Atọ́ka Awọn Kókó-ẹ̀kọ́ Ilé-ìṣọ́nà 1991
Tí Ńtọ́ka Ọjọ́ Itẹjade Ninu Eyi Tí Ọrọ-ẹkọ Farahàn
AWỌN ẸLẸ́RÌÍ JEHOFA
Awọn Apejọpọ Agbegbe Èdè Mímọ́gaara, 1/15
Ayọ̀ Yíká Ilẹ̀-ayé, 1/1
Bawo Ni Awa Ṣe Le San Asanpada Fun Jehofa? 12/1
Fífún Irugbin Ijọba Ni Iha Guusu Chile, 5/15
Ìfaradà Aláyọ̀ ní Agbedeméjì Ìlà-oòrùn (Lebanon), 1/1
Igboyejade Gilead, 6/1, 12/1
Ihinrere Dé Awọn Igberiko South Africa, 11/15
Ilepa Ìdásílẹ̀ ní Senegal, 8/15
Iṣẹ-ojiṣẹ Kan Fun Ọ Bi? 12/15
Iwakiri Araye Fun Ọlọrun (Iwe), 4/1
Jíjẹ́rìí Ni France—Ilẹ Ọlọ́kankòjọ̀kan, 6/15
Kikore Ni Brazil, 9/15
“Lati Ile de Ile,” 8/1
Mímú Ìmọ́lẹ̀ Wá Sí Ibi Jíjìnnà Ni Bolivia, 2/15
Orílẹ̀-èdè Aláyọ̀, 1/1
Pipolongo Ihin Rere Ni “Ilu Polynesia” Ti New Zealand, 3/15
Soviet Union, 7/15
AWỌN ÌTÀN IGBESI-AYE
‘Alayọ Ni Gbogbo Awọn Wọnni Ti Nduro De Jehofa’ (D. Piccone), 10/1
Ayọ Lati Jokoo Nidii Tabili Jehofa! (E. Wauer), 8/1
Ẹ Maa Baa Lọ Ni Fífúnrúgbìn—Jehofa Yoo Si Mu Ibisi Wa (F. Metcalf), 5/1
‘Fifunrugbin Pẹlu Omije, Kikarugbin Pẹlu Igbe Ayọ’ (M. Idei), 9/1
Gẹgẹ Bi Opó Kan, Mo Rí Ìtùnú Tootọ (L. Arthur), 2/1
‘Gbigbe Pẹlu Isunmọle Ọjọ Jehofa Ni Ọkan’ (L. Reusch), 7/1
Idi Ọpẹ́ Mi Ti Pọ Lọpọlọpọ Tó! (L. Hall), 3/1
‘Jehofa Ni Ọlọrun Mi, Ninu Ẹni Ti Emi Yoo Nigbẹkẹle’ (W. Diehl), 11/1
Rírọ̀ Timọtimọ Mọ Eto-ajọ Ọlọrun (R. Ryan), 12/1
AWỌN OLUPOKIKI IJỌBA ROHIN
1/1, 2/1, 3/1, 4/1, 5/1, 6/1, 7/1, 8/1, 9/1, 10/1, 11/1
BIBELI
Iwe Akajọ Òkun Òkú, 4/15
New World Translation—Fi Ijinlẹ Ẹ̀kọ́ Hàn Kò Fi Otitọ Pamọ, 3/1
O Ha Jẹ Mimọ Nitootọ Bi? 6/1
O Ha Ti Ọdọ Ọlọrun Wa Bi? 6/1
Ṣiṣayẹwo Awọn Apa-iha, 6/15
1 Tẹsalonika, 1/15
2 Tẹsalonika, 1/15
1 Timoti, 1/15
2 Timoti, 1/15
Titu, 2/15
Filemoni, 2/15
Heberu, 2/15
Jakọbu, 3/15
1 Peteru, 3/15
2 Peteru, 3/15
1 Johanu, 4/15
2 Johanu, 4/15
3 Johanu, 4/15
Juuda, 4/15
Iṣipaya, 5/1
IBEERE LATI ỌWỌ́ AWỌN ONKAWE
A fi awọn Angẹli han pẹlu iyẹ, 3/1
Awọn ọmọ ẹhin inu Johanu 18:15 ati Maaku 14:51, 52 ha jẹ́ ọkannaa bi? 4/1
