ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • rsg19
  • Ìdílé

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìdílé
  • Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—Ẹ̀dà Ti Ọdún—2019
  • Ìsọ̀rí
  • Àpọ́n, Àìlọ́kọ Tàbí Aya
  • Fífẹ́ra àti Ìfẹ́sọ́nà
  • Ìgbéyàwó àti Àpèjẹ Ìgbéyàwó
  • Ìgbéyàwó
  • Ìfètòsọ́mọbíbí
  • Àwọn Òbí àti Àwọn Ọmọ
  • Ọ̀dọ́
  • Àwọn Òbí Tó Ti Dàgbà àti Àwọn Òbí Àgbà
  • Ìdílé Tí Wọ́n Ti Ń Ṣe Ẹ̀sìn Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀
  • Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ àti Òbí Anìkàntọ́mọ
  • Bí Ìdílé Ṣe Lè Lágbára
  • Àwọn Ìṣòro Ìdílé àti Ojútùú
  • Ìjọsìn Ìdílé
Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—Ẹ̀dà Ti Ọdún—2019
rsg19

Ìdílé

Tún wo ìkànnì wa:

www.jw.org/yo

Tún wo ìwé:

Ayọ̀ Ìdílé

Ohun Tó O Lè Ṣe Kí Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀ Bíbélì Fi Kọ́ni, orí 14

Ìbéèrè 17: Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ran Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́? Ohun Tó Wà Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Láyọ̀? Ìròyìn Ayọ̀, ẹ̀kọ́ 9

Ohun Tó Yẹ Kó O Ṣe Kó O Lè Ní Ìdílé Tó Ń Múnú Ọlọ́run Dùn Ọjọ́ Jèhófà, orí 10

Àpọ́n, Àìlọ́kọ Tàbí Aya

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ṣé àwọn tó yàn láti má ṣe ní ọkọ tàbí aya gba ẹ̀bùn yìí lọ́nà ìyanu ni? (Mát. 19:10-12) Ilé Ìṣọ́, 11/15/2012

Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé: Ṣé Ó Dìgbà Téèyàn Bá Lọ́kọ Tàbí Téèyàn Bá Láya Kó Tó Lè Láyọ̀? Ilé Ìṣọ́, 10/1/2012

Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Fáwọn Tí Kò Ṣègbéyàwó Àtàwọn Tó Ṣègbéyàwó Ilé Ìṣọ́, 10/15/2011

Lo Ẹ̀bùn Wíwà Láìní Ọkọ Tàbí Aya Lọ́nà Tó Dára Jù Lọ Ilé Ìṣọ́, 1/15/2011

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jeremáyà Kó O Lè “Máa Wà Láàyè Nìṣó Jeremáyà, orí 8

Bó O Ṣe Lè Láyọ̀ Láìlọ́kọ Tàbí Aya Ilé Ìṣọ́, 6/15/2009

Ìgbéyàwó àti Ọmọ Bíbí Lákòókò Òpin Yìí (§ Wíwà Láìlọ́kọ, Láìláya Tàbí Láìbímọ fún Ìdí Rere) Ilé Ìṣọ́, 4/15/2008

‘Ẹ Pa Agbára Ìmòye Yín Mọ́ Délẹ̀délẹ̀’ (§ Ìṣòro Tó Dojú Kọ Àwọn Kristẹni Tí Kò Tí ì Ṣègbéyàwó) Ilé Ìṣọ́, 3/1/2006

“Ọ̀dọ̀ Jèhófà Ni Ìrànlọ́wọ́ Mi Ti Wá”: Wọn Ò Lọ́kọ Wọn Ò Láya àmọ́ Ọkàn Wọn Balẹ̀ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 7/15/2005

Àwọn Obìnrin Kristẹni Olóòótọ́ Jẹ́ Ẹni Ọ̀wọ́n Tó Ń Sin Ọlọ́run (§ Àwọn Obìnrin Tí Kò Lọ́kọ, Síbẹ̀ Tí Wọ́n Jẹ́ Ẹni Ọ̀wọ́n) Ilé Ìṣọ́, 11/1/2003

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ṣé gbogbo ìgbà la gbọ́dọ̀ san ẹ̀jẹ́ tá a bá jẹ́ fún Ọlọ́run? Ilé Ìṣọ́, 11/15/2002

Ṣé Ò Ń Dámọ̀ràn Ara Rẹ Fáwọn Ẹlòmíràn? (§ Gẹ́gẹ́ Bí Ọkọ Tàbí Aya Rere Lọ́la) Ilé Ìṣọ́, 4/15/2000

Fífẹ́ra àti Ìfẹ́sọ́nà

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́? Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 12/2017

Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ń Fẹ́ra Wọn

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Ṣé Ọ̀rẹ́ Lásán La Jẹ́ àbí Ọ̀rọ̀ Ìfẹ́ Ti Ń Wọ̀ Ọ́? Apá 1 Jí!, 7/2012

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Ṣé Ọ̀rẹ́ Lásán La Jẹ́ àbí Ọ̀rọ̀ Ìfẹ́ Ti Ń Wọ̀ Ọ́?, Apá Kejì Jí!, 10/2012

Kí Nìdí Táwọn Ọkùnrin Kì Í Fi Í Gba Tèmi? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 27

Kí Nìdí Táwọn Obìnrin Kì Í Fi Í Gba Tèmi? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 28

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Táwọn Ọkùnrin Kì Í Fi Í Gba Tèmi? Jí!, 4/2010

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Táwọn Obìnrin Kì Í Fi Í Gba Tèmi? Jí!, 7/2009

Ṣó Ti Yẹ Kí N Lẹ́ni Tí Mò Ń Fẹ́? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 1

Kí Ló Burú Nínú Fífẹ́ra Sọ́nà Ní Bòókẹ́lẹ́? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 2

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ló Burú Nínú Bíbára Ẹni Jáde Ní Bòókẹ́lẹ́? Jí!, 7/2007

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Ìgbà Wo Ló Yẹ Kí N Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Bá Ẹni Tí Kì Í Ṣe Ọkùnrin Tàbí Obìnrin Bíi Tèmi Jáde? Jí!, 1/2007

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe Bí Ọ̀dọ́bìnrin Kan Bá Dẹnu Ìfẹ́ Kọ Mí? Jí!, 7/8/2005

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Bó Bá Lóun Ò Lè Fẹ́ Mi Ńkọ́? Jí!, 1/8/2005

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Ewu Wo Ló Wà Nínú Kí Àwọn Èwe Máa Dájọ́ Àjọròde? Jí!, 1/8/2002

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Bí Àwọn Òbí Mi Bá Sọ Pé Mi Ò Tí ì Tẹ́ni Tó Ń Dájọ́ Àjọròde Ńkọ́? Jí!, 2/8/2001

Ẹni Tó Ń Wá Ọkọ Tàbí Aya

Tẹ́ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: “Mo Múra Tán Láti Lọ” Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 3 2016

Ṣọ́ Àwọn Tó Ò Ń Bá Kẹ́gbẹ́ ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn Yìí Ilé Ìṣọ́, 8/15/2015

Gbéyàwó “Kìkì Nínú Olúwa”​—⁠Ǹjẹ́ Ó Ṣì Bọ́gbọ́n Mu? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2015

Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé: Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Pàṣẹ fún Àwọn Olùjọsìn Rẹ̀ Láti Fẹ́ Kìkì Àwọn Tí Wọ́n Jọ Ń Jọ́sìn Òun? Ilé Ìṣọ́, 7/1/2012

Ṣé Òótọ́ Lo Mọrírì Ìgbéyàwó Tó Jẹ́ Ẹ̀bùn Ọlọ́run? (§ Yíyàn Tá A Bá Ṣe Kan Ọlọ́run) Ilé Ìṣọ́, 5/15/2012

Ṣé Ẹni Tó Yẹ Kí N Fẹ́ Nìyí? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 3

Ìgbéyàwó Jẹ́ Ẹ̀bùn Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run Tó Nífẹ̀ẹ́ Wa (§ Bó O Ṣe Lè Mọ Ẹni Tó Yẹ Kó O Fẹ́?) ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 10

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Ṣé Ẹni Tó Yẹ Kí N Fẹ́ Nìyí? Jí!, 7/2007

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Ṣé Bẹ́ẹ̀ Ni Ewu Pọ̀ Tó Nínú Fífẹ́ra Sọ́nà Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì? Jí!, 6/8/2005

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: “Ṣé Mo Lè Rẹ́ni Fẹ́ Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì?” Jí!, 5/8/2005

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Sọ Ohun Tó Wà Lọ́kàn Mi Fún Un? Jí!, 11/8/2004

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Àwọn wo ni Pọ́ọ̀lù ń tọ́ka sí nígbà tó lo ọ̀rọ̀ náà “aláìgbàgbọ́” nínú 2 Kọ́ríńtì 6:14? Ilé Ìṣọ́, 7/1/2004

Ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run Lórí Ọ̀ràn Yíyan Ẹni Tí A Óò Fẹ́ Ilé Ìṣọ́, 5/15/2001

Mímúra Sílẹ̀ fún Ìgbéyàwó Aláṣeyọrí Ayọ̀ Ìdílé, orí 2

Ìfẹ́sọ́nà

Ǹjẹ́ Ìfẹ́ Àárín Tọkọtaya Lè Wà Pẹ́ Títí? Ilé Ìṣọ́, 1/15/2015

Báwo Ni Mo Ṣe Máa Mọ̀ Bóyá Ìfẹ́ Tòótọ́ Ni? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 29

Ǹjẹ́ A Ti Ṣe Tán Láti Ṣègbéyàwó Báyìí? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 30

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ẹ Má Fi Ìfẹ́sọ́nà Ṣeré Jí!, 4/2010

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣó Dáa Kí Ọkùnrin àti Obìnrin Máa Gbé Pọ̀ Kí Wọ́n Tó Ṣègbéyàwó? Jí!, 1/2010

Ìgbéyàwó Jẹ́ Ẹ̀bùn Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run Tó Nífẹ̀ẹ́ Wa (§ Báwo Lo Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìgbéyàwó Tó Máa Yọrí Sí Rere?) ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 10

Mímúra Sílẹ̀ fún Ìgbéyàwó Aláṣeyọrí (§ Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́sọ́nà Yín Lọ́lá) Ayọ̀ Ìdílé, orí 2

Àwọn Ìṣòro

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí Ìwọ àti Àfẹ́sọ́nà Rẹ Bá Fi Ara Yín Sílẹ̀ Jí!, 9/2015

Báwo Ni Màá Ṣe Borí Ẹ̀dùn Ọkàn Mi Bí Àfẹ́sọ́nà Mi Bá Já Mi Sílẹ̀? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 31

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Fara Dà Á Bí Ẹni Tí Mò Ń Fẹ́ Bá Fi Mí Sílẹ̀? Jí!, 4/2009

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Ṣé Kémi Àtẹni Tá A Jọ Ń Fẹ́ra Fira Wa Sílẹ̀? Jí!, 1/2009

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ni Mo Lè Ṣe Láti Mú Kí Ọ̀rẹ́kùnrin Mi Dẹ́kun Fíf ìyà Jẹ Mí? Jí!, 7/8/2004

