lókun’ Ilé Ìṣọ́, 8/15/2014
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́kùnrin, Ǹjẹ́ Ẹ Ṣe Tán Láti Di Ìránṣẹ́ Tàbí Alàgbà? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 7/2013
Ẹ Kọ́ Àwọn Mí ì Kí Wọ́n Lè Tóótun fún Àǹfààní Iṣẹ́ Ìsìn Ilé Ìṣọ́, 11/15/2011
Bá A Ṣe Lè Fi Ọwọ́ Pàtàkì Mú Iṣẹ́ Ìsìn Wa sí Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 4/15/2011
Ẹ̀yin Arákùnrin, Ẹ Fúnrúgbìn Nípa Tẹ̀mí, Kẹ́ Ẹ sì Máa Wá Àǹfààní Iṣẹ́ Ìsìn! Ilé Ìṣọ́, 5/15/2010
Jẹ́ Kí Ìlọsíwájú Rẹ Máa Fara Hàn Kedere Ilé Ìṣọ́, 12/15/2009
Mọyì Ojúṣe Rẹ Nínú Ìjọ Ilé Ìṣọ́, 11/15/2009
Ṣé O Ti Sìn Nígbà Kan Rí? Ǹjẹ́ O Tún Lè Sìn Lẹ́ẹ̀kan Sí I? Ilé Ìṣọ́, 8/15/2009
Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Tí Wọ́n Jẹ́ “Àpẹẹrẹ Fún Agbo”
A Fẹ́ Kó O Ṣèrànwọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 1/2006
Lo Ipò Nǹkan Tó Ń Yí Padà Lọ́nà Tó Dáa Ilé Ìṣọ́, 3/1/2003
Ẹ̀yin Alàgbà—Ẹ Kọ́ Àwọn Ẹlòmíràn Láti Gbé Ẹrù Náà Ilé Ìṣọ́, 1/1/2002
Ìránṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́
Àwọn Ìránṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ń Ṣe Ìjọ Láǹfààní A Ṣètò Wa, orí 6
Kí Ni Ojúṣe Àwọn Ìránṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 16
Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Tí Wọ́n Jẹ́ “Àpẹẹrẹ fún Agbo”
Ohun Téèyàn Gbọ́dọ̀ Dójú Ìlà Rẹ̀
Àwọn Ìránṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ń Ṣe Ìjọ Láǹfààní A Ṣètò Wa, orí 6
Ǹjẹ́ Ò Ń ‘Nàgà fún Iṣẹ́ Àtàtà’? Ilé Ìṣọ́, 9/15/2014
Ṣé Ò Ń Dámọ̀ràn Ara Rẹ Fáwọn Ẹlòmíràn? (§ Àwọn Àǹfààní Nínú Ìjọ) Ilé Ìṣọ́, 4/15/2000
Alàgbà
Àwọn Alábòójútó Tó Ń Ṣe Olùṣọ́ Àgùntàn Agbo A Ṣètò Wa, orí 5
A Ṣètò Wa Láti Jọ́sìn “Ọlọ́run Àlàáfíà” Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 12
Àwọn Alàgbà Jẹ́ ‘Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ Fún Ìdùnnú Wa’ Ilé Ìṣọ́, 1/15/2013
Báwo Ni Àwọn Alàgbà Ṣe Ń Ran Ìjọ Lọ́wọ́? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 15
Ǹjẹ́ O Lè Ṣe Bíi Ti Fíníhásì Bó O Bá Dojú Kọ Àwọn Ipò Tó Nira? Ilé Ìṣọ́, 9/15/2011
Fífaṣẹ́lénilọ́wọ́—Kí Nìdí Tó Fi Ṣe Pàtàkì Báwo Ló sì Ṣe Yẹ Ká Ṣe É? Ilé Ìṣọ́, 6/15/2009
Ṣé Bíi Ti Jèhófà Lo Ṣe Ń Bìkítà Nípa Àwọn Ẹlòmí ì? Ilé Ìṣọ́, 6/15/2007
Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Tí Wọ́n Jẹ́ “Àpẹẹrẹ Fún Agbo”
Tó O Bá Wà Nípò Àṣẹ, Máa Fara Wé Kristi Ilé Ìṣọ́, 4/1/2006
Ẹ̀yin Alàgbà—Ẹ Kọ́ Àwọn Ẹlòmíràn Láti Gbé Ẹrù Náà Ilé Ìṣọ́, 1/1/2002
Ohun Téèyàn Gbọ́dọ̀ Dójú Ìlà Rẹ̀
Ǹjẹ́ Ò Ń ‘Nàgà fún Iṣẹ́ Àtàtà’? Ilé Ìṣọ́, 9/15/2014
Ṣé Ò Ń Dámọ̀ràn Ara Rẹ Fáwọn Ẹlòmíràn? (§ Àwọn Àǹfààní Nínú Ìjọ) Ilé Ìṣọ́, 4/15/2000
Ṣíṣe Olùṣọ́ Àgùntàn
Ẹ̀yin Olùṣọ́ Àgùntàn, Ẹ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Ńlá Náà Ilé Ìṣọ́, 11/15/2013
Ẹ̀yin Alàgbà, Ẹ Máa Tu “Ọkàn Tí Àárẹ̀ Mú” Lára Ilé Ìṣọ́, 6/15/2013
“Ẹ Máa Ṣe Olùṣọ́ Àgùntàn Agbo Ọlọ́run Tí Ń Bẹ Lábẹ́ Àbójútó Yín” Ilé Ìṣọ́, 6/15/2011
‘Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Ní Ìbámu Pẹ̀lú Ọkàn-àyà Mi’ Jeremáyà, orí 11
Ìfẹ́ Kristi Ń Mú Ká Ní Ìfẹ́ (§ Ẹ Máa Hùwà Bíi Kristi Sáwọn Tó Hùwà Àìtọ́) Ilé Ìṣọ́, 9/15/2009
Ibi Ìfarapamọ́sí Kúrò Lọ́wọ́ Ẹ̀fúùfù Ilé Ìṣọ́, 2/15/2002
Ẹ̀yin Kristẹni Olùṣọ́ Àgùntàn,—‘Ẹ Jẹ́ Kí Ọkàn-Àyà Yín Gbòòrò’! Ilé Ìṣọ́, 7/1/2000
Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àti Fífa Iṣẹ́ Lé Àwọn Míì Lọ́wọ́
Fi ‘Nǹkan Wọ̀nyí Lé Àwọn Olùṣòtítọ́ Lọ́wọ́’ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 1/2017
Alábòójútó Àyíká
Àwọn Alábòójútó Tó Ń Ṣe Olùṣọ́ Àgùntàn Agbo (§ Alábòójútó Àyíká) A Ṣètò Wa, orí 5
Báwo Ni Àwọn Alábòójútó Arìnrìn-Àjò Ṣe Ń Ràn Wá Lọ́wọ́? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 17
Pọ́ọ̀lù “Ń Fún Àwọn Ìjọ Lókun” Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, orí 15
Ìṣòro Nínú Ìjọ
Bí Gáyọ́sì Ṣe Ran Àwọn Ará Lọ́wọ́ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 5/2017
Bí A Ṣe Lè Jẹ́ Kí Àlàáfíà Jọba Láàárín Wa Ká sì Jẹ́ Mímọ́ A Ṣètò Wa, orí 14
Ẹ Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Ẹnu Yín “Dára fún Gbígbéniró” ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 12 ¶11 àti 12
Kí A Gbé Ìjọ Ró (§ Má Ṣe Kúrò Nínú Ìjọ Ọlọ́run) Ilé Ìṣọ́, 4/15/2007
Àwọn Ohun Rere Inú Ètò Jèhófà Ni Kó O Máa Fiyè Sí Ilé Ìṣọ́, 7/15/2006
Ìyọlẹ́gbẹ́ àti Ìmúra-Ẹni-Kúrò-Lẹ́gbẹ́
Tún wo ìwé pẹlẹbẹ:
