ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w92 1/1 ojú ìwé 32
  • Iwọ Yoo Ha Gba Ìkésíni Bi?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Iwọ Yoo Ha Gba Ìkésíni Bi?
  • Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1992
Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1992
w92 1/1 ojú ìwé 32

Iwọ Yoo Ha Gba Ìkésíni Bi?

Ani ninu ayé onidaamu yii, iwọ lè jere ayọ lati inu ìmọ̀ Bibeli pipeye nipa Ọlọrun, Ijọba rẹ̀, ati ète agbayanu rẹ̀ fun araye. Bi iwọ yoo bá fẹ́ lati gba isọfunni siwaju sii tabi fẹ́ lati jẹ́ ki ẹnikan ké si ọ lati dari ikẹkọọ Bibeli inu ile lọfẹẹ pẹlu rẹ, jọwọ kọwe si Watch Tower, P.M.B. 1090, Benin City, Edo State, tabi si adirẹsi ti ó ṣe wẹ́kú ti a tò si oju-iwe 2.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́