Atọ́ka Àwọn Kókó-ẹ̀kọ́ Fún Ilé-ìṣọ́nà 1993
Tí ń tọ́ka ọjọ́ ìtẹ̀jáde nínú èyí tí ọ̀rọ̀-ẹ̀kọ́ fárahàn
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JEHOFA
Àwọn Àpéjọpọ̀ Àgbègbè “Àwọn Olùtan Ìmọ́lẹ̀” 1/15
Àwọn Àpéjọpọ̀ Àgbègbè “Ẹ̀kọ́ Àtọ̀runwá,” 6/1
Àwọn Ìpèsè Ìrànlọ́wọ́ Fi Ìfẹ́ Kristian Hàn (Russia, Ukraine), 2/1
Àwọn Òjíhìn-Iṣẹ́-Ọlọ́run ní Micronesia, 3/1
“Àwọn Olùpòkìkí Ìjọba” Rìn Lórí Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Omi Guyana, 4/1
Fífi Ìfaradà Wàásù ní Ilẹ̀ Yìnyín àti Iná (Iceland), 9/15
Ìkẹ́kọ̀ọ́yege Gileadi, 12/1
Ilé-Ẹjọ́ Gíga ti Europe Gbèjà Ẹ̀tọ́ Láti Wàásù ni Greece, 9/1
Ilé-ẹ̀kọ́ Gilead Pé 50 Ọdún Ó Sì Ń Ṣaṣeyọrí! 6/1
Irú Àwárí Yíyàtọ̀ kan (Bahamas), 3/15
Jehofa Ń Dáàbòbo Àwọn Ènìyàn Rẹ̀ ní Hungary, 7/15
Jehofa Yí Àkókò àti Ìgbà Padà ní Romania, 6/15
Máa Báa Lọ Nínú Iṣẹ́-Ìsìn Aṣáájú-Ọ̀nà, 9/15
Ó Jà fún Ìgbàgbọ́ Rẹ̀ (C. Bazán Listán), 6/15
Ọlọrun Kò Gbàgbé “Ìfẹ́ tí Ẹ̀yin Fihàn” (Ìlà-Oòrùn Europe), 1/1
Rírí Ọrọ̀ Tòótọ́ ní Hong Kong, 5/15
Wíwàásù Láti Abúlé dé Abúlé ní Spain, 11/15
Wíwàásù ní Ilẹ̀ Onírúurú Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ (Australia), 10/15
ÀWỌN ÌTÀN ÌGBÉSÍ-AYÉ
A Fi “Adé Ìyè” San Èrè fun Un (F. Franz), 3/15
Didagbasoke Pẹlu Eto-Ajọ Jehofa ni South Africa (F. Muller), 4/1
“Emi Niyi; Rán Mi” (W. John), 5/1
Jehofa, Igbẹkẹle Mi Lati Ìgbà Èwe Wá (B. Tsatos), 8/1
Jehofa Pa Iwalaaye Mi Mọ́ Ninu Ọgbà-Ẹ̀wọ̀n Aṣálẹ̀ Kan (I. Mnwe), 3/1
Mo Kún fún Ìmoore fún Itilẹyin Jehofa Tí Kìí Kùnà (S. Gaskins), 6/1
Mo Rí Itẹlọrun Ninu Ṣiṣiṣẹsin Ọlọrun (J. Thongoana), 2/1
Ogún-Ìní Ṣíṣọ̀wọ́n ti Kristian Kan (B. Brandt), 10/1
Ṣíṣiṣẹ́sìn Pẹ̀lú Òye Ìmọ̀lára Ìjẹ́kánjúkánjú (H. van Vuure), 11/1
Títẹ Iwe-Ikẹkọọ Bibeli Nigba Ti A Wà Labẹ Ifofinde (M. Vale), 7/1
ÀWỌN OLÙPÒKÌKÍ ÌJỌBA RÒYÌN
2/1, 3/1, 5/1, 7/1, 8/1, 10/1, 11/1
BIBELI
A Ha Nílò Bibeli Bí? 5/1
Atọ́nà Gbígbéṣẹ́ fún Ènìyàn Òde-Òní, 5/1
Àwọn Ìsọtẹ́lẹ̀ Bibeli, 5/15
Ẹ̀kọ́ Bibeli Nípa Ìrísí Ojú-Ilẹ̀, 6/15