Idà Ni Òtítọ́ Ń Mú Wá, Kì Í Ṣe Àlàáfíà Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 10/2017
Ìdí Tí Ìyọlẹ́gbẹ́ Fi Jẹ́ Ìpèsè Onífẹ̀ẹ́ Ilé Ìṣọ́, 4/15/2015
Bí A Ṣe Lè Jẹ́ Kí Àlàáfíà Jọba Láàárín Wa Ká sì Jẹ́ Mímọ́ A Ṣètò Wa, orí 14
Má Ṣe Jẹ́ Kí Ohunkóhun Mú ẹ Jìnnà sí Jèhófà (§ Àjọṣe Ìdílé) Ilé Ìṣọ́, 1/15/2013
Ọwọ́ Tó Yẹ Ká Fi Mú Ẹni Tí Wọ́n Bá Yọ Lẹ́gbẹ́ ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ Àfikún
Bó Ò Ṣe Ní Yẹsẹ̀ Tí Ọmọ Rẹ Bá Kẹ̀yìn sí Ìlànà Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 1/15/2007
Máa Gba Ìbáwí Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 11/15/2006
Nígbà Tí Èèyàn Wa Kan Bá Fi Jèhófà Sílẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 9/1/2006
Ìrònúpìwàdà
Sún Mọ́ Ọlọ́run: “Jọ̀wọ́ Jẹ́ Ká Pa Dà Wá Sílé” Ilé Ìṣọ́, 4/1/2012
“Wá Jèhófà” Nípa Jíjọ́sìn Rẹ̀ Lọ́nà Tó Fẹ́ (§ Padà Sọ́dọ̀ Jèhófà) Ọjọ́ Jèhófà, orí 5
“Àwọn Ọ̀nà Jèhófà Dúró Ṣánṣán” (§ Àwọn Tó Dẹ́ṣẹ̀ Lè Padà Sọ́dọ̀ Jèhófà) Ilé Ìṣọ́, 11/15/2005
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ǹjẹ́ Ẹ̀ṣẹ̀ Kan Wà Tí Kò Ní Ìdáríjì? Jí!, 2/8/2003
Ǹjẹ́ Àwọn Tó Ń Ṣe Ohun Búburú Lè Yí Padà? Olùkọ́, orí 25
Ìjẹ́wọ́ Tí Ń Yọrí sí Ìwòsàn Ilé Ìṣọ́, 6/1/2001
Àwọn Aláìṣiṣẹ́mọ́
Tún wo ìwé pẹlẹbẹ:
Fún Àwọn Aláìṣiṣẹ́mọ́ Níṣìírí Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 4/2017
Iṣẹ́ Ìwàásù
Ọkàn Àwọn Èèyàn Ló Ṣe Pàtàkì, Kì Í Ṣe Ìrísí Wọn Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 6/2017
Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Ìwàásù Ìhìn Rere Máa Fún Ẹ Láyọ̀ Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 6/2017
Máa Fọgbọ́n Lo Àwọn Ìtẹ̀jáde Wa Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 2/2017
Ṣé Bí Ìrì Ni Iṣẹ́ Ìwàásù Rẹ Rí? Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 4/2016
À Ń Láyọ̀ Bá A Ṣe Ń Bá Ọlọ́run Ṣiṣẹ́ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 1/2016
Ọgọ́rùn-ún Ọdún Tí Ìjọba Ọlọ́run Ti Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣàkóso! Ilé Ìṣọ́, 11/15/2015
Máa Ra Àkókò Tí Ó Rọgbọ Pa Dà Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 4/2015
Máa Fi Ìdúróṣinṣin Ti Àwọn Arákùnrin Kristi Lẹ́yìn Ilé Ìṣọ́, 3/15/2015
Máa Fi Ìtara Wàásù Nìṣó Ilé Ìṣọ́, 2/15/2015
Àwọn Òjíṣẹ́ Tó Ń Wàásù Ìhìn Rere A Ṣètò Wa, orí 8
Máa Lo Àǹfààní Tó O Bá Ní Láti Tan Ìhìn Rere Ìjọba Náà Kálẹ̀! Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2014
“Ẹ Ó sì Jẹ́ Ẹlẹ́rìí Mi” Ilé Ìṣọ́, 7/15/2014
Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Tí Kò Fi Bẹ́ẹ̀ Mọ̀wé Kà Lọ́wọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 6/2014
‘Oúnjẹ Mi Ni Láti Ṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run’ Ilé Ìṣọ́, 5/15/2014
Má Ṣe Jẹ́ Alábàáṣiṣẹ́ Tí Kì Í Sọ̀rọ̀ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 1/2014
Àwọn Oníwàásù—Àwọn Òjíṣẹ́ Ọlọ́run Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 6
Àwọn Àbájáde Iṣẹ́ Ìwàásù—“Àwọn Pápá . . . Ti Funfun fún Kíkórè” Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 9
O Ò Ṣe Ṣiṣẹ́ Díẹ̀ Sí I? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 2/2013
Ṣé Wàá Fẹ́ Ní Ìpínlẹ̀ Ìwàásù Tìrẹ? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 1/2013
Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Tẹ́tí sí Ọlọ́run Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 7/2012
Ìdí Méjìlá Tá A Fi Ń Wàásù Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 6/2012
Ẹ Máa Ṣọ́ra Tẹ́ Ẹ Bá Wà Lóde Ẹ̀rí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2012
Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè “Jí Lójú Oorun” Ilé Ìṣọ́, 3/15/2012
Wọ́n Fi Ìgboyà Polongo Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run! Ilé Ìṣọ́, 2/15/2012
Kọ́ Bó O Ṣe Lè Máa Ṣọ́nà Látinú Àpẹẹrẹ Àwọn Àpọ́sítélì Jésù Ilé Ìṣọ́, 1/15/2012
Báwo La Ṣe Ṣètò Iṣẹ́ Ìwàásù Ìjọba Ọlọ́run Tí À Ń Ṣe? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 12
“Wákàtí Mélòó Ni Kí N Ròyìn?” Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 6/2011
Báwo Lo Ṣe Lè Máa Fi Ìfaradà Ṣe Iṣẹ́ Ìwàásù Lọ? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2009
Ṣáwọn Míṣọ́nnárì Dé Ìpẹ̀kun Ìlà Oòrùn Ayé? Ilé Ìṣọ́, 1/1/2009
“Títí Dé Apá Ibi Jíjìnnà Jù Lọ ní Ilẹ̀ Ayé” Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, orí 28
“Ẹ̀rí fún Gbogbo Àwọn Orílẹ̀-Èdè” Ilé Ìṣọ́, 2/1/2006