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ló Fà Á Tó Fi Ń Hu Irú Ìwà Yìí sí Mi? Jí!, 6/8/2004

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Màá Ṣe Sọ Fún Un Pé Mi Ò Ṣe? Jí!, 4/8/2001

Ìgbéyàwó àti Àpèjẹ Ìgbéyàwó

Àpótí Ìbéèrè: Báwo ni tọkọtaya tó fẹ́ lo Gbọ̀ngàn Ìjọba fún ìgbéyàwó wọn ṣe lè béèrè fún un? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2008

Àwọn Ayẹyẹ Tí Inú Ọlọ́run Ò Dùn Sí (§ Má Ṣe Sọ Ayẹyẹ Ìgbéyàwó Rẹ Di Ẹlẹ́gbin) ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 13

❐ Ilé Ìṣọ́, 10/15/2006

Ìgbéyàwó Tó Ní Ọlá Lójú Ọlọ́run àti Èèyàn

Jẹ́ Kí Ọ̀nà Tí O Gbà Ń Gbé Ìgbésí Ayé Rẹ Fi Hàn Pé O Ní Ìgbàgbọ́

Ṣe Ohun Tó Máa Jẹ́ Kí Ayọ̀ àti Iyì Ọjọ́ Ìgbéyàwó Rẹ Pọ̀ Sí I

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Ṣé Dandan Ni Ká Ṣègbéyàwó Níṣulọ́kà? Jí!, 12/8/2005

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Àwọn ìlànà Ìwé Mímọ́ wo ló kan fífúnni ní ẹ̀bùn tàbí gbígba ẹ̀bùn nígbà ìgbéyàwó? Ilé Ìṣọ́, 9/1/2003

❐ Jí!, 2/8/2002

“Ọjọ́ Tó Dùn Jù Lọ Nínú Ìgbésí Ayé Wa”

Ọjọ́ Ìgbéyàwó​—⁠Ọjọ́ Olóyinmọmọ Ni àmọ́ Ó Tún Ní Wàhálà Tiẹ̀

Àwọn Ìgbéyàwó Aláyọ̀ Tí Ń Bọlá fún Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 5/1/2000

Lílọ Síbi Ìgbéyàwó Ẹlòmí ì

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ǹjẹ́ ó yẹ ká lọ síbi ìgbéyàwó ẹni tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí? Ilé Ìṣọ́, 11/15/2007

Bó O Ṣe Lè Máa Ṣe Ohun Tí Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ Ń Sọ Ilé Ìṣọ́, 10/15/2007 ¶10 sí 15

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ǹjẹ́ ó bọ́gbọ́n mu ká lọ síbi ètò ìsìnkú tàbí ìgbéyàwó nínú ṣọ́ọ̀ṣì? Ilé Ìṣọ́, 5/15/2002

Ìgbéyàwó

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́? Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 12/2017

❐ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 8/2016

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Ṣètò Ìgbéyàwó?

Ohun Táá Jẹ́ Kí Tọkọtaya Bára Wọn Kalẹ́

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Fi Ọ̀wọ̀ Hàn Jí!, No. 6 2016

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí Ìfẹ́ Yín Ṣe Lè Jinlẹ̀ Sí I Jí!, 7/2015

❐ Ilé Ìṣọ́, 1/15/2015

Bí Tọkọtaya Ṣe Lè Ṣera Wọn Lọ́kan Kí Wọ́n sì Láyọ̀

Jẹ́ Kí Jèhófà Dáàbò Bo Ìgbéyàwó Rẹ Kó sì Fún Un Lókun

Ǹjẹ́ Ìfẹ́ Àárín Tọkọtaya Lè Wà Pẹ́ Títí?

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí Ìgbéyàwó Rẹ Kò Bá Rí Bó O Ṣe Rò Jí!, 5/2014

Ẹ Jẹ́ Kí Ọlọ́run Ràn Yín Lọ́wọ́ Kí Ẹ Lè Jẹ́ Tọkọtaya Aláyọ̀ Ìdílé Aláyọ̀, apá 1

Ẹ Jẹ́ Olóòótọ́ sí Ara Yín Ìdílé Aláyọ̀, apá 2

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bí Àwọn Tó Tún Ìgbéyàwó Ṣe Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí Ilé Ìṣọ́, 7/1/2013

Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé: Ṣé Ó Dìgbà Téèyàn Bá Lọ́kọ Tàbí Téèyàn Bá Láya Kó Tó Lè Láyọ̀? Ilé Ìṣọ́, 10/1/2012

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ni Mo Lè Máa Retí Tá A Bá Di Tọkọtaya?​—⁠Apá Kìíní Jí!, 10/2012

Ṣé Òótọ́ Lo Mọrírì Ìgbéyàwó Tó Jẹ́ Ẹ̀bùn Ọlọ́run? Ilé Ìṣọ́, 5/15/2012

Ojú Ìwòye Bíbélì: Bí Ìgbéyàwó Ṣe Lè Wà Pẹ́ Títí Jí!, 1/2012

Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Fáwọn Tí Kò Ṣègbéyàwó Àtàwọn Tó Ṣègbéyàwó Ilé Ìṣọ́, 10/15/2011

Bọ̀wọ̀ fún Ìgbéyàwó Tó Jẹ́ Ẹ̀bùn Ọlọ́run Ilé Ìṣọ́, 1/15/2011

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bí O Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí Nínú Ọdún Àkọ́kọ́ Ìgbéyàwó Ilé Ìṣọ́, 8/1/2010

Ojú Ìwòye Bíbélì: Kí Ló Túmọ̀ Sí Pé Kí Ọkọ Tàbí Aya Má Dalẹ̀ Ara Wọn? Jí!, 4/2009

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bí Tọkọtaya Ṣe Lè Máa Ṣera Wọn Lọ́kan Ilé Ìṣọ́, 11/1/2008

Máa Jẹ́ Kí Ìgbéyàwó Rẹ Jẹ́ “Okùn Onífọ́nrán Mẹ́ta” Ilé Ìṣọ́, 9/15/2008

❐ Jí!, 7/2008

Wàhálà Ti Bá Ìgbéyàwó

Ìṣòro Tó Lè Wáyé?

Bí Ìgbéyàwó Ṣe Lè Kẹ́sẹ Járí

Jẹ́ Kí Ayọ̀ Wà Nínú Ilé Rẹ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2008

Ìgbéyàwó Jẹ́ Ẹ̀bùn Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run Tó Nífẹ̀ẹ́ Wa ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 10

Má Ṣe Ya Ohun Tí Ọlọ́run Ti So Pọ̀ Ilé Ìṣọ́, 5/1/2007

“Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Aya Ìgbà Èwe Rẹ” Ilé Ìṣọ́, 9/15/2006

❐ Jí!, 7/2006

Ṣé Ìjì Tó Ń Jà Yìí Ò Ní Í Gbé Ìgbéyàwó Lọ?

Béèyàn Ṣe Lè Láyọ̀ Nínú Ìgbéyàwó

❐ Ilé Ìṣọ́, 3/1/2005

Bí Tọkọtaya Ṣe Lè Láyọ̀ Lóde Òní

Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n fún Àwọn Tọkọtaya

Ojú Ìwòye Bíbélì: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ka Ìgbéyàwó Sí Ohun Mímọ́? Jí!, 5/8/2004

❐ Ilé Ìṣọ́, 9/15/2003

Bíbélì Lè Ràn Ọ́ Lọ́wọ́ Nínú Ìgbéyàwó Rẹ

Bó O Ṣe Lè Mú Kí Ìdè Ìgbéyàwó Rẹ Lágbára Sí I

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ṣé bí Ọlọ́run ṣe fàyè gba ìkóbìnrinjọ ní ìgbàanì wá túmọ̀ sí pé àwọn ìlànà rẹ̀ máa ń yí pa dà? Ilé Ìṣọ́, 8/1/2003

Ìdè Tó Yẹ Kó Wà Pẹ́ Títí Ni Ìgbéyàwó Jí!, 2/8/2002

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ǹjẹ́ ìkàléèwọ̀ tó wà nínú Òfin Mósè pé kéèyàn má ṣègbéyàwó pẹ̀lú ìbátan rẹ̀ kàn wá lóde òní? Ilé Ìṣọ́, 2/1/2002

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣé Ó Yẹ Kí Ìgbéyàwó Wà Pẹ́ Títí? Jí!, 2/8/2001

❐ Jí!, 1/8/2001

Híhá Sínú Ìgbéyàwó Aláìnífẹ̀ẹ́

Èé Ṣe Tí Ìfẹ́ Fi Ń Pòórá?

Ǹjẹ́ Ìrètí Ńbẹ?

Ó Ṣeé Ṣe Kí Ìgbéyàwó Yín Má Forí Ṣánpọ́n O!

Kọ́kọ́rọ́ Méjì sí Ìgbéyàwó Wíwà Pẹ́ Títí Ayọ̀ Ìdílé, orí 3

Dídàgbà Pọ̀ Ayọ̀ Ìdílé, orí 14

Ọkọ

Ẹ̀yin Ọkọ​—⁠Ẹ Mú Kí Ilé Yín Tura Ilé Ìṣọ́, 1/1/2015

Ẹ̀yin Ọkùnrin, Ṣé Ẹ̀ Ń Tẹrí Ba fún Ipò Orí Kristi? Ilé Ìṣọ́, 5/15/2010

Ẹ̀yin Ọkọ, Ẹ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìfẹ́ Kristi! Ilé Ìṣọ́, 5/15/2009

Ẹ̀yin Ọkọ, Ẹ Mọ Kristi Ní Orí Yín Ilé Ìṣọ́, 2/15/2007

Aya

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: Ọlọ́run Pè É Ní “Ìyá Ọba” Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 5 2017

‘Ẹni Mímọ̀ Ni Ọkọ Rẹ̀ Jẹ́ Ní Àwọn Ẹnubodè’ Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 11/2016

Ẹ̀yin Obìnrin, Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kẹ́ Ẹ Máa Tẹrí Ba fún Ipò Orí? Ilé Ìṣọ́, 5/15/2010

Ẹ̀yin Aya, Ẹ Ní Ọ̀wọ̀ Jíjinlẹ̀ fún Ọkọ Yín Ilé Ìṣọ́, 2/15/2007

Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Látọ̀dọ̀ Ìyá Kan Ilé Ìṣọ́, 2/1/2000

Ipò Orí àti Ìtẹríba

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ọ̀nà Wo Ni Ọkọ Gbà Jẹ́ Orí Aya? Jí!, 1/2008

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Bọ̀wọ̀ Fáwọn Aláṣẹ? (§ Bá A Ṣe Lè Fọ̀wọ̀ Hàn Nínú Ìdílé) ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 4

Ọkùnrin àti Obìnrin​—⁠Ipò Iyì Ni Ọlọ́run Fi Kálukú Wọn Sí Ilé Ìṣọ́, 1/15/2007

Ojú Ìwòye Bíbélì: Kí Ni Jíjẹ́ Olórí Ìdílé Túmọ̀ Sí? Jí!, 7/8/2004

Ṣé Lóòótọ́ Lo Gbà Pé Kristi Ni Aṣáájú Wa? (§ “Ẹ Wà Ní Ìtẹríba fún Ara Yín”) Ilé Ìṣọ́, 3/15/2002