Eeṣe ti o fi jẹ pe awọn apọsiteli nikan ni wọn wà nibi Iṣe iranti akọkọ? 7/15
Esteri ha ni ìbálòpọ̀ takọtabo oníwà pálapàla pẹlu ọba bi? 1/1
Ifajẹsinilara tí ile-ẹjọ fi aṣẹ si, 6/15
“Ikoko yoo gbé pọ fun igba diẹ pẹlu akọ ọdọ agutan” kẹ̀? 9/15
Irapada fun Joobu (Joobu 33:24), 2/15
Itọni Isin Ti O Jẹ́ Kàn-ńpá, 12/15
“Mọ iwa agbo ẹran” (Owe 27:23), 8/1
Ododo ìsìnkú, 10/15
Ohun ọṣọ, eroja ìṣaralóge, 6/1
Onkọwe Bibeli wo ni o jẹ ọgagun? 3/15
“Rere” ti Pọọlu ko le ṣe (Roomu 7:19), 9/1
Ta ni awọn arakunrin nipa tẹmi ti a nilọkan ni Matiu 10:21? 5/15
29 C.E. deeti pataki kan, 11/15
IGBESI-AYE ATI AWỌN ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
A Mú Ọwọ́ Dí Jọjọ Pẹlu Ihinrere Naa, 7/1
Bawo Ni Awa Ṣe Lè San Asanpada Fun Jehofa? 12/1
Eeṣe Ti A Fi Nilati Gbé Irẹlẹ Wọ̀? 7/15
“Ẹ Maṣe Maa Mu Awọn Ọmọ Yin Binu,” 10/1
‘Ẹ Mú Gbogbo Ẹrù Wiwuwo Kuro,’ 10/15
Ẹyin Ọdọ—Ẹ Duro Gbọnyingbọnyin Ninu Igbagbọ, 7/15
Ẹyin Ọdọ—Ẹyin Yoo Ha Yege Idanwo Iduroṣinṣin Kristian Bi? 6/15
Fi Ọlọrun Ṣe Akọkọ Ninu Igbesi-aye Idile! 5/15
Gbigbe Awọn Animọ Iwa Kristian Ró Ninu Awọn Ọmọ, 7/1
Inututu, 2/15
Iṣẹ-ojiṣẹ Kan Fun Ọ Bi? 12/15
Iṣẹ Ọkunrin (Efe. 6:4), 9/1
Itẹriba Ninu Igbeyawo, 12/15
Iwọ Ha Mọriri Eto-ajọ Jehofa Ori Ilẹ-aye Bi? 11/1
Iwọ Ha Ńsẹ́ Awọn Itẹsi Ti Wọn Kún Fun Ẹṣẹ Bi? 8/15
Iwọ Ha Le Layọ Pẹlu Pupọ Lati Ṣe Bi? 5/15
Ki Ni O Nfa Idaamu Idile? 5/15
Kọkọrọ sí Isin Kristẹni Tootọ 10/1
Ṣiṣiro Ohun Ti Ṣiṣilọ Sí Ilẹ Ọlọrọ Yoo Náni, 4/1
Yíyá Awọn Kristẹni Ẹlẹgbẹ Wa Lówó, 10/15
IGBESI-AYE ATI IṢẸ́-ÒJÍṢẸ́ JESU
1/1, 1/15, 2/1, 2/15, 3/1, 3/15, 4/1, 4/15, 5/1, 5/15, 6/1
JEHOFA
“Akin Ọkunrin Ogun,” 8/15
Jehofa ati Kristi—Awọn Olubanisọrọpọ Ti Wọn Gba Ipo Iwaju Julọ, 9/1
JESU KRISTI
Àríyànjiyàn Lori Ikú Jesu, 2/15
Bawo Ni O Ṣe Jẹ́ Wolii Kan Bii Mose? 11/15
Bi Ipalarada Ṣe Nipa Lori Rẹ, 9/15
Irapada—Ẹkọ-igbagbọ Kristẹndọm Tí Ó Ti Sọnu, 2/15
Jehofa ati Kristi—Awọn Olubanisọrọpọ Ti Wọn Gba Ipo Iwaju Julọ, 9/1
Òpó-igi Idaloro, 2/15
LÁJORÍ AWỌN Ọ̀RỌ̀ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