“Ẹ Pòkìkí Èyí Láàárín Àwọn Orílẹ̀-Èdè” Ọjọ́ Jèhófà, orí 13
‘Ẹ Lọ, Kí Ẹ sì Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn’ Ilé Ìṣọ́, 7/1/2004
Ojú Wo Ló Yẹ Ká Máa Fi Wo Àwọn Èèyàn bí Ọjọ́ Jèhófà Ṣe Ń Sún Mọ́lé? Ilé Ìṣọ́, 7/15/2003
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ǹjẹ́ Ó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Wàásù Fáwọn Ẹlòmíràn? Jí!, 6/8/2002
Ṣé Ìjọ Yín Ní Ìpínlẹ̀ Tó Tóbi Gan-an? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2002
Gbogbo Orílẹ̀-Èdè Ni Ọlọ́run Tẹ́wọ́ Gbà Ilé Ìṣọ́, 4/1/2002
Ìhìn Tí A Ní Láti Polongo Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
Àwọn Wo Ni Òjíṣẹ́ Ọlọ́run Lóde Òní? Ilé Ìṣọ́, 11/15/2000
“Àwọn Ohun Fífani-lọ́kàn-mọ́ra” Ń Kún Ilé Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 1/15/2000
Bí A Ṣe Lè Sunwọ̀n Sí I
Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Bí O Ṣe Lè Fi Ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni Lọni
Máa Lo Àwọn Ohun Pàtàkì Tó Wà Nínú Ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni Lọ́nà Tó Gbéṣẹ́
Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Bó O Ṣe Lè Dá Àwọn Ẹni Tuntun Lẹ́kọ̀ọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 8/2015
Àwọn Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 7/2015
Bí O Ṣe Lè Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Akéde Tó Nírìírí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 6/2015
Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Fi Fóònù Wàásù Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 2/2015
Máa Tẹ̀ Síwájú Gẹ́gẹ́ Bí Òjíṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 1/2015
Máa Lo Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ Yè! Ilé Ìṣọ́, 8/15/2014
Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Fi Ìgboyà Sọ̀rọ̀ Nípa Ìjọba Ọlọ́run Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 8/2014
Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Bẹ̀rẹ̀ Ìjíròrò Lọ́nà Àìjẹ́-Bí-Àṣà Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 7/2014
Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Múra Ìnasẹ̀ Ọ̀rọ̀ Rẹ Sílẹ̀ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2014
Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Ṣàkọsílẹ̀ Àwọn Tó Fìfẹ́ Hàn Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 2/2014
Máa Ṣe Ojúṣe Rẹ Gẹ́gẹ́ Bí Ajíhìnrere Ilé Ìṣọ́, 5/15/2013
“Máa Bá A Lọ ní Fífi Ara Rẹ . . . fún Kíkọ́ni” Ilé Ìṣọ́, 7/15/2010
Fiyè sí “Ọnà Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́” Rẹ Ilé Ìṣọ́, 1/15/2008
Bá A Ṣe Lè Di Òjíṣẹ́ Tó Mọṣẹ́ Rẹ̀ Níṣẹ́ Tó Tún Mọwọ́ Yí Padà Ilé Ìṣọ́, 12/1/2005
Ìtọ́ni Jésù Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Láti Jẹ́rìí Kúnnákúnná Ilé Ìṣọ́, 1/1/2005
Ǹjẹ́ Bó O Ṣe Ń Kọ́ni Múná Dóko? Ilé Ìṣọ́, 7/1/2002
A Ti Mú Wa Gbára Dì fún Iṣẹ́ Olùkọ́ni Ní Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ilé Ìṣọ́, 2/15/2002
Bí A Ṣe Lè Mú Ọ̀nà Tí A Gbà Ń Fọ̀rọ̀ Wérọ̀ Sunwọ̀n Sí I Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
Mọ Bí Ó Ṣe Yẹ Kí O Dáhùn Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
Iṣẹ́ Ìwàásù Ilé-dé-Ilé
Máa Hùwà Tó Bójú Mu Lóde Ẹ̀rí Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 7/2017
Tí Ọmọdé Kan Bá Sọ Pé Ká Wọlé Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 9/2016
“Màá Gba Ìwé Yín Tí Ìwọ Náà Bá Gba Ìwé Wa” Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 9/2013
Ǹjẹ́ O Máa Ń Lo Àwọn Ìwé Pẹlẹbẹ Yìí? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 1/2012
Bá A Ṣe Lè Lo Fọ́ọ̀mù Padà-Lọ-Ṣèbẹ̀wò, ìyẹn Please Follow Up (S-43) Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2011
Bá A Ṣe Lè Lo Ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni Láti Wàásù Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 3/2006
“Ṣe Iṣẹ́ Ajíhìnrere” Ilé Ìṣọ́, 3/15/2004
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Bí Mo Bá Lọ Pàdé Ọmọ Iléèwé Mi Ńkọ́? Jí!, 3/8/2002
Awọn Ìnasẹ̀-Ọ̀rọ̀ Fún Lílò Ninu Iṣẹ́-Ìsìn Pápá Bí A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ìjíròrò
Bí O Ṣe Lè Dáhùnpadà sí Awọn Ọ̀rọ̀ Tí Ó Lè Bẹ́gidínà Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀pọ̀ Bí A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ìjíròrò
Ìjíròrò Láàárín Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti Ẹnì Kan (Ọ̀wọ́ àpilẹ̀kọ Ilé Ìṣọ́)