“Ẹ Di Aláfarawé Ọlọ́run” Nípa Bí Ẹ Ṣe Ń Lo Agbára (§ Nínú Ìdílé) Sún Mọ́ Jèhófà, orí 10

Wá Ọjọ́ Ọ̀la Wíwà Pẹ́ Títí fún Ìdílé Rẹ (§ Ojú Ìwòye Tí Ó Tọ́ Nípa Ipò Orí) Ayọ̀ Ìdílé, orí 16

Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Nígbà Tí Àwọn Ọmọ Bá Ti Kúrò Nílé Jí!, No. 4 2017

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Mọyì Ẹnì Kejì Rẹ Jí!, No. 1 2017

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Yanjú Ọ̀rọ̀ Jí!, No. 3 2016

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí Ẹ Ṣe Lè Gbà Fún Ara Yín Jí!, 1/2015

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí O Ṣe Lè Máa Fetí Sílẹ̀ Dáadáa Jí!, 1/2014

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí Ẹ Ṣe Lè Máa Dárí Ji Ara Yín Jí!, 11/2013

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Bíbá Ara Yín Yan Odì Jí!, 7/2013

Ẹ Máa Bá Ara Yín Sọ̀rọ̀ Kẹ́ ẹ Lè Túbọ̀ Ṣera Yín Lọ́kan Ilé Ìṣọ́, 5/15/2013

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí Ẹ Ṣe Lè Yẹra Fún Sísọ Ọ̀rọ̀ Líle sí Ara Yín Jí!, 5/2013

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí Ẹ Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Bíbá Ara Yín Jiyàn Jí!, 3/2013

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Máa Bọ̀wọ̀ fún Ọkọ Tàbí Aya Rẹ Ilé Ìṣọ́, 8/1/2011

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bá A Ṣe Lè Yanjú Ìṣòro Tó Bá Jẹ Yọ Ilé Ìṣọ́, 5/1/2008

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bá A Ṣe Lè Yanjú Èdèkòyédè Ilé Ìṣọ́, 2/1/2008

“Ẹ Jẹ́ Kí Ìgbéyàwó Ní Ọlá” (§ Má Ṣe Hùwà, Má sì Ṣe Sọ̀rọ̀ Tó Ń Tàbùkù sí Ìgbéyàwó) ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 11

Nígbà Tí Nǹkan Ò Bá Rí Bó O Ṣe Rò Ilé Ìṣọ́, 4/15/2007

❐ Ilé Ìṣọ́, 4/15/2006

Ẹ̀yin Tọkọtaya Ǹjẹ́ Ẹ Máa Ń Jùmọ̀ Sọ̀rọ̀ Dáadáa?

Àwọn Ohun Tó Lè Mú Kí Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀ Máa Lọ Déédéé Láàárín Tọkọtaya

Tí Èdèkòyédè Bá Wáyé Láàárín Tọkọtaya Ilé Ìṣọ́, 6/1/2005

Ìbálòpọ̀

Ohun Táá Jẹ́ Kí Tọkọtaya Bára Wọn Kalẹ́ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 8/2016

Jẹ́ Kí Jèhófà Dáàbò Bo Ìgbéyàwó Rẹ Kó sì Fún Un Lókun Ilé Ìṣọ́, 1/15/2015

Bíbélì Dáhùn Ìbéèrè Mẹ́wàá Nípa Ìbálòpọ̀ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2011

Jẹ́ Kí Ayọ̀ Wà Nínú Ilé Rẹ (§ Ẹ Má Máa Rin Kinkin Mọ́ Ohun Tẹ́nì Kọ̀ọ̀kan Yín Ń Fẹ́) Ilé Ìṣọ́, 3/15/2008

Ẹ Fi Ìkóra-ẹni-níjàánu Kún Ìmọ̀ Yín (§ Ìkóra-Ẹni-Níjàánu Nínú Ìgbéyàwó) Ilé Ìṣọ́, 10/15/2003

Bí Ìgbéyàwó Bá Wà ní Bèbè Àtitúká (§ Fífi Ẹ̀tọ́ Ìgbéyàwó Fúnni) Ayọ̀ Ìdílé, orí 13

Mọ̀lẹ́bí àti Àna

Tún wo Ọmọ Tó Ti Dàgbà lábẹ́ Ìdílé lábẹ́ Àwọn Òbí àti Àwọn Ọmọ

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Ní Àjọṣe Tó Dáa Pẹ̀lú Àwọn Àna Rẹ Jí!, 5/2015

Bí Ẹ Ṣe Lè Jẹ́ Kí Àlàáfíà Jọba Láàárín Ẹ̀yin Àtàwọn Mọ̀lẹ́bí Yín Ìdílé Aláyọ̀, apá 5

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bó O Ṣe Lè Yanjú Ìṣòro Àárín Ìwọ àti Àna Rẹ Ilé Ìṣọ́, 2/1/2010

Jẹ́ Kí Ayọ̀ Wà Nínú Ilé Rẹ (§ Kí Ló Ń Mú Kí Ìgbéyàwó Yọrí sí Rere?) Ilé Ìṣọ́, 3/15/2008

Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Wàásù fún Àwọn Mọ̀lẹ́bí Wa? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 12/2004

Ojú Ìwòye Bíbélì: Bí Ẹ̀sìn Rẹ àti Tàwọn Ìbátan Rẹ Ò Bá Dọ́gba Jí!, 11/8/2003

Ìfètòsọ́mọbíbí

Tún wo Oyún, Ọmọ Bíbí àti Ìtọ́jú Ìkókó lábẹ́ Ìlera Ara àti Ọpọlọ

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ǹjẹ́ àwọn tọkọtaya Kristẹni lè lo ìfètòsọ́mọbíbí kan tí wọ́n ń pè ní IUD (ìyẹn intrauterine device)? Ǹjẹ́ ó bá ìlànà Ìwé Mímọ́ Mu? Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 12/2017

Jèhófà Bù Kún Mi Gan-an Torí Pé Mo Ṣègbọràn Sí I (§ Ohun Àìròtẹ́lẹ̀ Kan Ṣẹlẹ̀) Ilé Ìṣọ́, 6/15/2013

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Kí ni ká ti ṣe ọlẹ̀ tó kù tí wọ́n kò lò tán tí wọ́n tọ́jú sínú yìnyín? Ilé Ìṣọ́, 12/15/2012

Ohun Tí Àwọn Òbí Sọ (Àpótí: A Lóyún Láìròtẹ́lẹ̀ Àyípadà Tá A Ṣe) Jí!, 10/2011

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣó Dáa Kéèyàn Máa Lo Oògùn Máàjóyúndúró? Jí!, 1/2008

Àwọn Òbí àti Àwọn Ọmọ

Ẹ̀yin Òbí Àtẹ̀yin Ọmọ, Ẹ Máa Fìfẹ́ Bá Ara Yín Sọ̀rọ̀ Ilé Ìṣọ́, 5/15/2013

❐ Jí!, 10/2011

“Ohun Àgbàyanu Tó Ń Yára Kẹ́kọ̀ọ́ Jù Lọ Lágbàáyé”

Ohun Tí Àwọn Òbí Sọ (Ìgbà Kékeré)

Bó O Ṣe Lè Tọ́ Ọmọ Láti Ìgbà Ọmọdé Títí Dìgbà Ìbàlágà

Ohun Tí Àwọn Òbí Sọ (Ìgbà Ọmọdé)

Bí Àwọn Òbí Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ fún Àwọn Ọmọ Wọn Tó Ti Bàlágà

Ohun Tí Àwọn Òbí Sọ (Ìgbà Ìbàlágà)

Ojú Ìwòye Bíbélì: Kí Ló Yẹ Kó Jẹ́ Àfojúsùn Àwọn Òbí?

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Irú Èèyàn Wo Gan-an Ni Mo Jẹ́?

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Ipa Tí Ọmọ Lè Ní Lórí Àjọṣe Ọkọ àti Aya Ilé Ìṣọ́, 5/1/2011

Ìgbéyàwó àti Ọmọ Bíbí Lákòókò Òpin Yìí Ilé Ìṣọ́, 4/15/2008

❐ Jí!, 10/2007

Wá Ìmọ̀ràn Tó Dáa Gbà

Jẹ́ Kí Ilé Rẹ Jẹ́ Ilé Aláyọ̀

Lo Àṣẹ Rẹ Gẹ́gẹ́ Bí Òbí

Jẹ́ Kí Ìlànà Wà Tí Ìdílé Gbọ́dọ̀ Máa Tẹ̀ Lé

Jẹ́ Kí Olúkúlùkù Mọ Iṣẹ́ Táá Máa Ṣe Nínú Ilé

Máa Gbọ́ Àwọn Ọmọ Ẹ Lágbọ̀ọ́yé

Jẹ́ Káwọn Ọmọ Rí Ẹ̀kọ́ Kọ́ Lára Ẹ

Ṣé Ìdádọ̀dọ́ La Fi Ń Mọ̀ Pé Èèyàn Ti Di Ọkùnrin? Ilé Ìṣọ́, 6/1/2007

Ẹ̀yin Òbí Ẹ Jẹ́ Àpẹẹrẹ Rere Fáwọn Ọmọ Yín Ilé Ìṣọ́, 4/1/2006

Ojúṣe Rẹ Gẹ́gẹ́ bí Òbí Jí!, 11/8/2004

Ìgbọràn Ń Dáàbò Bò Ọ́ Olùkọ́, orí 7

Kíkẹ́ Lọmọ Jí!, 12/8/2000

Bàbá

Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Bàbá Rere Jí!, 5/2013

Ó Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ̀, Ó Pèsè fún Wọn, Ó sì Ní Ìfaradà Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ, orí 19

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: Ó Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ̀, Ó Pèsè fún Wọn, Ó sì Lo Ìfaradà Ilé Ìṣọ́, 4/1/2012

Kí Làwọn Bàbá Lè Ṣe Tí Àjọṣe Wọn Pẹ̀lú Ọmọkùnrin Wọn Kò Fi Ní Bà Jẹ́? Ilé Ìṣọ́, 11/1/2011

Béèyàn Ṣe Lè Jẹ́ Bàbá Rere Ilé Ìṣọ́, 10/1/2008

Béèyàn Ṣe Lè Jẹ́ Bàbá Tó Dáa Jí!, 9/8/2004

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Àwọn Ìsáǹsá Bàbá Ọmọ​—⁠Ṣé Lóòótọ́ Ni Wọ́n Lè Bọ́? Jí!, 6/8/2000