Ọ̀rọ̀-Ìtàn Bibeli, 6/1
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Àwọn aláìgbàgbọ́ tí ó kú ṣáájú ìpọ́njú ńlá, 5/15
Àwọn Kristian àti ìbàyíkájẹ́, 1/1
Bí a kò bá rí olùbáṣègbéyàwó, 1/15
Fífi owó kọ́ iyàn, 6/15
“Johannu Baptisi” tàbí “Johannu Arinibọmi”? 8/1
Kò lè wá síbi Ìṣe-ìrántí, 2/1
Melkisedeki ha wà “láìní ìlà ìdílé” bí? (Heb 7:3), 11/15
“Ní ẹ̀bùn ẹ̀mí” (1Kor 14:37), 10/15
O ha níláti da òwò pọ̀ pẹ̀lú aláìgbàgbọ́ kan bí? 10/1
Paulu ha fi ìwàláàyè rẹ̀ lélẹ̀ fún àwọn Ju bí? (Ro 9:3), 9/15
ÌGBÉSÍ-AYÉ ÀTI ÀWỌN ÀNÍMỌ́ KRISTIAN
Àwọn Kristian Ha Ń Pa Ọjọ́ Ìsinmi Mọ́ Bi? 2/15
Bí A Ṣe Lè Mú Ìdè Ìgbéyàwó Lókun Síi, 8/15
Bí Àwọn Kristian Ṣe Lè Ran Àwọn Àgbàlagbà Lọ́wọ́, 8/15
Bíbójútó Àwọn Arúgbó, 2/15
Èéṣe Tí O fi Níláti Gba Àṣìṣe? 11/15
Èéṣe Tí O Fí Níláti Lọ sí Àwọn Ìpàdé Kristian? 8/15
Èéṣe Tí O Fi Níláti Ṣiṣẹ́sin Jehofa? 5/15
Ẹ Jẹ́ Aláyọ̀ Kí Ẹ Sì Wà Létòlétò, 4/1
‘Ẹ Wá Jehofa, Gbogbo Ẹ̀yin Onínútútù,’ 12/15
Fífi Jẹ̀lẹ́ńkẹ́ Bójútó Àwọn Àgùtàn Ṣíṣeyebíye ti Jehofa, 7/15
Ìfẹ́ Aládùúgbò, 9/15
Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀pọ̀—Ju Kìkì Ọ̀rọ̀ Sísọ Lásán Lọ, 8/1
Ìlànà Tàbí Ìgbajúmọ̀—Èwo ni? 10/1
Ìrètí—Ìdáàbòbò Ṣíṣekókó, 4/15
Ìwọ Ha Bọ̀wọ̀ fún Ibi Ìjọ́sìn Rẹ Bí? 6/15
Ìwọ Ha Ń Ṣe Gbogbo Ohun Tí O Lè Ṣe Bí? 4/15
Ìwọ Ha Ń Tọ Jehofa Lẹ́yìn Lẹ́kùn-ún-rẹ́rẹ́ Bí? 5/15
Jehofa Ń Rántí Àwọn Aláìsàn, Àwọn Àgbàlagbà, 8/1
Jíjẹ́ kí Ojú “Mú Ọ̀nà Kan” Nínú Iṣẹ́ Ìjọba, 12/15
Kíkẹ́kọ̀ọ́ Láti Dúró, 10/15
Kọ́kọ́rọ́ sí Ìgbésí-Ayé Ìdílé Aláṣeyọrísírere, 10/1
Ní Ojú-Ìwòye Títọ̀nà Nípa Àánú Ọlọrun, 10/1
Ògo-Ẹwà Orí-Ewú, 3/15
Olùfúnni ní “Gbogbo Ẹ̀bùn Rere,” 12/1
Ọlọrun Ń Mú Kí Ó Dàgbà—Ìwọ Ha Ń Kó Ipa Tìrẹ Bí? 3/1
Wọ́n Ń Fi Ìyọ́nú Ṣolùṣọ́ Àwọn Àgùtàn Kékeré Náà, 9/15
ÌRÍSÍ ÌRAN LÁTI ILẸ̀ ÌLÉRÍ
Beerṣeba, 7/1
Ẹ Yọ̀! Àwọn Ẹkù náà Kún fun Òróró ni Àkúnwọ́sílẹ̀, 3/1
Gerisimu, 1/1
Gileadi, 9/1
Òkun Galili, 11/1
Sinai—Oke Mose ati Àánú, 5/1
JEHOFA
Atóbilọ́lá Ẹlẹ́dàá Wa àti Àwọn Iṣẹ́ Rẹ̀, 1/1