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Ṣe Ìrántí Ikú Jésù? Ilé Ìṣọ́, 4/1/2015
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Ṣàyẹ̀wò Bíbélì? Ilé Ìṣọ́, 2/1/2015
Bí A Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tá A Gbà Gbọ́ Nípa Ọdún 1914 Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2014
Ìgbà Wo Ni Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀?—Apá 1 Ilé Ìṣọ́, 10/1/2014
Ìgbà Wo Ni Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀?—Apá 2 Ilé Ìṣọ́, 11/1/2014
Ǹjẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gba Jésù Gbọ́? Ilé Ìṣọ́, 5/1/2014
Kí Nìdí Tí Ọlọ́run fi Fàyè Gba Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé? Ilé Ìṣọ́, 1/1/2014
Ǹjẹ́ Ìyà Tó Ń Jẹ Wá Tiẹ̀ Kan Ọlọ́run? Ilé Ìṣọ́, 7/1/2013
Ṣé Ọlọ́run Máa Ń Dá Àwọn Èèyàn Lóró Nínú Iná Ọ̀run Àpáàdì? Ilé Ìṣọ́, 10/1/2012
Ṣé Gbogbo Èèyàn Rere Ló Máa Lọ sí Ọ̀run? Ilé Ìṣọ́, 8/1/2012
Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run? Ilé Ìṣọ́, 4/1/2012
Kí Ni Ẹ̀mí Mímọ́? Ilé Ìṣọ́, 10/1/2010
Ìpadàbẹ̀wò àti Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Ṣe Ìpadàbẹ̀wò Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 11/2017
Kọ́ Wọn Láti Máa Sin Jèhófà Láìyẹsẹ̀ Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 9/2017
Bá A Ṣe Lè Lo Ìwé Àwọn Wo Ló Ń ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní? Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 3/2017
Bá A Ṣe Máa Lo Ìwé Tẹ́tí sí Ọlọ́run Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 3/2017
Bá A Ṣe Máa Lo Ìwé Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa? Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 11/2016
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dá Àwọn Míì Lẹ́kọ̀ọ́? Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 8/2016
Bí A Ṣe Lè Fi Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Darí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 1/2016
Àpótí Ìbéèrè: Ìgbà wo ló yẹ kó o dá ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kan dúró? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 12/2015
Bí A Ṣe Lè Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Wa Wọ Àwọn Tí À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Lọ́kàn Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2015
Máa Pọkàn Pọ̀ Sórí Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 7/2015
Bí A Ṣe Lè Máa Darí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́nà Tó Múná Dóko Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 12/2014
Ó Yẹ Ká Tètè Wá Wọn Lọ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 6/2014
Bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Pẹ̀lú Àwọn Tó Ò Ń Fún Ní Ìwé Ìròyìn Déédéé Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 1/2014
Máa Fi Àwọn Fídíò Wa Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2013
Bá A Ṣe Lè Lo Ìwé Àwọn Wo Ló Ń Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 3/2013
Bá A Ṣe Lè Lo Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run! Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 3/2013
Túbọ̀ Sa Gbogbo Ipá Rẹ—Tó O Bá Ń Rò Pé O Kò Tóótun Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2012
Túbọ̀ Sa Gbogbo Ipá Rẹ—Tọ́wọ́ Rẹ Bá Tiẹ̀ Máa Ń Dí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2012
Ohun Márùn-ún Tó O Lè Ṣe Kó O Lè Ní Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2012
Ẹ Ran Àwọn Ọkùnrin Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Tẹ̀ Síwájú Nípa Tẹ̀mí Ilé Ìṣọ́, 11/15/2011
Bá A Ṣe Máa fi Ìwé “Ìfẹ́ Ọlọ́run” Darí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 3/2009
Ìmúrasílẹ̀—Ọ̀nà Kan Ṣoṣo Láti Ṣe Ìpadàbẹ̀wò Tó Múná Dóko Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 7/2008
Àpẹẹrẹ Olùkọ́ Ńlá Náà Ni Kó O Máa Tẹ̀ Lé Bó O Bá Ń Lo Ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 2/2007
Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Nínú Ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 3/2006
Bí A Ṣe Lè Darí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Tí Yóò Máa Tẹ̀ Síwájú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2005
Mú Kí Ìfẹ́ Àwọn Tó Ò Ń Fún Ní Ìwé Ìròyìn Déédéé Jinlẹ̀ Sí I Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2005