Ìyá

Ìfẹ́ Ìyá sí Ọmọ Ń Gbé Ìfẹ́ Ọlọ́run Yọ Ilé Ìṣọ́, 5/1/2008

Iṣẹ́ Tó Lè Fún Abiyamọ Nítẹ̀ẹ́lọ́rùn Jù Lọ Ilé Ìṣọ́, 2/1/2008

❐ Jí!, 3/8/2005

Abiyamọ Kú Ọrọ̀ Ọmọ

Àwọn Abiyamọ Tó Ti Jàjàyè

Ìyá Ni Wúrà

Iṣẹ́ Abiyamọ​—⁠Bí O Ṣe Lè Ṣe É Láṣeyanjú Jí!, 4/8/2002

Ààbò

❐ Jí!, 10/2007

Ewu Tí Gbogbo Òbí Ń Kọminú Lé Lórí

Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Yín

Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Mú Kí Ilé Yín Jẹ́ Ibi Ààbò

Bó O Ṣe Lè Fi Ọgbọ́n Ọlọ́run Yọ Àwọn Ọmọ Rẹ Nínú Ewu Ilé Ìṣọ́, 1/1/2005

Jíja Àjàbọ́ Lọ́wọ́ Ìfòòró Ẹni Jí!, 9/8/2003

Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́ Agbára Ìdarí Apanirun Ayọ̀ Ìdílé, orí 8

Ọmọ Ọwọ́ àti Ọmọdé

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Ní Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ Jí!, No. 6 2017

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Láti Máa Gbọ́ràn Jí!, 7/2015

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Tí Ọmọ Rẹ Bá Ń Purọ́ Jí!, 1/2015

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Má Ṣe Sọ Ọmọ Rẹ Di Àkẹ́bàjẹ́ Jí!, 9/2014

Bí Ọmọ Ṣe Ń Yí Nǹkan Pa Dà Láàárín Tọkọtaya Ìdílé Aláyọ̀, apá 6

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Bójú Tó Ọmọ Tó Ń Ṣe Ìjọ̀ngbọ̀n Jí!, 9/2013

❐ Jí!, 10/2011

“Ohun Àgbàyanu Tó Ń Yára Kẹ́kọ̀ọ́ Jù Lọ Lágbàáyé”

Ohun Tí Àwọn Òbí Sọ (Ìgbà Kékeré)

Bó O Ṣe Lè Tọ́ Ọmọ Láti Ìgbà Ọmọdé Títí Dìgbà Ìbàlágà

Ohun Tí Àwọn Òbí Sọ (Ìgbà Ọmọdé)

Bó Ṣe Ṣe Pàtàkì Tó Pé Kó O Tọ́ Ọmọ Rẹ Jí!, 11/8/2004

❐ Jí!, 1/8/2004

Ohun Tí Àwọn Ọmọ Ọwọ́ Nílò àti Ohun Tí Wọ́n Fẹ́

Pípèsè Ohun Tí Àwọn Ọmọdé Nílò fún Wọn

Àwọn Ọmọ Tí Kò Gbádùn Ìgbà Èwe Wọn Jí!, 5/8/2003

Ọmọ Tó Bàlágà

Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Kíyè Sára Tó Bá Ń Lo Íńtánẹ́ẹ̀tì Jí!, 7/2014

Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Nǹkan Bá Tojú Sú Ọmọ Rẹ Obìnrin Jí!, 3/2014

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bí O Ṣe Lè Máa Bá Ọmọ Rẹ Sọ̀rọ̀ Láìsí Àríyànjiyàn Ilé Ìṣọ́, 11/1/2013

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Bá Ọmọ Rẹ Wí Jí!, 9/2013

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Máa Fi Òfin Lélẹ̀ fún Ọmọ Rẹ Tó Ti Ń Bàlágà Jí!, 5/2013

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Máa Bá Ọmọ Rẹ Tó Ti Ń Bàlágà Sọ̀rọ̀ Jí!, 1/2013

❐ Jí!, 10/2011

Bó O Ṣe Lè Tọ́ Ọmọ Láti Ìgbà Ọmọdé Títí Dìgbà Ìbàlágà

Ohun Tí Àwọn Òbí Sọ (Ìgbà Ọmọdé)

Bí Àwọn Òbí Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ Fún Àwọn Ọmọ Wọn Tó Ti Bàlágà

Ohun Tí Àwọn Òbí Sọ (Ìgbà Ìbàlágà)

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bó O Ṣe Lè Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Nígbà Tí Wọ́n Bá Ń Bàlágà Ilé Ìṣọ́, 5/1/2009

Ran Ọ̀dọ́langba Rẹ Lọ́wọ́ Láti Ṣàṣeyọrí Ayọ̀ Ìdílé, orí 6

Ọmọ Tó Ti Dàgbà

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: Ó Fara Da Ọgbẹ́ Ọkàn Ilé Ìṣọ́, 5/1/2014

Bí Ẹ Ṣe Lè Jẹ́ Kí Àlàáfíà Jọba Láàárín Ẹ̀yin Àtàwọn Mọ̀lẹ́bí Yín Ìdílé Aláyọ̀, apá 5

Ẹ̀kọ́ àti Ìdánilẹ́kọ̀ọ́

Tún wo ìwé pẹlẹbẹ:

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

Kọ́ Ọmọ Rẹ

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Iṣẹ́ Ilé Ṣe Pàtàkì Jí!, No. 3 2017

Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Níwà Ọmọlúwàbí Lóde Òní Jí!, 1/2013

Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Láti Máa Bọ̀wọ̀ Fúnni Ilé Ìṣọ́, 2/15/2011

Ẹ Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Láti Nífẹ̀ẹ́ sí Ìwé Kíkà àti Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́, 7/15/2010

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bá A Ṣe Lè Tọ́ Ọmọ Kan Di Ẹni Tó Dáńgájíá Ilé Ìṣọ́, 5/1/2010

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dúpẹ́ Oore? Ilé Ìṣọ́, 8/1/2008

Ọmọ Títọ́ Láyé Táwọn Èèyàn Ti Ń Ṣèyí Tó Wù Wọ́n Ilé Ìṣọ́, 4/1/2008

❐ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2006

Ìmọ̀ràn “Àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n” Kò Dúró Sójú Kan

Ìmọ̀ràn Tó Ṣeé Gbára Lé Lórí Ọ̀rọ̀ Ọmọ Títọ́

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ẹ Máa Wáyè Gbọ́ Tàwọn Ọmọ Jí!, 2/8/2005

Bá A Ṣe Lè Dẹni Tó Nífẹ̀ẹ́ sí Ẹ̀kọ́ Kíkọ́ Jí!, 8/8/2004

❐ Ilé Ìṣọ́, 6/15/2004

Ìṣòro Tó Wà Nínú Ọmọ Títọ́ Lóde Òní

Ǹjẹ́ Bíbélì Lè Ràn Ọ́ Lọ́wọ́ Láti Tọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ?

Ohun Tí Kì Í Jẹ́ Kí Àwọn Ọmọdé Gbádùn Ìgbà Èwe Wọn Jí!, 5/8/2003

A Gbọ́dọ̀ Kọ Ìdẹwò Olùkọ́, orí 9

Ìdí Tó Fi Nira Láti Máa Ṣe Rere Olùkọ́, orí 26

Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Kó O Máa Kàwé Sókè Ketekete fún Ọmọ Rẹ? Jí!, 12/8/2001

Ìgbọràn​—⁠Ṣé Ẹ̀kọ́ Pàtàkì Téèyàn Ń Kọ́ Lọ́mọdé Ni? Ilé Ìṣọ́, 4/1/2001

Kọ́ Ọmọ Rẹ Láti Ìgbà Ọmọdé Jòjòló Ayọ̀ Ìdílé, orí 5

Ìtọ́ni Tẹ̀mí

❐ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 12/2017

Ẹ̀yin Òbí​​—⁠Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè “Di Ọlọ́gbọ́n fún Ìgbàlà”

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​​—⁠“Ẹ Máa Ṣiṣẹ́ Ìgbàlà Yín Yọrí”

Bá A Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ Fáwọn Ọmọ Tí Òbí Wọn Jẹ́ Àjèjì Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 5/2017

Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ní Ìgbàgbọ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Nínú Ẹlẹ́dàá Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 2/2017

Ṣé Ọwọ́ Pàtàkì Lo Fi Ń Mú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run? Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 11/2016

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Rẹ Jó Rẹ̀yìn Tó O Bá Ń Sìn Nílẹ̀ Àjèjì Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 10/2016

Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Káwọn Ọmọ Yín Nígbàgbọ́ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 9/2016

❐ Ilé Ìṣọ́, 11/15/2015

Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Sin Jèhófà​—⁠Apá Kìíní

Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Sin Jèhófà​—⁠Apá Kejì

Àfikún (§ Ọ̀rọ̀ Ìyànjú fún Àwọn Òbí) A Ṣètò Wa

Ẹ̀yin Òbí​—⁠Ẹ Máa Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Ilé Ìṣọ́, 9/15/2014

Àpótí Ìbéèrè: Kí làwọn ọmọ gbọ́dọ̀ kọ́ kí ẹ̀kọ́ òtítọ́ lè jinlẹ̀ nínú wọn? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2014

Bí O Ṣe Lè Máa Kọ́ Ọmọ Rẹ Ìdílé Aláyọ̀, apá 7

Máa Lo Ìkànnì Wa Láti Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2013

Ẹ̀yin Òbí​—⁠Ẹ Kọ́ Ọmọ Yín Láti Kékeré Ilé Ìṣọ́, 8/15/2013

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Kí Lo Lè Ṣe Bí Ọmọ Rẹ Tó Ti Bàlágà Bá Ń Ṣiyè Méjì Nípa Ẹ̀sìn Rẹ? Ilé Ìṣọ́, 2/1/2012

❐ Ilé Ìṣọ́, 8/1/2011

Ṣé Ó Yẹ Kí Àwọn Ọmọdé Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Ọlọ́run?

Kí Ló Yẹ Kí Àwọn Ọmọdé Kọ́?

Ta Ló Yẹ Kí Ó Kọ́ Àwọn Ọmọdé Nípa Ọlọ́run?

Bí A Ṣe Lè Kọ́ Àwọn Ọmọdé Nípa Ọlọ́run​—⁠Àwọn Ọ̀nà Wo Ló Dára Jù Lọ Láti Gbà Kọ́ Wọn?

Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Láti Kojú Àwọn Ìṣòro Tó Ń Bá Wọn Fínra Ilé Ìṣọ́, 1/15/2010

Kọ́ Ọmọ Rẹ Láti Jẹ́ Ẹni Àlàáfíà Ilé Ìṣọ́, 12/1/2007

Bó O Ṣe Lè Gbin Ìfẹ́ Ọlọ́run Sọ́kàn Ọmọ Rẹ Ilé Ìṣọ́, 9/15/2007

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ǹjẹ́ àwọn ọmọ táwọn òbí tó jẹ́ Kristẹni bá tọ́ dáadáa ò ní kúrò ní ọ̀nà Jèhófà? (Òwe 22:6) Ilé Ìṣọ́, 6/1/2007

Kí Ni Mo Lè Ṣe Kí Ọmọ Mi Lè Jẹ́ Ẹni Tó Gbẹ̀kọ́? Ilé Ìṣọ́, 5/15/2007

❐ Ilé Ìṣọ́, 4/1/2005

Ogun Iyebíye Làwọn Ọmọ Wa

Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Dáàbò Bo Ogún Iyebíye Tẹ́ Ẹ Ní

Ogún Wo Ló Yẹ Kó O Fi Sílẹ̀ fún Àwọn Ọmọ Rẹ? Ilé Ìṣọ́, 9/1/2004

Ogún Ṣíṣeyebíye Jù Lọ Ilé Ìṣọ́, 6/15/2004

Gbin Ohun Tó Dáa Sọ́kàn Ọmọ Rẹ Láti Kékeré! Ilé Ìṣọ́, 2/15/2003

Ohun Tó Yẹ Kí Àwọn Òbí Ṣe fún Àwọn Ọmọ Wọn Olùkọ́, Ọ̀rọ̀ àkọ́sọ

Títọ́ Ọmọ Nílẹ̀ Òkèèrè Ìpèníjà àti Èrè Tó Wà Ńbẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 10/15/2002

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ìlànà wo ló wà fún ọmọ títọ́ nínú ìdílé tí àwọn òbí ti ń ṣe ẹ̀sìn ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀? Ilé Ìṣọ́, 8/15/2002

❐ Ilé Ìṣọ́, 10/1/2001

Fara Wé Jèhófà Nígbà Tóo Bá Ń Tọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ

Báwo Lo Ṣe Lè Ran Ọmọ “Onínàákúnàá” Lọ́wọ́?

Gbígbé Ìdílé Tó Dúró Sán-ún Nípa Tẹ̀mí Ró Ilé Ìṣọ́, 5/15/2001

Ẹ̀kọ́ Nípa Ìbálòpọ̀

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Kọ́ Ọmọ Rẹ Nípa Ìbálòpọ̀ Jí!, No. 5 2016

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Ran Ọmọ Rẹ Tó Ń Bàlágà Lọ́wọ́ Jí!, No. 2 2016

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bá Ọmọ Rẹ Sọ̀rọ̀ Nípa Fífi Ọ̀rọ̀ Ìṣekúṣe Ránṣẹ́ Lórí Fóònù Jí!, 1/2014

Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé: Ṣé Ó Yẹ Kí Àwọn Òbí Kọ́ Àwọn Ọmọ Wọn Lẹ́kọ̀ọ́ Nípa Ìbálòpọ̀? Ilé Ìṣọ́, 11/1/2011

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Ní Ohun Tó Tọ́ Nípa Ìbálòpọ̀ Ilé Ìṣọ́, 2/1/2011

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bá Ọmọ Rẹ Sọ̀rọ̀ Nípa Ìbálòpọ̀ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2010

Bó O Ṣe Lè Ran Ọmọbìnrin Rẹ Lọ́wọ́ Láti Múra Sílẹ̀ De Ìgbà Tó Máa Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣe Nǹkan Oṣù Jí!, 10/2006

Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Dáàbò Bo Ogún Iyebíye Tẹ́ Ẹ Ní (§ Ẹ̀kọ́ Tó Ṣe Pàtàkì Lóde Òní) Ilé Ìṣọ́, 4/1/2005

Agbára Jésù Ju Ti Àwọn Ẹ̀mí Èṣù Lọ Olùkọ́, orí 10

Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́ Agbára Ìdarí Apanirun (§ Ta Ni Yóò Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ?; § Ojú Ìwòye Ọlọrun Nípa Ìbálòpọ̀) Ayọ̀ Ìdílé, orí 8

“Kọ́ Ọmọ Rẹ” (Ọ̀wọ́ àpilẹ̀kọ Ilé Ìṣọ́)

Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Rántí​—⁠Jésù Kristi? Ilé Ìṣọ́, 12/1/2013

Ohun Tí O Bá Ṣe Lè Dun Ọlọ́run​—⁠Bí O Ṣe Lè Mú Inú Rẹ̀ Dùn Ilé Ìṣọ́, 9/1/2013

Kí La Rí Kọ́ Nínú Ohun Tó Ṣẹlẹ̀ sí Ọ̀daràn Kan? Ilé Ìṣọ́, 6/1/2013

Pétérù Parọ́, Ananíà Náà Parọ́​—⁠Ẹ̀kọ́ Wo Ni Èyí Kọ́ Wa? Ilé Ìṣọ́, 3/1/2013

Jótámù Jẹ́ Olóòótọ́ Bó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Bàbá Rẹ̀ Kò Sin Jèhófà Mọ́ Ilé Ìṣọ́, 12/1/2012

Géhásì Fi Ojúkòkòrò Ba Ayé Ara Rẹ̀ Jẹ́ Ilé Ìṣọ́, 9/1/2012

Ó Kọ́kọ́ Ṣàìgbọràn àmọ́ Nígbà Tó Yá Ó Ṣègbọràn Ilé Ìṣọ́, 6/1/2012

‘Ó Ń Bá A Nìṣó Ní Fífà Mọ́ Jèhófà’ Ilé Ìṣọ́, 3/1/2012

A Pè Wọ́n Ní “Àwọn Ọmọ Ààrá” Ilé Ìṣọ́, 12/1/2011

Àkókò Tí Kò Yẹ Ká Sùn Ilé Ìṣọ́, 10/1/2011

Ìdí Tí Àwọn Èèyàn Fi Fẹ́ràn Dọ́káàsì Ilé Ìṣọ́, 8/1/2011

Ǹjẹ́ Ó Máa Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé Àjèjì Ni Ẹ́? Ilé Ìṣọ́, 6/1/2011

Ǹjẹ́ Ó Máa Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé O Dá Wà Tí Ẹ̀rù sì Ń Bà Ẹ́? Ilé Ìṣọ́, 4/1/2011

Ọlọ́run Fẹ́ràn Rẹ̀, Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ̀ sì Fẹ́ràn Rẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 2/1/2011

Àṣírí Kan Tó O Lè Sọ fún Ẹlòmí ì Ilé Ìṣọ́, 12/1/2010

Ìjọba Tó Máa Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà Ilé Ìṣọ́, 10/1/2010

Kí Nìdí Tí Jésù Kò Fi Kánjú Ilé Ìṣọ́, 8/1/2010

Àwọn Tó Kọ̀wé Nípa Jésù Ilé Ìṣọ́, 6/1/2010

Jésù Kẹ́kọ̀ọ́ Láti Jẹ́ Onígbọràn Ilé Ìṣọ́, 4/1/2010

Rèbékà Fẹ́ Láti Ṣe Ohun Tí Inú Jèhófà Dùn Sí Ilé Ìṣọ́, 2/1/2010

Jeremáyà Kò Jáwọ́ Nínú Ṣíṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run Ilé Ìṣọ́, 12/1/2009

Ṣémù Rí Ìwà Ìbàjẹ́ Tó Wà Láyé Ṣáájú àti Lẹ́yìn Ìkún-omi Ilé Ìṣọ́, 10/1/2009

Ráhábù Fi Ohun Tó Gbọ́ Sọ́kàn Ilé Ìṣọ́, 8/1/2009

Ọmọkùnrin Kan Gba Ẹ̀mí Pọ́ọ̀lù Là Ilé Ìṣọ́, 6/1/2009

Ẹgbẹ́ Búburú Ò Jẹ́ Kí Jèhóáṣì Sin Jèhófà Mọ́ Ilé Ìṣọ́, 4/1/2009

Jòsáyà Pinnu Láti Ṣohun Tó Tọ́ Ilé Ìṣọ́, 2/1/2009

Ìdí Tí Dáfídì Ò Fi Bẹ̀rù Ilé Ìṣọ́, 12/1/2008

Sámúẹ́lì Tẹra Mọ́ Ṣíṣe Ohun Tí Ó Tọ́ Ilé Ìṣọ́, 8/1/2008

Ọmọbìnrin Kan Ran Ọkọ Ọ̀gá Rẹ̀ Lọ́wọ́ Ilé Ìṣọ́, 6/1/2008

Tímótì Ti Ṣe Tán, Ó sì Wù Ú Láti Sin Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 4/1/2008

Máàkù Ò Rẹ̀wẹ̀sì Ilé Ìṣọ́, 2/1/2008

Ìbáwí

Bí O Ṣe Lè Bá Àwọn Ọmọ Rẹ Wí Ilé Ìṣọ́, 7/1/2014

Ohun Tí Àwọn Òbí Sọ (§ Ìbáwí) Jí!, 10/2011

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Ọmọ Títọ́ Ilé Ìṣọ́, 2/1/2009

Ẹ̀yin Òbí​—⁠Ẹ Máa Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Tìfẹ́tìfẹ́ (§ Béèyàn Ṣe Lè Bá Ọmọ Wí Tìfẹ́tìfẹ́) Ilé Ìṣọ́, 9/1/2007

Ohun Tó Yẹ Kó O Ṣe Kó O Lè Ní Ìdílé Tó Ń Múnú Ọlọ́run Dùn (§ “Okùn Ìfẹ́” Ló Ń Múni Báni Wí) Ọjọ́ Jèhófà, orí 10

Ojú Ìwòye Bíbélì: Fífi Ìbáwí Ọlọ́run Tọ́ Àwọn Ọmọ Jí!, 11/8/2004

Mímọrírì Ìdí Tá A Fi Ń Báni Wí (§ Ìbáwí Látọ̀dọ̀ Àwọn Òbí To Nífẹ̀ẹ́; § Àwọn Kristẹni Olùṣọ́ Àgùntàn Ń Fi Ìwà Tútù Báni Wí) Ilé Ìṣọ́, 10/1/2003

A Ní Ọlọ̀tẹ̀ Nílé Bí? Ayọ̀ Ìdílé, orí 7

Ìgbàṣọmọ àti Ìgbéyàwó Àtúnṣe

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bí Àárín Àwọn Tó Tún Ìgbéyàwó Ṣe àti Àwọn Ẹlòmíì Ṣe Lè Tòrò Ilé Ìṣọ́, 5/1/2013

Dádì Tàbí Mọ́mì Mi Fẹ́ Ẹlòmí ì, Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Un Mọ́ra? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 5

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kojú Ìṣòro Jíjẹ́ Ọmọ Àgbàtọ́? Jí!, 6/8/2003

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Tí Wọ́n Fi Fi Mí Sọ́dọ̀ Alágbàtọ́? Jí!, 5/8/2003

Jẹ́ Kí Àlàáfíà Jọba Nínú Agbo Ilé Rẹ (§ Ìpènijà Jíjẹ́ Òbí Nínú Ìgbéyàwó Àtúnṣe) Ayọ̀ Ìdílé, orí 11

Ọ̀dọ́

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: “Ọmọ Mi Olùfẹ́ Ọ̀wọ́n àti Olùṣòtítọ́ Nínú Olúwa” Ilé Ìṣọ́, 11/1/2015

Àjọṣe Pẹ̀lú Ọlọ́run

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​​—⁠“Ẹ Máa Ṣiṣẹ́ Ìgbàlà Yín Yọrí” Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 12/2017

❐ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 3/2016

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—⁠Ṣé Ẹ Ti Múra Tán Láti Ṣe Ìrìbọmi?

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—⁠Báwo Lẹ Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìrìbọmi?

