Iwọ Yoo Ha Gba Ìkésíni Bi?
Ani ninu ayé onidaamu yii, iwọ lè jere ayọ lati inu ìmọ̀ pipeye ninu Bibeli nipa Ọlọrun, Ijọba rẹ̀, ati ète agbayanu rẹ̀ fun aráyé. Bi iwọ yoo bá fẹ́ lati gba isọfunni siwaju sii tabi bi iwọ yoo bá fẹ́ ki ẹnikan késí ọ lati dari ikẹkọọ Bibeli inu ile lọfẹẹ pẹlu rẹ, jọwọ kọwe si Watch Tower, P.M.B. 1090, Benin City, Edo State, tabi si adirẹsi ti ó ṣe wẹ́kú ti a tò si oju-iwe 2.