Ǹjẹ́ Òtítọ́ Ń So Èso Nínú Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́? Ilé Ìṣọ́, 2/1/2005
‘Ẹ Kọ́ Wọn Láti Pa Gbogbo Ohun Tí Mo Ti Pa Láṣẹ fún Yín Mọ́’ Ilé Ìṣọ́, 7/1/2004
‘Ṣàṣeparí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ ní Kíkún’ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2004
‘Gba Ara Rẹ Àtàwọn Tí Ń Fetí sí Ọ Là’ Ilé Ìṣọ́, 6/1/2000
Onírúurú Ọ̀nà Ìjẹ́rìí
Àwọn Ọ̀nà Tá À Ń Gbà Wàásù Ìhìn Rere A Ṣètò Wa, orí 9
Máa Lo Ìwé Àṣàrò Kúkúrú Láti Wàásù Ìhìn Rere Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2012
Ǹjẹ́ O Lè Kópa Nínú Ìjẹ́rìí Ìrọ̀lẹ́? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2012
Bá A Ṣe Lè Kọ́kọ́ Wá Àwọn Èèyàn Ká Tó Wàásù Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 7/2012
Ẹ Sapá Gidigidi Láti Wàásù Fáwọn Ọkùnrin Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 8/2009
“Jẹ́rìí Kúnnákúnná” Nígbà Tó O Bá Ń Wàásù Nílé Elérò Púpọ̀ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 12/2008
Ìjẹ́rìí Àìjẹ́-Bí-Àṣà
O Lè Jẹ́rìí Láìjẹ́-Bí-Àṣà! Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 8/2010
Wíwàásù Láìjẹ́-Bí-Àṣà Fáwọn Tó Ń Sọ Èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Mẹ́síkò Ilé Ìṣọ́, 4/15/2004
Wíwàásù Láwọn Ibi Tí Èrò Máa Ń Pọ̀ Sí
Bá A Ṣe Lè Jẹ́rìí Nípa Lílo Àwọn Ohun Tá A Fi Ń Pàtẹ Àwọn Ìwé Wa Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 4/2015
Ọ̀nà Tuntun Tó Lárinrin Tá A Ó Máa Gbà Wàásù Láwọn Ibi Tí Èrò Pọ̀ Sí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2014
Ó Yẹ Ká Tètè Wá Wọn Lọ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 6/2014
Ọ̀nà Tuntun Tá A Fẹ́ Máa Gbà Wàásù Láwọn Ibi Tí Èrò Pọ̀ Sí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 7/2013
Ibi Táwọn Èèyàn Ti Ń Ṣiṣẹ́ Ajé
Fi Ìgboyà Wàásù Níbi Táwọn Èèyàn Ti Ń Ṣiṣẹ́ Ajé Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 3/2012
Ìjẹ́rìí Nílé Ìwé
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nípa Ọlọ́run? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 36
Ó Bá Àwọn Ọmọ Kíláàsì Rẹ̀ Sọ̀rọ̀ Nípa Ẹ̀sìn Rẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 10/1/2004
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Jèhófà Ò Mà Ní Gbàgbé Iṣẹ́ Yín! Ilé Ìṣọ́, 4/15/2003
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Wàásù fún Àwọn Ọmọ Iléèwé Mi? Jí!, 4/8/2002
Wíwàásù fún Àwọn Mọ̀lẹ́bí
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: Ó Fara Da Ọgbẹ́ Ọkàn Ilé Ìṣọ́, 5/1/2014
Bá A Ṣe Lè Mú Kí Àwọn Ìbátan Wa Tí Kì í Ṣe Ẹlẹ́rìí Nífẹ̀ẹ́ Òtítọ́ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2014
Báwo Lo Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ fún Ọkọ Tàbí Aya Tó Jẹ́ Aláìgbàgbọ́? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2010
Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Wàásù fún Àwọn Mọ̀lẹ́bí Wa? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 12/2004
Fífi Fóònù Wàásù àti Lẹ́tà Kíkọ
Fífi Fóònù Wàásù Máa Ń Gbéṣẹ́ Gan-an Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2009
Fífi Lẹ́tà Báni Sọ̀rọ̀ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
Ìjẹ́rìí Orí Tẹlifóònù Tó Ń Yọrí sí Rere Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 2/2001
Wíwàásù ní Ọgbà Ẹ̀wọ̀n
Àwọn Tó Wà Ní Ilé Ìtọ́jú Àwọn Arúgbó
Ẹ Máa Rántí Àwọn Tó Wà Ní Ilé Ìtọ́jú Àwọn Arúgbó Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 6/2014
Wíwàásù fún Àwọn Afọ́jú
Ran Àwọn Afọ́jú Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Mọ Jèhófà Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2015
Sísìn Níbi Tí Wọ́n Ti Nílò Oníwàásù Púpọ̀ Sí I
Bí Ara Ẹ Ṣe Lè Mọlé Nínú Ìjọ Tó O Wà Báyìí Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 11/2017
Ṣé O Lè Ran Ìjọ Rẹ Lọ́wọ́? Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 3/2016
Àwọn Ọ̀nà Tó O Fi Lè Mú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Gbòòrò Sí I A Ṣètò Wa, orí 10
Ǹjẹ́ O Lè ‘Ré Kọjá Lọ sí Makedóníà’? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2011
Ǹjẹ́ O Lè Ré Kọjá Lọ sí Makedóníà? Ilé Ìṣọ́, 12/15/2009
Ṣé O Lè Lọ Sìn Níbi Tí Wọ́n Ti Nílò Oníwàásù Púpọ̀ Sí I? Ilé Ìṣọ́, 4/15/2009
“Rékọjá Wá sí Makedóníà” Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, orí 16
Iṣẹ́ Ìwàásù Tí A Kò Lè Gbàgbé Ilé Ìṣọ́, 4/15/2003
Ǹjẹ́ O Lè Sìn Níbi Tí Àìní Gbé Pọ̀? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 7/2001
“Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú” (Ọ̀wọ́ àpilẹ̀kọ Ilé Ìṣọ́)
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Tọ́kì Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 7/2017
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 1/2017
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Gánà Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 7/2016
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Rọ́ṣíà Ilé Ìṣọ́, 7/15/2015
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní New York Ilé Ìṣọ́, 1/15/2015
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Taiwan Ilé Ìṣọ́, 10/15/2014
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Micronesia Ilé Ìṣọ́, 7/15/2014
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà Ilé Ìṣọ́, 1/15/2014
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Philippines Ilé Ìṣọ́, 10/15/2013
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Mẹ́síkò Ilé Ìṣọ́, 4/15/2013
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Norway Ilé Ìṣọ́, 1/15/2013
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Brazil Ilé Ìṣọ́, 10/15/2012
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Ecuador Ilé Ìṣọ́, 7/15/2012
Àwọn Tó Ń Sọ Èdè Mí ì
Ìpinnu Tí Mo Ṣe Nígbà Tí Mo Wà ní Kékeré Ilé Ìṣọ́, 1/15/2014
Bá A Ṣe Lè Wàásù fún Àwọn Tó Ń Sọ Èdè Mí ì Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2009
Ǹjẹ́ O Lè Lọ Sìn ní Ìjọ Tí Wọ́n Ti Ń Sọ Èdè Ilẹ̀ Òkèèrè? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2006
Ṣíṣèrànwọ́ fún Àwùjọ Kan Tí Èdè Wọn Yàtọ̀ ní Korea Ilé Ìṣọ́, 6/15/2003
Iṣẹ́ Ìtumọ̀ Èdè Ń Ti Iṣẹ́ Ìwàásù Lẹ́yìn
“Kí Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Erékùṣù Máa Yọ̀” Ilé Ìṣọ́, 8/15/2015
Ilé Ìṣọ́ Tá A Fi Èdè Gẹ̀ẹ́sì Tó Rọrùn Kọ—Kí Nìdí Tá A Fi Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Tẹ̀ Ẹ́? Ilé Ìṣọ́, 12/15/2012
Báwo Ni A Ṣe Ń Kọ Àwọn Ìwé Wa, Tí A sì Ń Túmọ̀ Wọn? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 23
Ìhìn Rere ní Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta Èdè Ilé Ìṣọ́, 11/1/2009
“Tèmi Ni Fàdákà, Tèmi sì Ni Wúrà” Ilé Ìṣọ́, 11/1/2007
Àwọn Ọmọ Ìbílẹ̀ Mẹ́síkò Ń Gbọ́ Ìhìn Rere Náà Ilé Ìṣọ́, 8/15/2004
Àkókò Láti Dáwọ̀ọ́ Ìdùnnú ní Àwọn Orílẹ̀-Èdè Balkan Ilé Ìṣọ́, 10/15/2002
Ètò Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Tó Kárí Ayé (§ Ìdí Tí Wọ́n Fi Ń Tẹ Àwọn Ìwé Náà ní Èdè Abínibí) Jí!, 1/8/2001
Ojú Ìwòye àti Ìgbàgbọ́
Tún wo ìwé pẹlẹbẹ:
Àwọn Kristẹni Ń jọ́sìn Ní Ẹ̀mí Àti Òtítọ́ Ilé Ìṣọ́, 7/15/2002
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣé Ó Yẹ Káwọn Kristẹni Retí Pé Kí Ọlọ́run Yọ Wọ́n Nínú Gbogbo Ewu? Jí!, 4/8/2002
Ìlànà Ìwà Híhù
Báwo Lèèyàn Ṣe Lè Gbé Ìgbé Ayé Rere? Ilé Ìṣọ́, 4/15/2008
Ìlànà Ìwà Rere Tó Wà Títí Ayé Ilé Ìṣọ́, 6/15/2007
Máa Fi Ìwà Rere Kristẹni Kọ́ Ara Rẹ Àtàwọn Ẹlòmíràn Ilé Ìṣọ́, 6/15/2002
Ọtí Líle
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ọtí Líle Jí!, 9/2013
Ṣọ́ra Fún Ọtí Àmujù Ilé Ìṣọ́, 12/1/2004
Àmúlùmálà Ìgbàgbọ́
Ìlàlóye Nípa Àwọn Ohun Tá A Gbà Gbọ́
À Ń Rìn Ní Ọ̀nà Ìmọ́lẹ̀ Tó Túbọ̀ Ń Mọ́lẹ̀ Sí I Ilé Ìṣọ́, 2/15/2006
‘Ọlọ́run, Rán Ìmọ́lẹ̀ Rẹ Jáde’ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2000
Àlìkámà àti Àwọn Èpò
“Wò Ó! Mo Wà Pẹ̀lú Yín Ní Gbogbo Àwọn Ọjọ́” Ilé Ìṣọ́, 7/15/2013
Àwọn Àgùntàn àti Ewúrẹ́
Àwọn Àpèjúwe Jésù
Sọ Fún Wa, Ìgbà Wo Ni Nǹkan Wọ̀nyí Yóò Ṣẹlẹ̀?
“Wò Ó! Mo Wà Pẹ̀lú Yín Ní Gbogbo Àwọn Ọjọ́”
“Àwọn Olódodo Yóò Máa Tàn Yòò Bí Oòrùn” Ilé Ìṣọ́, 3/15/2010
Àwọn Àpẹẹrẹ Tó Jẹ́ Àsọtẹ́lẹ̀
Èyí Ni “Ọ̀nà Tí Ìwọ Tẹ́wọ́ Gbà” Ilé Ìṣọ́, 3/15/2015
Àwọn Ará Ilé
“Ní Ti Tòótọ́, Ta Ni Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye?” Ilé Ìṣọ́, 7/15/2013
Àwọn Májẹ̀mú
Ní Ìgbàgbọ́ Tó Fẹsẹ̀ Múlẹ̀ Ṣinṣin Nínú Ìjọba Ọlọ́run Ilé Ìṣọ́, 10/15/2014
Bábílónì Ńlá
Ẹkún àti Ìpayínkeke
“Wò Ó! Mo Wà Pẹ̀lú Yín Ní Gbogbo Àwọn Ọjọ́” Ilé Ìṣọ́, 7/15/2013
Ẹlẹ́rìí Méjì (Ìṣípayá 11)
Ẹni Àmì Òróró
Sọ Fún Wa, Ìgbà Wo Ni Nǹkan Wọ̀nyí Yóò Ṣẹlẹ̀?
“Wò Ó! Mo Wà Pẹ̀lú Yín Ní Gbogbo Àwọn Ọjọ́”
Ẹrú Búburú
“Ní Ti Tòótọ́, Ta Ni Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye?” Ilé Ìṣọ́, 7/15/2013
Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye
Gọ́ọ̀gù Ti Ilẹ̀ Mágọ́gù
Gbígba Ẹni Tí Wọ́n Yọ Lẹ́gbẹ́ Pa Dà
Ìbẹ̀wò àti Iṣẹ́ Ìwẹ̀nùmọ́ Tẹ́ńpìlì