❐ Ilé Ìṣọ́, 12/15/2014

Bá A Ṣe Lè La Òpin Ayé Ògbólógbòó Yìí Já Pa Pọ̀

Ǹjẹ́ O Mọyì Ohun Tí O Ti Rí Gbà?

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: ‘Èmi Kò Lè Hùwà Búburú Ńlá Yìí’ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2014

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Lọ Sáwọn Ìpàdé Kristẹni? Jí!, 7/2012

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbádùn Ìjọsìn Ọlọ́run? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 38

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Mú Kí Ìfẹ́ Yín Láti Sin Jèhófà Jinlẹ̀ Sí I Ilé Ìṣọ́, 4/15/2010

Ṣé Àwọn Òbí Mi​—⁠Ni Yóò Pinnu Ẹ̀sìn Mi àbí Èmi Fúnra Mi? Ilé Ìṣọ́, 9/15/2009

Pinnu Láti Sin Jèhófà Látìgbà Èwe Rẹ Ilé Ìṣọ́, 5/15/2008

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Tó FI Yẹ Kí N Máa Fàwọn Ìlànà Bíbélì Ṣèwà Hù? Jí!, 1/2008

Ẹ̀yin Èwe, Ẹ Yin Jèhófà! Ilé Ìṣọ́, 6/15/2005

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́ Ẹ Jẹ́ Káwọn Òbí Yín Ràn Yín Lọ́wọ́ Kẹ́ Ẹ Lè Dáàbò Bo Ọkàn Yín! Ilé Ìṣọ́, 10/15/2004

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ǹjẹ́ Ẹ̀ Ń Múra Sílẹ̀ fún Ọjọ́ Ọ̀la? Ilé Ìṣọ́, 5/1/2004

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Máa Rìn Ní Ọ̀nà Tó Wu Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 10/15/2003

❐ Ilé Ìṣọ́, 4/15/2003

Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ń Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—⁠Jèhófà Ò Mà Ní Gbàgbé Iṣẹ́ Yín!

Àwọn Ọmọdé Tó Mú Inú Ọlọ́run Dùn Olùkọ́, orí 41

Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Fẹ́ràn Òtítọ́ Ilé Ìṣọ́, 10/1/2002

“Ẹ Wá Sọ́dọ̀ Mi, . . . Èmi Yóò sì Tù Yín Lára”: Àwọn Èwe Tí Wọ́n Dà Bí Ìrì Tó Ń Tuni Lára Ilé Ìṣọ́, 9/15/2002

❐ Ilé Ìṣọ́, 8/15/2001

Ìwé Tí Ọ̀pọ̀ Jù Lọ Àwọn Ọ̀dọ́ Kò Nífẹ̀ẹ́ Sí

Bí Ìgbà Èwe Rẹ Ṣe Lè Dùn Bí Oyin

Ẹ Dúró Lọ́nà Pípé Pẹ̀lú Ìgbàgbọ́ Tó Fìdí Múlẹ̀: Fífi Ìtọ́ni Àsìkò Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Ilé Ìṣọ́, 7/15/2001

Àjọṣe Pẹ̀lú Ìdílé

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Bá Àwọn Òbí Mi Sọ̀rọ̀? Ìbéèrè 10, ìbéèrè 3

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Ìgbà Tó Yẹ Kó O Pa Dà Sọ́dọ̀ Àwọn Òbí Rẹ Jí!, 11/2015

Tẹ́ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn: “Ẹ Jọ̀wọ́, Ẹ Fetí sí Àlá Tí Mo Lá” (§ Ìdílé Tó Ti Wá Kò Fara Rọ; § Owú Bẹ̀rẹ̀) Ilé Ìṣọ́, 8/1/2014

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Tí Ọ̀rọ̀ Mi Kò Fi Yé Àwọn Òbí Mi? Jí!, 7/2012

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Táwọn Òbí Mi Kì Í Jẹ́ Kí N Gbádùn Ara Mi? Jí!, 4/2011

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Òbí Mi Sọ̀rọ̀? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 1

Kí Nìdí Témi Àtàwọn Òbí Mi Fi Máa Ń Bára Wa Jiyàn? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 2

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Màá Fi Ní Òmìnira Sí I? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 3

Báwo Lọ̀rọ̀ Èmi àti Tẹ̀gbọ́n-Tàbúrò Mi Ṣe Lè Wọ̀ Dáadáa? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 6

Ṣé Ó Burú Kéèyàn Tiẹ̀ Láṣìírí Ni? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 15

Kí Nìdí Táwọn Òbí Mi Kì Í Fi Í Jẹ́ Kí N Gbádùn Ara Mi? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 37

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Témi Àtàwọn Òbí Mi Kì Í Fi Í Gbọ́ra Wa Yé? Jí!, 4/2010

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Òbí Mi Sọ̀rọ̀? Jí!, 1/2010

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Táwọn Òbí Mi Ò Fi Fọkàn Tán Mi? Jí!, 4/2008

Òfin Yìí Ò Wa Pọ̀ Jù? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 22

Kí Ni Kí N Ṣe Báwọn Òbí Mi Bá Ń Jà? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 24

“Ẹ̀yin Ọmọ, Ẹ Jẹ́ Onígbọràn sí Àwọn Òbí Yín” Ilé Ìṣọ́, 2/15/2007

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Fífi Ẹ̀gbọ́n Mi Ṣe Àwòkọ́ṣe Nínú Gbogbo Nǹkan? Jí!, 12/8/2003

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Làwọn Èèyàn Ṣe Lè Máa Fi Ọ̀wọ̀ Tèmi Wọ̀ Mí? Jí!, 11/8/2003

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Fara Dà Á Nígbà Tí Àjálù Bá Wáyé? Jí!, 7/8/2003

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ló Dé Tí Ọ̀kan Nínú Àwọn Òbí Mi Kò Fi Nífẹ̀ẹ́ Mi Mọ́? Jí!, 10/8/2002

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Màá Ṣe Fara Dà Á Ní Báyìí Tí Dádì Ti Já Wa Sílẹ̀? Jí!, 1/8/2001

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Èé Ṣe Tí Dádì Fi Já Wa Sílẹ̀? Jí!, 12/8/2000

Jẹ́ Kí Àlàáfíà Jọba Nínú Agbo Ilé Rẹ (§Bí Ìsìn Rẹ Bá Yàtọ̀ Sí Ti Àwọn Òbí Rẹ) Ayọ̀ Ìdílé, orí 11

Àjọṣe Pẹ̀lú Àwọn Ẹlòmíì

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Àyípadà Bá Ṣẹlẹ̀ Jí!, No. 4 2016

Àwọn Ìbéèrè tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè: Àwọn Wo Ni Ọ̀rẹ́ Mi Tòótọ́? Jí!, 1/2012

Àwọn Ìbéèrè tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Rí Ọ̀rẹ́ Tí Ọ̀rọ̀ Wa Bára Mu? Jí!, 7/2011

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ní Àwọn Ọ̀rẹ́ Tó Dáa? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 8

Èdè àti Àṣà Tàwọn Òbí Mi Yàtọ̀ sí Tibi Tá À Ń Gbé, Kí Ni Kí N Ṣe? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 22

Àwọn Ìbéèrè tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè: Kí Ni Mo Lè Ṣe Táwọn Oníbìínú Èèyàn Bá Kò Mí Lójú? Jí!, 12/8/2001

Níní Àfojúsùn

Tún wo Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún lábẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lábẹ́ Ìjọ Kristẹni àti Nínàgà fún Àǹfààní Iṣẹ́ Ìsìn lábẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lábẹ́ Ìjọ Kristẹni

“Jẹ́ Onígboyà . . . Kí O sì Gbé Ìgbésẹ̀” Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 9/2017

Jèhófà Máa Jẹ́ Kí Àwọn Ìpinnu Rẹ Yọrí Sí Rere Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 7/2017

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—⁠Ẹ Má Ṣe Fàkókò Ṣòfò Láti Wọnú “Ilẹ̀kùn Ńlá” Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 11/2016

Àwọn Ọ̀nà Tó O Fi Lè Mú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Gbòòrò Sí I A Ṣètò Wa, orí 10

“Mú Ipa Ọ̀nà Ẹsẹ̀ Rẹ Jọ̀lọ̀” Kó O Lè Tẹ̀ Síwájú Ilé Ìṣọ́, 6/15/2014

Bó O Ṣe Lè Ṣe Ìpinnu Tó Bọ́gbọ́n Mu Nígbà Ọ̀dọ́ Ilé Ìṣọ́, 1/15/2014

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Àwọn Wo Ni Mo Fi Ń Ṣe Àwòkọ́ṣe? Jí!, 10/2012

Báwo Ni Ọwọ́ Mi Ṣe Lè Tẹ Àwọn Ohun Tí Mo Fẹ́ Lé Bá? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 39

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Kí Lẹ Máa Fi Ìgbésí Ayé Yín Ṣe? Ilé Ìṣọ́, 11/15/2010

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Ọwọ́ Mi Ṣe Lè Tẹ Àwọn Àfojúsùn Mi? Jí!, 1/2011

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Jẹ́ Kí Ìtẹ̀síwájú Yín Fara Hàn Kedere Ilé Ìṣọ́, 5/15/2009

Pinnu Láti Sin Jèhófà Látìgbà Èwe Rẹ Ilé Ìṣọ́, 5/15/2008

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Rántí Ẹlẹ́dàá Yín Atóbilọ́lá Nísinsìnyí Ilé Ìṣọ́, 4/15/2008

Kí Ni Màá Fayé Mi Ṣe? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 38

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—⁠Ẹ Máa Lépa Ohun Tó Máa Gbórúkọ Ọlọ́run Ga Ilé Ìṣọ́, 5/1/2007

Fi Àwọn Ohun Tó Ò Ń Lé Nípa Tẹ̀mí Yin Ẹlẹ́dàá Rẹ Lógo Ilé Ìṣọ́, 7/15/2004

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—⁠Ǹjẹ́ Ẹ̀ Ń Tẹ̀ Síwájú Nípa Tẹ̀mí? Ilé Ìṣọ́, 4/1/2003

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—⁠Kí Lẹ Máa Fi Ìgbésí Ayé Yín Ṣe? Ìgbésí Ayé Yín

Tó O Bá Fẹ́ Lọ Máa Dá Gbé

Ṣé Mo Ti Tó Ẹni Tó Lè Lọ Dá Gbé? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 7

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Ṣé Ó Ti Yẹ Kí N Kúrò Lọ́dọ̀ Àwọn Òbí Mi? Jí!, 10/2010

Àwọn Ìbéèrè tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè: Báwo Làjọgbé Èmi àti Alábàágbé Mi Ṣe Lè Wọ̀? Jí!, 7/8/2002

Àwọn Ìbéèrè tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Rí Alábàágbé Tó Dára? Jí!, 6/8/2002

Àwọn Ìbéèrè tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè: Kí Ló Dé Tí Àjọgbé Èmi àti Alábàágbé Mi Fi Nira? Jí!, 5/8/2002

