Iwe Irohin Isin Wo ni O ní Ipinkiri Pupọ Julọ? “Ilé-ìṣọ́na”!
Nisinsinyi ohun ti o ju ẹda 15 million ninu itẹjade Ilé-ìṣọ́nà kọọkan ni a ntẹ ni eyi ti o ju ọgọrun un ede. Iwọ le gba Ilé-ìṣọ́nà ni eyikeyi ninu awọn ede ti a to lẹsẹẹsẹ si oju-iwe 2. Bi iwọ ba fẹ lati gba Ilé-ìṣọ́nà, ti a ntẹjade lẹẹmeji loṣu, jọwọ kọ ọrọ kun alafo ti o baa rin yii ki o si fi ranṣẹ fun isọfunni.
Emi yoo fẹ ki ẹ fi isọfunni ranṣẹ nipa bi ẹ ṣe le maa fi iwe irohin Ilé-ìṣọ́nà ranṣẹ si ile mi.