“Wò Ó! Mo Wà Pẹ̀lú Yín Ní Gbogbo Àwọn Ọjọ́” Ilé Ìṣọ́, 7/15/2013
Ìdẹwò Jésù
Ìfètòsọ́mọbíbí (IUD)
Ìjẹ́mímọ́ Ẹ̀jẹ̀
Ikú àti Àjíǹde
“Àjíǹde Èkíní” Ti Ń Lọ Lọ́wọ́! (§ Ǹjẹ́ Àjíǹde Èkíní Ti Ń Lọ Lọ́wọ́?) Ilé Ìṣọ́, 1/1/2007
Ìlà Ìdílé Mèsáyà
Ìpọ́njú Ńlá àti Amágẹ́dọ́nì
Sọ Fún Wa, Ìgbà Wo Ni Nǹkan Wọ̀nyí Yóò Ṣẹlẹ̀? Ilé Ìṣọ́, 7/15/2013
Ìran
Ipa Tí Ẹ̀mí Mímọ́ Ń Kó Nínú Bí Ète Jèhófà Ṣe Ń Ní Ìmúṣẹ Ilé Ìṣọ́, 4/15/2010 ¶13 àti 14
Wíwàníhìn-ín Kristi—Báwo Ló Ṣe Yé Ọ Sí? Ilé Ìṣọ́, 2/15/2008
Ìràpadà
Ọlọ́run Dámọ̀ràn Ìfẹ́ Rẹ̀ Fún Wa Ilé Ìṣọ́, 6/15/2011
Ìwà Àìmọ́ àti Ìwà Àìníjàánu
Ìyípadà Ológo
Ìran Tó Jẹ́ Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Ìjọba Ọlọ́run Nímùúṣẹ Ilé Ìṣọ́, 1/15/2005 ¶6 àti 7
Jọ́sìn Ní “Ẹ̀mí àti Òtítọ́” (Jòhánù 4:24)
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Kí ni sísin Jèhófà “ní ẹ̀mí” túmọ̀ sí? Ilé Ìṣọ́, 9/15/2001
Àwọn Kristẹni Ń jọ́sìn Ní Ẹ̀mí Àti Òtítọ́ Ilé Ìṣọ́, 7/15/2002
Ogunlọ́gọ̀ Ńlá àti Àwọn Àgùntàn Mìíràn
Ọkùnrin Tó Ní Ìwo Yíǹkì Akọ̀wé
Ọ̀pá Méjì (Ìsíkíẹ́lì 37)
Párádísè Tí Pọ́ọ̀lù Rí Nínú Ìran
Bá A Ṣe Lè Fi Kún Ẹwà Párádísè Tẹ̀mí Ilé Ìṣọ́, 7/15/2015
Tálẹ́ńtì
Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àpèjúwe Nípa Àwọn Tálẹ́ńtì Náà Ilé Ìṣọ́, 3/15/2015
Wúńdíá Mẹ́wàá
Ṣé Wàá “Máa Bá A Nìṣó Ní Ṣíṣọ́nà”? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2015
Ọwọ́ Tó Yẹ Ká Fi Mú Àwọn Aláṣẹ Onípò Gíga
Kò Sí Ohun Tó Lè Dá Wọn Dúró Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Bíbélì, ẹ̀kọ́ 95
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣó Yẹ Ká Máa Forúkọ Oyè Pe Àwọn Èèyàn? Jí!, 10/2008
Ta Ni Ìwọ Ń Ṣègbọràn Sí—Ọlọ́run Ni Tàbí Ènìyàn? Ilé Ìṣọ́, 12/15/2005
‘Bí Ẹnì Kan Bá Fipá Gbéṣẹ́ fún Ọ’ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2005
Bí A Ṣe Lè Mọ Ẹni Tó Yẹ Kí Á Ṣègbọràn Sí Olùkọ́, orí 28
“Ìgbàlà Jẹ́ Ti Jèhófà” Ilé Ìṣọ́, 9/15/2002
Wọ́n Ń Bá A Lọ ní Rírìn Nínú Òtítọ́ (§ Òtítọ́ àti “Àwọn Aláṣẹ Onípò Gíga”) Ilé Ìṣọ́, 7/15/2002
Owó Orí
Ṣé Dandan Ni Kéèyàn Máa San Owó Orí? Ilé Ìṣọ́, 9/1/2011
Ṣé Ìwà Àìṣòótọ́ Ni? (§ “Ẹ San Àwọn Ohun ti Késárì Padà fún Késárì”) Ilé Ìṣọ́, 6/1/2010
Àìdá sí Ìṣèlú àti Ogun Jíjà
Má Ṣe Dá Sí Ọ̀rọ̀ Òṣèlú Tàbí Ogun Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 4/2016
Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Ìjọba Ọlọ́run Ilé Ìṣọ́, 7/15/2015
Ìjọba Ọlọ́run Nìkan Ṣoṣo Là Ń Tì Lẹ́yìn Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 14
Látinú Àpamọ́ Wa: Wọ́n Dúró Ṣinṣin ní “Wákàtí Ìdánwò” Ilé Ìṣọ́, 5/15/2013
“Olùgbé fún Ìgbà Díẹ̀” Ni Wá Ilé Ìṣọ́, 12/15/2012
Ojú Wo Ni Jésù Fi Wo Ọ̀rọ̀ Ìṣèlú?
Kí Ló Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Ṣe Lónìí?
Báwo Ni Ẹ̀kọ́ Tí Àwọn Kristẹni Fi Ń Kọ́ni Ṣe Ń Ṣe Àwọn Ará Ìlú Láǹfààní?
Kí Nìdí Tí Jésù Kò Fi Lọ́wọ́ Nínú Ìṣèlú? Ilé Ìṣọ́, 7/1/2010
Ṣó Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Máa Jagun? Ilé Ìṣọ́, 10/1/2009
Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé: Kí Nìdí Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kì í Fi í Lọ Sójú Ogun? Ilé Ìṣọ́, 7/1/2008
Kíkí Àsíá, Dídìbò àti Sísin Ìlú Ẹni ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ Àfikún
Ǹjẹ́ Àìdá-sí-ìṣèlú Dí Ìfẹ́ Kristẹni Lọ́wọ́ Ilé Ìṣọ́, 5/1/2004
Àwọn Kristẹni Tí Kì Í Dá sí Tọ̀túntòsì Láwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn Ilé Ìṣọ́, 11/1/2002
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ǹjẹ́ Ọlọ́run Fọwọ́ sí Ogun Jíjà? Jí!, 5/8/2002
Ìtóye Ọ̀nà Ìwà Híhù Tí Ó Yẹ Láti Bọ̀wọ̀ Fún Ìmọ̀ Ẹ̀kọ́
Ilé Ẹjọ́ àti Ọ̀ràn Òfin
À Ń Gbèjà Ìhìn Rere Níwájú Àwọn Aláṣẹ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 9/2016
Àwọn Akéde Ìjọba Ọlọ́run Gbé Ọ̀rọ̀ Lọ Sílé Ẹjọ́ Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 13
Bí A Ṣe Jà fún Òmìnira Láti Lè Máa Sin Jèhófà Láìsí Ìdíwọ́ Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 15
Ilé Ẹjọ́ Ilẹ̀ Yúróòpù Gbèjà Ẹ̀tọ́ Ẹni Tí Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ̀ Kò Jẹ́ Kó Ṣiṣẹ́ Ológun Ilé Ìṣọ́, 11/1/2012
Ilé Ẹjọ́ Dá Àwọn Èèyàn Jèhófà Láre! Ilé Ìṣọ́, 7/15/2011
“Ẹ Gbọ́ Ìgbèjà Mi” Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, orí 23
“Jẹ́ Onígboyà Gidi Gan-an!” Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, orí 24
“Mo Ké Gbàjarè sí Késárì!” Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, orí 25