Àwọn Ìṣòro Mí ì

Tún wo Ìṣòro lábẹ́ Ẹ̀kọ́ Ìwé àti Èdè lábẹ́ Ilé Ìwé

Irú Èèyàn Wo Gan-an Ni Mo Jẹ́? Ìbéèrè 10, ìbéèrè 1

Ṣó Yẹ Kí N Máa Da Ara Mi Láàmú Torí Bí Mo Ṣe Rí? Ìbéèrè 10, ìbéèrè 2

Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Wọ́n Bá Ń Halẹ̀ Mọ́ Mi Níléèwé? Ìbéèrè 10, ìbéèrè 5

Kí Ni Mo Lè Ṣe Káwọn Ojúgbà Mi Má Bàa Ba Ìwà Mi Jẹ́? Ìbéèrè 10, ìbéèrè 6

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí O Ṣe Lè Borí Ìdẹwò Jí!, 11/2014

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Ojú Wo Ló Yẹ Kó O Fi Wo Ìbáwí? Jí!, 5/2014

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Irú Èèyàn Wo Gan-an Ni Mo Jẹ́? Jí!, 1/2012

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Borí Ìdẹwò? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 9

Irú Aṣọ Wo Ló Yẹ Kí N Wọ̀? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 11

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Fọgbọ́n Lo Àkókò Mi? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 21

❐ Ilé Ìṣọ́, 11/15/2010

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Máa Darí Yín

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Má Ṣe Fàyè Gba Ẹ̀mí Ṣohun-tẹ́gbẹ́-ń-ṣe

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Jẹ́ Kí Ìtẹ̀síwájú Yín Fara Hàn Kedere (§ Lo “Ìyèkooro Èrò Inú” Nígbà Ìṣòro) Ilé Ìṣọ́, 5/15/2009

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe Báwọn Òbí Mi Bá Ní Aago Báyìí Ni Mo Gbọ́dọ̀ Máa Wọlé? Jí!, 10/2008

Ǹjẹ́ O Ti Múra Tán Láti Gbèjà Ìgbàgbọ́ Rẹ? Ilé Ìṣọ́, 6/15/2008

Ibo Ni Mo Ti Lè Rí Ìmọ̀ràn Tó Dáa Jù Lọ? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú

Kí Nìdí Tára Mi Fi Ń Yí Pa Dà? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 6

Báwọn Òbí Mi Ò Bá Lówó Ńkọ́? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 20

Kí Ni Mo Lè Ṣe Táwọn Òbí Mi Bá Ń Rí sí Mi Ṣáá? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 21

❐ Jí!, 4/8/2005

Wàhálà Tó Ń Báwọn Ọ̀dọ́ Òde Ìwòyí Fínra

Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Òde Ìwòyí Lọ́wọ́

❐ Jí!, 7/8/2004

Ayọ̀ àti Ìṣòro Ìgbà Ìbàlágà

“Rántí Ẹlẹ́dàá Rẹ”

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Èé Ṣe Tí Mo Fi Rí Tẹ́ẹ́rẹ́ Báyìí? Jí!, 10/8/2000

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Àwọn Ìsáǹsá Bàbá Ọmọ​—⁠Ṣé Lóòótọ́ Ni Wọ́n Lè Bọ́? Jí!, 6/8/2000

Ìmọ̀lára

❐ Jí!, No. 2 2017

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Nígbà Tí Òbí Ẹnì Kan Bá Kú

Tí Òbí Ọmọdé Kan Bá Kú

Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ní Ìdààmú Ọkàn Jí!, No. 1 2017

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Ohun Tó O Lè Ṣe Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bí I Pé O Kò Ní Ọ̀rẹ́ Jí!, 5/2015

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí O Ṣe Lè Ṣàkóso Ìbínú Rẹ Jí!, 3/2015

Àwọn Ìbéèrè tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè: Kí Ló Dé Témi Ò fi Mọ Nǹkan Kan Ṣe? Jí!, 7/2011

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Túbọ̀ Dá Ara Mi Lójú? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 12

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Ìbànújẹ́ Kúrò Lọ́kàn Mi? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 13

Àbí Kí N Para Mi Ni? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 14

Ṣé Bí Mo Ṣe Ń Kẹ́dùn Dáa Báyìí? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 16

Àwọn Ìbéèrè tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè: Kí Ni Kí N Ṣe Bí Mi Ò Bá Ṣe Dáadáa Tó? Jí!, 12/8/2004

Tẹlifóònù

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Gba Tàwọn Míì Rò Tí O Bá Ń Lo Fóònù Rẹ Jí!, 9/2014

Àwọn Òbí Tó Ti Dàgbà àti Àwọn Òbí Àgbà

❐ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2014

Ẹ Máa Bọlá fún Àwọn Àgbàlagbà Tó Wà Láàárín Yín

Bá A Ṣe Lè Máa Tọ́jú Àwọn Àgbàlagbà

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Lájọṣe Tímọ́tímọ́ Pẹ̀lú Àwọn Òbí Mi Àgbà? Jí!, 6/8/2001

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Kí N Sún Mọ́ Àwọn Òbí Mi Àgbà? Jí!, 5/8/2001

Dídàgbà Pọ̀ Ayọ̀ Ìdílé, orí 14

Bíbọlá fún Àwọn Òbí Wa Àgbàlagbà Ayọ̀ Ìdílé, orí 15

Ìdílé Tí Wọ́n Ti Ń Ṣe Ẹ̀sìn Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀

Idà Ni Òtítọ́ Ń Mú Wá, Kì Í Ṣe Àlàáfíà Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 10/2017

Bá A Ṣe Lè Mú Kí Àwọn Ìbátan Wa Tí Kì í Ṣe Ẹlẹ́rìí Nífẹ̀ẹ́ Òtítọ́ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2014

Má Ṣe Sọ̀rètí Nù! Ilé Ìṣọ́, 3/15/2013

Àwọn Tó Wà Nínú Ìdílé Tí Wọ́n Ti Ń Ṣe Ẹ̀sìn Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ Lè Láyọ̀ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2012

Báwo Lo Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ fún Ọkọ Tàbí Aya Tó Jẹ́ Aláìgbàgbọ́? Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2010

Ẹ̀yin Obìnrin, Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kẹ́ Ẹ Máa Tẹrí Ba fún Ipò Orí? (§ Bí Ọkọ Tàbí Aya Bá Jẹ́ Aláìgbàgbọ́) Ilé Ìṣọ́, 5/15/2010

Ṣáwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Tú Ìgbéyàwó Ká? Ilé Ìṣọ́, 11/1/2008

Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n fún Àwọn Tọkọtaya (§ Nínú Ìdílé Tí Wọn Ò Ti Ṣe Ẹ̀sìn Kan Náà) Ilé Ìṣọ́, 3/1/2005

Àwọn Obìnrin Tó Mú Inú Jèhófà Dùn (§ Ǹjẹ́ O Lè Dà Bí Ábígẹ́lì?) Ilé Ìṣọ́, 11/1/2003

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Kí ni kí aya kan ṣe tí ọkọ rẹ̀ aláìgbàgbọ́ bá ń ṣe àwọn ọdún ìsìn? Ilé Ìṣọ́, 12/15/2001

Jẹ́ Kí Àlàáfíà Jọba Nínú Agbo Ilé Rẹ Ayọ̀ Ìdílé, orí 11

Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ àti Òbí Anìkàntọ́mọ

Ohun Tí Àwọn Òbí Sọ (Àpótí: Bí Mo Ṣe Ṣàṣeyọrí Gẹ́gẹ́ Bí Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ) Jí!, 10/2011

Máa Fi Ìgbatẹnirò Hàn fún Àwọn Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ Ilé Ìṣọ́, 12/1/2010

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Láyọ̀ Bí Òbí Mi Bá Jẹ́ Anìkàntọ́mọ? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 25

Ẹ̀yin Òbí Ẹ Jẹ́ Àpẹẹrẹ Rere Fáwọn Ọmọ Yín (§ Àwọn Òbí Tó Ń Dá Nìkan Tọ́mọ Lè Kẹ́sẹ Járí) Ilé Ìṣọ́, 4/1/2006

Àwọn Obìnrin Kristẹni Olóòótọ́ Jẹ́ Ẹni Ọ̀wọ́n Tó Ń Sin Ọlọ́run (§ Bí Àwọn Òbí Anìkàntọ́mọ Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí) Ilé Ìṣọ́, 11/1/2003

❐ Jí!, 10/8/2002

Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ Túbọ̀ Ń Pọ̀ Sí I

Ìṣòro Tí Àwọn Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ Ń Kojú Kò Níye

Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ, àmọ́ Tí Kò Dá Wà

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Màá Ṣe Fara Dà Á Ní Báyìí Tí Dádì Ti Já Wa Sílẹ̀? Jí!, 1/8/2000

❐ Jí!, 2/8/2000

Àwọn Ìdílé Tí Kò Ti Sí Bàbá​—⁠Àmì Ìgbàlódé Ni

Àwọn Bàbá​—⁠Ìdí Tí Wọ́n Fi Ń Di Àwátì

Àwọn Ìdílé Tí Kò Ti Sí Bàbá​—⁠Fífòpin sí Ìṣòro Náà

Àwọn Ìdílé Olóbìí Kan Lè Kẹ́sẹ Járí! Ayọ̀ Ìdílé, orí 9

“Àwọn Ọmọ Aláìníbaba”

Sún Mọ́ Ọlọ́run: Bàbá Àwọn Ọmọ Aláìníbaba Ilé Ìṣọ́, 4/1/2009

Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Jèrè Ìyè​—⁠Ǹjẹ́ Ìwọ Náà Fẹ́ Bẹ́ẹ̀? (§ ‘Ó Ń Fi Àánú Hàn sí Ọmọdékùnrin Aláìníbaba’) Ọjọ́ Jèhófà, orí 11

Fi Ìfẹ́ Àtọkànwá Hàn sí “Àwọn Ọmọdékùnrin Aláìníbaba” Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 11/2002

Bí Ìdílé Ṣe Lè Lágbára

❐ Ilé Ìṣọ́, 5/15/2011

Ẹ̀yin Ìdílé Kristẹni​—⁠“Ẹ Wà Lójúfò”

Ẹ̀yin Ìdílé Kristẹni​—⁠“Ẹ Wà Ní Ìmúratán”

❐ Jí!, 1/2010

Ohun Àkọ́kọ́: Fi Ohun Tó Yẹ Sípò Àkọ́kọ́

Ohun Kejì: Pa Àdéhùn Ìgbéyàwó Mọ́

Ohun Kẹta: Ìfọwọ́sowọ́pọ̀

Ohun Kẹrin: Ọ̀wọ̀

Ohun Karùn-ún: Ìfòyebánilò

Ohun Kẹfà: Ìdáríjì

Ohun Keje: Àjọṣe Tó Fìdí Múlẹ̀ Ṣinṣin

Ẹ̀yin Ìdílé Kristẹni Ẹ Máa Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù! Ilé Ìṣọ́, 7/15/2009

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bá A Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Ọmọ Tó Ṣẹ̀ṣẹ̀ Ń Bàlágà Sọ̀rọ̀ Ilé Ìṣọ́, 8/1/2008

Máa Fi ‘Ọ̀rọ̀ Tó Dára’ Gbé Ìdílé Rẹ Ró Ilé Ìṣọ́, 1/1/2008

Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Pèsè Ohun Tí Ìdílé Yín Nílò Ilé Ìṣọ́, 6/15/2005

Ẹ Máa Fi Ìfẹ́ Hàn Nínú Agbo Ìdílé Ilé Ìṣọ́, 12/15/2002

Àwọn Ìṣòro Ìdílé àti Ojútùú

Tún wo Owó lábẹ́ Iṣẹ́ àti Ìnáwó

❐ Jí!, No. 1 2016

Kí Ló Máa Ń Fa Wàhálà Nínú Ilé?