Àwọn Ìṣe Ìgbàlà Jehofa Nísinsìnyí, 12/1
Àwọn Kristian Ìjímìjí Ha Lo Orúkọ Ọlọrun Bí? 11/1
Jehofa—Ọlọrun Òtítọ́ àti Alààyè, 7/15
Mímú Àdììtú Orúkọ Títóbilọ́lá Jùlọ náà Ṣe Kedere, 11/1
Olùfúnni ní ‘Gbogbo Ẹ̀bùn Rere,’ 12/1
Orúkọ Ọlọrun, 12/1
Ta Ni Jehofa? 7/15
JESU KRISTI
A Ha Bí I Ní Ìgbà Òjò-Dídì Bí? 12/15
LÁJORÍ ÀWỌN Ọ̀RỌ̀ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Àánú Jehofa Ń Gbà Wá Là Kuro Ninu Ainireti, 3/15
Aláyọ̀ ni Àwọn Onírẹ̀lẹ̀-Ọkàn, 12/1
Àwọn Àpẹẹrẹ Ìrẹ̀lẹ̀-Ọkàn Láti Ṣàfarawé, 12/1
Àwọn Ìdílé Kristian Máa Ń Ṣe Nǹkan Papọ̀, 9/1
Àwọn Ìdílé Kristian Ń Fi Àwọn Ohun Tẹ̀mí Sí Ipò Àkọ́kọ́, 9/1
Àwọn Ìdílé Kristian Ń Ran Àwọn Àgbàlagbà Lọ́wọ́, 9/1
Awọn Igbokegbodo Ti A Mú Gbooro Sii Nigba Wíwàníhìn-ín Kristi, 5/1
Awọn Kristian ati Ẹgbẹ́ Awujọ Eniyan Lonii, 7/1
Àwọn Olùtan Ìmọ́lẹ̀—Fun Ète Wo? 1/15
Àwọn Ọjọ́ Alásọtẹ́lẹ̀ Danieli àti Ìgbàgbọ́ Wa, 11/1
Àwọn Wo Ni Wọn Ń Tẹle Ìmọ́lẹ̀ Ayé? 4/1
Bawo Ni A Ṣe Lè Fi Iwafunfun Kún Igbagbọ Wa? 7/15
Dahunpada si Awọn Ileri Ọlọrun Nipa Lilo Igbagbọ, 7/15
Eeṣe Ti A Fi Nilati Ṣọra fun Ibọriṣa? 1/15
Ẹ Fi Ìfọkànsìn Oníwà-bí-Ọlọ́run kún Ìfaradà Yín, 9/15
Ẹ Fi Imuratan Bojuto Agbo Ọlọrun, 5/15
Ẹ Gbẹ́kẹ̀lé Jehofa! 12/15
Ẹ Jẹ́ Ẹni Ti A Yipada Ni Ero-Inu Ti A Sì Làlóye Ni Ọkan-Aya, 3/1
Ẹ Jẹ́ Ki Ikora-Ẹni-Nijaanu Yin Wà Ki Ó Sì Kún Àkúnwọ́sílẹ̀, 8/15
Ẹ Maa Baa Lọ ni Didagba Ninu Ìmọ̀, 8/15
“Ẹ Maa Baa Lọ Ní Rírìn Gẹgẹ Bi Àwọn Ọmọ Ìmọ́lẹ̀,” 3/1
Ẹ Ní Ìgboyà Dáradára! 11/15
Ẹ Ṣọra fun Àwọn Orin Ti Kò Sunwọn! 4/15
Ẹ Ṣọra fun Gbogbo Oniruuru Ibọriṣa, 1/15
Ẹ Tẹle Ìmọ́lẹ̀ Ayé Naa, 4/1
Ẹ Yèkooro Ní Ero-Inu—Opin Ti Sunmọle, 6/1
Ẹyin Èwe—Kí Ni Ẹyin Ń Lépa? 4/15
Fifi Ẹmi Ifara-Ẹni-Rubọ Ṣiṣẹsin Jehofa, 6/1
Fi Tìgboyà-Tìgboyà Rìn Ní Àwọn Ọ̀nà Jehofa, 11/15
Idande Lakooko Ifarahan Jesu Kristi, 5/1
Ìfaradà—Ṣekókó fún Àwọn Kristian, 9/15
Ìfẹ́ (Agape)—Ohun Tí Kò Jẹ́ àti Ohun tí Ó Jẹ́, 10/15
Ìjagunmólú Ìkẹyìn ti Mikaeli, Balógun Ńlá Náà, 11/1
