ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w91 8/15 ojú ìwé 32
  • “Ọkanṣoṣo Ọ̀gá”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ọkanṣoṣo Ọ̀gá”
  • Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
w91 8/15 ojú ìwé 32

“Ọkanṣoṣo Ọ̀gá”

Iyẹn ni ohun ti ọjọgbọn ede Gẹẹsi kan lati ile-ẹkọ giga kan ni Georgia, U.S.A., wi nipa iwe irohin Ji!. Ó kọwe lẹnu aipẹ yi pe:

“Mo ti nlo awọn iwe irohin Ji! ninu ẹkọ arokọ mi ni ile-ẹkọ giga fun ohun ti o ti ju ọdun meje lọ, mo si gbọdọ sọ pe, awọn onkọwe yin jẹ ọkanṣoṣo ọ̀gá. Awọn inasẹ ọrọ ti nru ifẹ ọkan soke ati awọn kulẹkulẹ ti o ṣe kedere tí ọpọlọpọ ọrọ-ẹkọ ni ninu jẹ awọn apẹẹrẹ titayọ fun awọn onkọwe ti wọn ṣẹṣẹ bẹrẹ, ti wọn ti wà lẹnu rẹ fun igba diẹ, ati awọn ti wọn ti rin jinna.

“Kii ṣe kiki pe awọn ọrọ-ẹkọ ninu Ji! jẹ adanilaraya ati eyi ti o kun fun ẹkọ nikan ṣugbọn o tun jẹ ti ojulowo gigajulọ ninu girama. Mo nlo wọn lati tọka ilo ami iwe kikọ titọna, awọn akanlo ede, ede afiṣapẹẹrẹ, ati yiyan ọrọ yiyẹ. Anfaani mimọ awọn ọrọ titun ti onkawe nri jẹ ipenija kan nitootọ, sibẹ o tunilara, yatọ si iwe irohin lasan. Aṣeyọrisi rere Ji! funni ni ẹri isapa alaapọn ati afiyesi ti a fifun itẹjade kọọkan.”

Bi iwọ yoo ba fẹ lati gba Ji!, jọwọ kọ ọrọ kún alafo ti o ba a rin yii ki o si fi ranṣẹ fun isọfunni.

Emi yoo fẹ ki ẹ fi isọfunni bi mo ṣe le maa gba iwe irohin Ji! ranṣẹ si ile mi.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́