Bí Ẹ Ṣe Lè Dín Wàhálà Kù Nínú Ilé

Bí Ẹ Ṣe Lè Mú Kí Àlàáfíà Wà Nínú Ilé

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Tọrọ Àforíjì Jí!, 11/2015

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bó O Ṣe Lè Dárí Ji Aya Tàbí Ọkọ Rẹ Jí!, 11/2014

❐ Ilé Ìṣọ́, 4/15/2014

Kò Sí Ẹni Tó Lè Sin Ọ̀gá Méjì

Jẹ́ Onígboyà​—⁠Jèhófà Ni Olùrànlọ́wọ́ Rẹ!

Bí Ẹ Ṣe Lè Máa Yanjú Ìṣòro Ìdílé Aláyọ̀, apá 3

Bí Ẹ Ṣe Lè Máa Ṣọ́wó Ná Ìdílé Aláyọ̀, apá 4

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bí Ọ̀rẹ́ Ìwọ Àtẹnì Kan Bá Ti Ń Wọra Jù Jí!, 11/2013

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Ohun Tí Ẹ Lè Ṣe Tí Ọmọ Yín Bá Jẹ́ Abirùn Ilé Ìṣọ́, 2/1/2013

Ìwà Ọ̀dàlẹ̀ Àmì Búburú Kan Tó Fi Hàn Pé À Ń Gbé Ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn! (§ Má Ṣe Dalẹ̀ Ọkọ Tàbí Aya Rẹ) Ilé Ìṣọ́, 4/15/2012

❐ Ilé Ìṣọ́, 2/1/2011

Kí Nìdí Tí Ọ̀pọ̀ Ìgbéyàwó Fi Ń Tú Ká?

Ojútùú sí Àwọn Àròyé Tó Máa Ń Wáyé

Ìwà Ipá Abẹ́lé

Bí Ọkọ Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Lílu Ìyàwó Rẹ̀ Jí!, 5/2013

Kí Ló Fà Á Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Fi Ń Bẹ̀rù? (§ Àwọn Èèyàn Ń Bẹ̀rù Ìwà Ipá Lọ́ọ̀dẹ̀ Wọn) Jí!, 8/8/2005

❐ Jí!, 11/8/2001

“Bóyá Ó Máa Yí Padà Lọ́tẹ̀ Yìí”

Kí Ló Dé Táwọn Ọkùnrin Kan Fi Máa Ń Lu Ìyàwó Wọn?

Ìrànwọ́ fún Àwọn Obìnrin Tí Ọkọ Wọn Ń Lù

“Bí Àlá Ló Máa Ń Rí Lójú Mi Nígbà Mí ì!”

Ìwọ Lè Borí Àwọn Ìṣòro Tí Ń Ṣe Ìdílé Lọ́ṣẹ́ (§ Ọṣẹ́ Tí Ìwà Ipá Abẹ́lé Ń Ṣe; § Bí A Ṣe Lè Yẹra fún Ìwà Ipá Abẹ́lé) Ayọ̀ Ìdílé, orí 12

Panṣágà

Ojú Ìwòye Bíbélì: Panṣágà Jí!, 7/2015

Ẹ Dúró Gbọn-in Kẹ́ Ẹ sì Sá fún Àwọn Ohun Tí Sátánì Fi Ń Múni! (§ Panṣágà, Ọ̀f ìn Tó Fara Sin) Ilé Ìṣọ́, 8/15/2012

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Pa Dà Máa Fọkàn Tán Ara Yín Ilé Ìṣọ́, 5/1/2012

Bó O Ṣe Lè Fara Dà Á Bí Ọkọ Tàbí Aya Rẹ Bá Já Ẹ Jù Sílẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 6/15/2010

Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé: Ṣé Ọlọ́run Fọwọ́ sí Ìkóbìnrinjọ? Ilé Ìṣọ́, 7/1/2009

“Ẹ Jẹ́ Kí Ìgbéyàwó Ní Ọlá” (§ ‘Kí Ibùsùn Ìgbéyàwó Wà Láìní Ẹ̀gbin’) ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 11

“Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Aya Ìgbà Èwe Rẹ” Ilé Ìṣọ́, 9/15/2006

Bí Tọkọtaya Ṣe Lè Láyọ̀ Lóde Òní (§ Àwọn Ewu Tí A Gbọ́dọ̀ Yẹra Fún) Ilé Ìṣọ́, 3/1/2005

Ìkọ̀sílẹ̀ àti Ìpínyà

Báwo La Ṣe Lè Ran Àwọn Kristẹni Tí Ọkọ Tàbí Ìyàwó Wọn Kọ̀ Sílẹ̀ Lọ́wọ́? Ilé Ìṣọ́, 6/15/2014

Bó O Ṣe Lè Máa Gbé Ayé Rẹ Lọ Lẹ́yìn Ìkọ̀sílẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 10/1/2013

Má Sọ̀rètí Nù Bí Ìgbéyàwó Rẹ Kò Bá Fún Ẹ Láyọ̀ (§ Wọ́n Ṣe Tán Láti Ṣèrànwọ́) Ilé Ìṣọ́, 5/15/2012

Kí Nìdí Tí Dádì àti Mọ́mì Fi Fi Ara Wọn Sílẹ̀? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 4

❐ Jí!, 4/2010

“Ó Ti Sú Mi!”

Ohun Mẹ́rin Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Ìkọ̀sílẹ̀

Kí Lẹ Lè Ṣe Tí Ìgbéyàwó Yín Ò Fi Ní Tú Ká?

Kí Ni Kí N Ṣe Báwọn Òbí Mi Bá Ń Jà? (Àpótí: Bí Dádì àti Mọ́mì Mi Bá Fira Wọn Sílẹ̀ Ńkọ́?) Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 24

Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìkọ̀sílẹ̀ àti Ìpínyà ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ Àfikún

Ohun Tó Yẹ Kó O Ṣe Kó O Lè Ní Ìdílé Tó Ń Múnú Ọlọ́run Dùn (§ “Òun Kórìíra Ìkọ̀sílẹ̀”) Ọjọ́ Jèhófà, orí 10

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣé Ìkọ̀sílẹ̀ Ló Máa Yanjú Ìṣòro Yín? Jí!, 9/8/2004

Ìdè Tó Yẹ Kó Wà Pẹ́ Títí Ni Ìgbéyàwó (Àpótí: Pípínyà àti Ìkọ̀sílẹ̀) Jí!, 2/8/2002

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Títí dé àyè wo ló yẹ kí ẹnì kan kọ̀ láti tẹ́wọ́ gba ìgbésẹ̀ ìkọ̀sílẹ̀ tí ọkọ tàbí aya rẹ̀ gbé? Ilé Ìṣọ́, 12/15/2000

Ìwọ Lè Borí Àwọn Ìṣòro Tí Ń Ṣe Ìdílé Lọ́ṣẹ́ (§ Pípínyà Tàbí Gbígbé Pa Pọ̀?) Ayọ̀ Ìdílé, orí 12

Bí Ìgbéyàwó Bá Wà Ní Bèbè Àtitúká Ayọ̀ Ìdílé, orí 13

Àbójútó Ọmọ

Bí A Ṣe Jà fún Òmìnira Láti Lè Máa Sin Jèhófà Láìsí Ìdíwọ́ (§ Ẹ̀tọ́ Tí Àwọn Òbí Ní Láti Fi Ìlànà Jèhófà Kọ́ Àwọn Ọmọ Wọn) Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, orí 15

Àwọn Bàbá​—⁠Ìdí Tí Wọ́n Fi Ń Di Àwátì Jí!, 2/8/2000

Ìjọsìn Ìdílé

Ran Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Máa Rántí Jèhófà Ìwé Ìpàdé, 3/2017

Ẹ̀yin Òbí​—⁠Ẹ Máa Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Ilé Ìṣọ́, 9/15/2014

Ìjọsìn Ìdílé​—⁠Ǹjẹ́ O Lè Mú Kó Túbọ̀ Gbádùn Mọ́ni? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2014

Ẹ Jọ Máa Sin Jèhófà Nínú Ìdílé Yín Ìdílé Aláyọ̀, apá 9

Máa Lo Ìkànnì Wa Láti Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2013

Kí Ni Ìjọsìn Ìdílé? Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 10

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Ẹ̀yin Tọkọtaya, Ẹ Kọ́ Bí Ẹ Ṣe Jọ Máa Jẹ́ Ẹni Tẹ̀mí Ilé Ìṣọ́, 11/1/2011

Àwọn Àbá Tó Lè Wúlò fún Yín Nígbà Ìjọsìn Ìdílé àti Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́, 8/15/2011

Ẹ̀yin Ìdílé Kristẹni​—⁠“Ẹ Wà Ní Ìmúratán” (§ Ẹ Máa Ṣe Ìjọsìn Ìdílé Déédéé) Ilé Ìṣọ́, 5/15/2011

Ẹ Ní Ìdí fún Ayọ̀ Yíyọ̀ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2011

Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Ìdílé Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 1/2011

Kí Ni Ọmọ Rẹ Máa Sọ? Ilé Ìṣọ́, 12/15/2010

Ẹ Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Mọ Ètò Jèhófà Dunjú (Àpótí: Àwọn Ohun Tẹ́ Ẹ Lè Gbé Yẹ̀ Wò Nígbà Ìjọsìn Ìdílé) Ilé Ìṣọ́, 10/15/2010

Bá A Ṣe Lè Rí Ìtura Nínú Àwọn Nǹkan Tẹ̀mí (§ Ìjọsìn Ìdílé Máa Ń Mára Tuni) Ilé Ìṣọ́, 6/15/2010

Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Láti Kojú Àwọn Ìṣòro Tó Ń Bá Wọn Fínra (§ Ìdí Tó Fi Ṣe Pàtàkì Láti Fi Ohun Tẹ́ Ẹ̀ Ń Kọ́ Dánra Wò) Ilé Ìṣọ́, 1/15/2010

❐ Ilé Ìṣọ́, 10/15/2009

Ìjọsìn Ìdílé Ṣe Pàtàkì fún Ìgbàlà Ìdílé Wa!

Ǹjẹ́ O Ti Ya Àkókò Kan Sọ́tọ̀ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Ń Mú Ìtẹ̀síwájú Wá Ilé Ìṣọ́, 7/15/2009

Ìdákẹ́kọ̀ọ́ àti Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ìdílé Ṣe Pàtàkì! Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 10/2008

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìdílé​—⁠Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ìdílé Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2005

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́