“Alaboojuto Kan Nilati Jẹ́ Ẹni Ti . . . Nko Ara Rẹ̀ Nijaanu,” 11/15
“A Rà Yín Pẹlu Iye-owo Kan,” 2/15
“Awọn Obinrin Ti Wọn Nṣiṣẹ Kára Ninu Oluwa,” 7/1
Awọn Ọmutipara Nipa Tẹmi—Ta Ni Wọn Íṣe? 6/1
Bi Awọn Ọlọkantutu Ti Jẹ́ Alayọ Tó! 10/15
Bọla Fun Jehofa—Eeṣe ati Bawo? 2/1
Bọla Fun Oriṣi Eniyan Gbogbo, 2/1
Bọla Fun Ọmọkunrin Naa, Olori Aṣoju Jehofa, 2/1
Èdè Mímọ́gaara Fun Gbogbo Orilẹ-ede, 4/1
Ẹ Duro Pẹkipẹki Ti Jehofa, 12/15
Ẹ Fi Iwapẹlẹ Wọ Araayin Ni Aṣọ! 10/15
“Ẹ Gbé Awọn Ohun Ija Imọlẹ Wọ̀,” 8/1
Ẹ Jẹ Ki “Alaafia Ọlọrun” Maa Daabobo Ọkan-aya Yin, 3/1
Ẹ Kún Fun Ayọ, 1/1
Ẹ Maa Baa Niṣo Ni Ṣiṣekilọ Àràmàǹdà Iṣẹ Jehofa, 6/1
Ẹ Maa Kọni Ni Gbangba Ati Lati Ile De Ile, 1/15
Ẹ Maa Lepa Iṣeun-ifẹ Nigba Gbogbo, 7/15
Ẹ Ni Ipamọra Fun Gbogbo Eniyan, 5/15
Ẹ Rin Gẹgẹ Bi Jehofa Ti Fun Yin Ni Itọni, 6/15
“Ẹ Wa Alaafia Ki Ẹ Si Maa Lepa Rẹ̀,” 3/1
Ẹ Wa Awọn Wọnni Tí Wọn Ní Ìtẹ̀sí-ọkàn Lọna Títọ́ Fun Ìyè Àìnípẹ̀kun, 1/15
Ẹ Wà Ni Iṣọkan Nipasẹ Èdè Mímọ́gaara Naa, 5/1
Ẹ Yọ̀ Ninu Ireti Ijọba Naa! 12/15
Fi Awọn Apa Jehofa Wiwa Titilae Ṣe Itilẹhin Rẹ, 10/1
Fifi Ẹ̀jẹ̀ Gba Ẹ̀mí Là—Bawo? 6/15
Gbé Awọn Àwòkọ́ṣe Ipamọra Yẹ̀wò, 5/15
Ibi Ìsádi Wọn—Irọ́ Ni! 6/1
Ifarada Tí Ó Jèrè Ìjagunmólú, 11/1
Ijumọsọrọpọ Ninu Iṣẹ-ojiṣẹ Kristẹni, 9/1
Ikora-ẹni-nijaanu—Eeṣe Ti O Fi Ṣe Pataki Tobẹẹ? 11/15
“Imọlẹ Ti Wá Sinu Aye,” 8/1
Ipa Tí Obinrin Kó Ninu Iwe Mimọ, 7/1
Irapada Tí Ó Dọ́gba Rẹ́gí Fun Gbogbo Eniyan, 2/15
Iwọ Yoo Ha Ṣafarawe Aanu Ọlọrun Bi? 4/15
Jehofa ati Kristi—Awọn Olubanisọrọpọ Ti Wọn Gba Ipo Iwaju Julọ, 9/1
Jija Àjàbọ́ Kuro Ninu Isin Èké, 12/1
Jijumọsọrọpọ Laaarin Idile ati Ninu Ijọ, 9/1
Kẹkẹ-ẹṣin Òkè Ọ̀run Ti Jehofa Wa Lori Ìrìn, 3/15
Lo Igbagbọ Ti A Gbekari Otitọ, 9/15
Maa Ṣísẹ̀rìn Ní Ìyára Kan Naa Pẹlu Kẹkẹ-ẹṣin Òkè Ọ̀run Ti Jehofa, 3/15
Mímú Eso Ikora-ẹni-nijaanu Dàgbà, 11/15
Mimu “Gbogbo Oniruuru Iwarere Iṣeun” Jade, 8/15
Mú Inu Jehofa Dùn Nipa Fifi Inurere Han, 7/15
Ni Igbẹkẹle Ninu Apa Igbala Jehofa, 10/1
Nisinsinyi Ni Akoko Naa Lati Wá Jehofa, 4/1