Iṣẹda Sọ Pe, ‘Wọn Wà Ní Àìríwí,’ 6/15
Itẹriba Oniwa-bi-Ọlọrun—Eeṣe ati Lati Ọwọ́ Ta Ni? 2/1
Jehofa Kò Gan Ọkàn Ìròbìnújẹ́, 3/15
‘Késí Àwọn Àgbà Ọkunrin,’ 5/15
“Ki Igbeyawo Ki O Ní Ọlá Laaarin Gbogbo Eniyan,” 2/15
Maṣe Jẹ́ Ki Ẹnikẹni Ba Ìwà Rere Rẹ Jẹ́, 8/1
Mímú Animọ-Iwa Titun Dagba Ninu Igbeyawo, 2/15
Mímú Ìbẹ̀rù Oníwà-bí-Ọlọ́run Dàgbà, 12/15
Mọ Jehofa Nípasẹ̀ Ọ̀rọ̀ Rẹ̀, 6/15
Ohun ti Itẹriba Oniwa-bi-Ọlọrun Ń Beere Lọwọ Wa, 2/1
Ọba kan Sọ Ibùjọsìn Jehofa Di Aláìmọ́, 11/1
Ọlọrun Ha Mọ̀ Ọ́ Níti Gidi Bí? 10/1
“Ọlọrun, Wádìí Mi,” 10/1
Rírìn Pẹlu Ọgbọ́n Sipa Ti Ayé, 7/1
Ṣaṣeyọri Ninu Yiyẹra fun Ìdẹkùn Ìwọra, 8/1
Ṣíṣàwárí Kọ́kọ́rọ́ Náà sí Ìfẹ́ni Ará, 10/15
Ṣíṣe Oluṣọ-agutan Pẹlu Atobilọla Ẹlẹdaa Wa, 1/1
Títan Ìmọ́lẹ̀ Sori Wíwàníhìn-ín Kristi, 5/1
Yíyọ̀ Ninu Atobilọla Ẹlẹdaa Wa, 1/1
Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN
A Ha Pọ́n Ìfàjẹ̀sínilára Ju Bi Ó ti Yẹ Lọ Bí? 10/15
A Ó Ha Gbà Ọ́ Lọ Soke Ọrun Bi? 1/15
A Ṣẹ́gun “Ọ̀tá Ìkẹyìn”! 11/15
Aásìkí Lè Dán Igbagbọ Rẹ Wò, 7/15
Àwọn Aworan Isin, 4/15
Àwọn Ìjábá ti Ẹ̀dá, 12/1
Awọn Iṣẹda Titun Ni A Mú Jade! 1/1
Àwọn Kristian Ijimiji ati Ayé, 7/1
Àwọn Oògùn Oríire, 9/1
Báwo ni Ìwọ Ṣe Lè Wàláàyè Pẹ́ Tó? 11/15
Bí Kristẹndọm Ṣe Di Apakan Ayé Yii, 7/1
Ìfẹ Owó, 2/15
Ìjáfara Léwu! 3/1
Ìmukúmu-Ọtí, 8/15
Ìpalẹ̀-Ìdọ̀tí-Mọ́ Kari-Aye, 2/15
Ìpín Aláròyé Kìí Ṣe Ọ̀kan Ti Ó Jẹ́ Alayọ, 3/15
Ire Yoo Ha Bori Ibi Lae Bi? 2/1
Iwọ Ha Nilati Gba Iribọmi Bi? 4/1
Ki Ni Ó Beere fun Lati Mú Ọ Layọ? 6/1
Kò Sí Èrò Nípa Jijuwọ́sílẹ̀! (Àwọn Kristian Ìjímìjí), 11/15
Mẹ́talọ́kan—A Ha Fi Kọ́ni Nínú Bibeli Bí? 10/15
Olè Jíjà Yóò Ha Dópin Láé Bí? 10/15
Oúnjẹ Alẹ́ Oluwa, 3/15
Ọpa-Alade Pomegranate, 4/15
Ọrun-Apaadi, 4/15
Papias Ka Àwọn Ọ̀rọ̀ Oluwa sí Iyebíye, 9/15
Rahabu—A Polongo Rẹ̀ Ní Olódodo Nípa Àwọn Iṣẹ́ Ìgbàgbọ́, 12/15
Ṣe Iribọmi! Ṣe Iribọmi! Ṣe Iribọmi!—Ṣugbọn Eeṣe? 4/1
Ṣọọṣi Latin-America Ninu Idaamu, 6/15
Tábà ati Awujọ-alufaa, 2/1
Yẹra fun Ẹmi Ìgbéraga! 5/15