Ilé Ẹjọ́ Gbèjà Àwọn Tí Wọ́n Hùwà Ìkà Sí Ilé Ìṣọ́, 3/1/2008
Ilé Ẹjọ́ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn Ti Ilẹ̀ Yúróòpù Dá Wọn Láre Ilé Ìṣọ́, 5/15/2007
Ilé Ẹjọ́ Ilẹ̀ Yúróòpù Fún Ìyá Kan Lẹ́tọ̀ọ́ Ẹ̀ Jí!, 12/8/2004
Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ Fọwọ́ sí Òmìnira Ọ̀rọ̀ Sísọ Jí!, 1/8/2003
Ìmúrasílẹ̀ àti Ìrànwọ́ Nígbà Àjálù
Tún wo Àjálù lábẹ́ Ètò Àwọn Nǹkan Sátánì lábẹ́ Ọ̀ràn Tó Jẹ Mọ́ Àyíká
Ìmúrasílẹ̀
Tí Àjálù Bá Ṣẹlẹ̀—Ohun Tó O Lè Ṣe Láti Gbẹ̀mí Là Jí!, No. 5 2017
Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀ De Àjálù? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 8/2012
Ṣíṣèrànwọ́
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tá A Fi Ń Ṣe Ìrànwọ́ Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 20
Báwo La Ṣe Ń Ṣèrànwọ́ fún Àwọn Ará Wa Tí Àjálù Bá? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 18
Ọ̀nà Wo La Lè Gbà Ṣèrànwọ́? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2005
Ọrẹ Tí Inú Ọlọ́run Ń Dùn Sí (§ Ìrànlọ́wọ́ Tá A Ṣètò Wá Ńkọ́?) Ilé Ìṣọ́, 6/1/2003
Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú Ilé Ìṣọ́, 5/1/2003
Ìfẹ́ Fara Hàn Gbangba Níbi Iṣẹ́ Àfiṣèrànwọ́ Kan Tó Fa Kíki Jí!, 12/8/2002
Ẹgbẹ́ Tó Ń Bìkítà fún Ara Wọn Kárí Ayé Ilé Ìṣọ́, 4/15/2001
Ìròyìn àti Ìrírí
“Irú Ìfẹ́ Yìí Wú Wa Lórí Gan-an Ni” Jí!, No. 1 2017
Àwọn Tí Ìjì Òjò Ṣàkóbá fún Lórílẹ̀-Èdè Myanmar Rí Ìrànlọ́wọ́ Gbà Ilé Ìṣọ́, 3/1/2009
Àjálù Ṣẹlẹ̀ ní Erékùṣù Solomon Islands Ilé Ìṣọ́, 5/1/2008
Ohun Kan Tí Ìjì Kò Lè Gbé Lọ Jí!, 8/8/2003
Kíkojú Àbájáde Rẹ̀ Jí!, 4/8/2002
Lẹ́yìn Ìjì Tó Jà—Ìpèsè Ìrànwọ́ ní Ilẹ̀ Faransé Jí!, 7/8/2000
Ọrẹ àti Ọ̀nà Tá A Gbà Ń Lo Owó
A Ó Bù Kún Ẹni Tí Ó Jẹ́ Ọ̀làwọ́ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 11/2017
Bá A Ṣe Lè Ní Ọrọ̀ Tòótọ́ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 7/2017
“Iṣẹ́ Náà Pọ̀” Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 11/2016
Mọrírì Ìwà Ọ̀làwọ́ Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 11/15/2015
Kí La Lè Rí Kọ́ Látinú Àpẹẹrẹ Jòánà? Ilé Ìṣọ́, 8/15/2015
Bí A Ṣe Ń Ti Iṣẹ́ Ìwàásù Lẹ́yìn Láwọn Ìjọ Kọ̀ọ̀kan àti Kárí Ayé A Ṣètò Wa, orí 12
Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Ní Ẹ̀mí Ìmúratán Ilé Ìṣọ́, 12/15/2014
Bí A Ṣe Ń Rí Owó Bójú Tó Iṣẹ́ Ìjọba Ọlọ́run Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 18
Bá A Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ fún Àwọn Èèyàn Ilé Ìṣọ́, 11/15/2013
Àṣẹ́kùsílẹ̀ Wọn Dí Àìnító Kan Ilé Ìṣọ́, 11/15/2012
Báwo La Ṣe Ń Rí Owó fún Iṣẹ́ Wa Kárí Ayé? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 24
Ǹjẹ́ O Máa Ń Rí Ayọ̀ Nínú “Àǹfààní Ìfúnni Onínúrere”? Ilé Ìṣọ́, 11/15/2011
Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé: Èló Ni Kí N Fi Ṣètọrẹ fún Iṣẹ́ Ọlọ́run? Ilé Ìṣọ́, 8/1/2009
Máa Lo Àwọn Ìtẹ̀jáde Wa Lọ́nà Tó Dáa Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2009
“Tèmi Ni Fàdákà, Tèmi sì Ni Wúrà” Ilé Ìṣọ́, 11/1/2007
Àwọn Ọrẹ Tó Ń Mú Inú Ọlọ́run Dùn Ilé Ìṣọ́, 11/1/2005
Pọ́ọ̀lù Ṣètò Ọrẹ Àfiṣèrànwọ́ Fáwọn Ẹni Mímọ́ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2001
Ìtẹ̀jáde Tá A Kà Sórí Ẹ̀rọ àti Fídíò
Bí A Ṣe Lè Lo Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Gbohùn Wọn Sílẹ̀ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2015
Látinú Àpamọ́ Wa: Sinimá Tó Dá Lórí Ìṣẹ̀dá Ti Pé Ọgọ́rùn-ún Ọdún Báyìí! Ilé Ìṣọ́, 2/15/2014
Ìkànnì jw.org
Ìkànnì àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ni www.jw.org/yo. Oríṣiríṣi nǹkan tó lè ràn wá lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bí Kristẹni, tó máa jẹ́ ká lè ṣe iṣẹ́ wa nínú ìjọ àti lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù ló wà níbẹ̀. Díẹ̀ lára wọn nǹkan tó wà níbẹ̀ ni àwọn àpilẹ̀kọ, àwọn iṣẹ́ ìkẹ́kọ̀ọ́, orin àti àwọn fídíò. O tún lè kà tàbí kó o wa àwọn ìtẹ̀jáde tó wà lórí ìkànnì yìí jáde.
Tẹlifíṣọ̀n orí Íńtánẹ́ẹ̀tì ni JW Broadcasting, ó wà lórí ìkànnì tv.jw.org. O lè wo àwọn ètò olóṣooṣù tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́, àwọn fídíò, orin, àwọn ohun pàtàkì tó ṣẹlẹ̀ àti àwọn ètò tó ń lọ lọ́wọ́ láti orí kọ̀ǹpútà, fóònù tàbí tablet. O lè wò ó tọ̀sántòru.
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower wà lórí ìkànnì wol.jw.org. Àwọn ìtẹ̀jáde wa tó wà ní èdè tó ju ọgọ́rùn-ún márùn-ún [500] lọ ló wà níbẹ̀.