Ọpọ Yanturu Iwarere Iṣeun Jehofa, 8/15
“Ran Mi Lọwọ Nibi Ti Mo Ti Nilo Igbagbọ!” 9/15
Sisa Eré-ìje Naa Pẹlu Ifarada, 11/1
Sọ Èdè Mímọ́gaara Naa Ki O Si Walaaye Titilae! 5/1
Ṣafarawe Aanu Ọlọrun Lonii, 4/15
Ṣiṣe Isin Mimọgaara fun Lilaaja, 12/1
Ṣíṣiṣẹ́sìn Jehofa Pẹlu Ayọ̀, 1/1
Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN
A Ha Pinnu Ọjọ-ọla Nipasẹ Àyànmọ́ Bi? 10/15
Alaafia Aye Ha Wà Ni Ojutaye Bí? 4/15
Ariyanjiyan Nla, 3/1
‘Awọn Àjàkálẹ̀-àrùn Lati Ibikan Sí Ibomiran,’ 11/15
Awọn Apejuwe—Kọkọrọ Kan Si Dide Inu Ọkan-aya, 9/15
Aye Titun Sunmọle! 7/15
Balogun Ọ̀rún Ara Roomu Oninuure, 11/15
Bawo Ni Iwọ Ṣe Mọ Bibeli Daradara To? 1/15
Bi Ẹmi Ọlọrun Ṣe Le Nipalori Rẹ, 1/15
Dida Ẹmi Mimọ Mọyatọ, 1/15
Eeṣe Ti A Fi Nilati Fọwọ́ Pataki Mu Isin? 2/1
Eeṣe Ti Ọlọrun Fi Mú Suuru Tóbẹ́ẹ̀? 10/1
“Eyi Ni Ara Mi,” 1/15
Ẹ̀san Ha Ṣàìtọ́ Bi? 11/1
Idajọ Ikẹhin, 8/1
Ifọkansin Fun Awọn Ohun Iranti, 11/15
Ijakadi Lodi Si Aisan ati Iku, 6/15
Ijẹwọ Awọn Ẹṣẹ, 3/15
Ijọsin Yèyé Abo-Ọlọrun, 7/1
Ilera ati Ayọ, 8/15
Imọ Ijinlẹ Ha Fihan Pe Irọ́ Ni Iṣẹ Iyanu Bí? 10/1
Ipo Poopu—Kristi Ni Ó Ha Dá a Silẹ Bi? 10/15
Isin Eyikeyii Ha Dara Tó Bi? 12/1
Isin Ha Pọndandan Nitootọ Bi? 12/1
Isin—Ki ni O Fa Àìnífẹ̀ẹ́ Si i? 2/1
Iṣelu—O Ha Jẹ́ Apakan Iṣẹ́ Ihinrere Ti a Fi Ran Ni Bí? 4/1
Itumọ Adura, 7/15
“Ìwérí Ọba ati Ìkéde-ẹ̀rí,” 2/1
“Iwọ Yoo Wà Pẹlu Mi ni Paradise,” 10/15
Jehofa Ńgbọ́ Igbe Wa Kanjukanju fun Iranlọwọ, 5/15
Jesu, Awọn Ọmọ-ẹhin Ha Fi Mẹtalọkan Kọni Bi? 11/1
Keresimesi—Eeṣe Tí O Fi Gbajumọ Tobẹẹ? 12/15
Keresimesi—Ó Ha Jẹ Ọna Lati Kí Jesu Kaabọ Bi? 12/15
Kikoju Iwa Ọdaran, 5/1
‘Ki Ni Akoko Wí?’ 8/1
Laipẹ Ko Ni Si Aisan Tabi Iku Mọ! 6/15
Nigba Wo Ni Alaafia Yoo De? 4/15
Oju-iwoye Bibeli Nipa Alaafia ati Ailewu, 9/1
Ọjọ Ẹ̀san Ọlọrun, 11/1
Ọjọ Idajọ, 8/1
“Ọjọ Oluwa,” 4/15
Ọlọrun Ndahun Awọn Adura Rẹ Bi? 9/15
Ọ̀nà Dídíjú Lati Dé Ọdọ Ọlọrun, 2/15
“Sibẹ Ó Ńyí!” (Galileo), 12/15
Sunmọ Ju Bi O Ti Rò Lọ Bí? 4/1
Ta Ni Ó Ní Ìpè Ti Ọ̀run? 3/15