ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w98 3/15 ojú ìwé 31-32
  • Jọ̀wọ́ Dara Pọ̀ Mọ́ Wa Fún Ìṣẹ̀lẹ̀ Àkànṣe kan Ní Saturday, April 11, 1998

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jọ̀wọ́ Dara Pọ̀ Mọ́ Wa Fún Ìṣẹ̀lẹ̀ Àkànṣe kan Ní Saturday, April 11, 1998
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1998
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1998
w98 3/15 ojú ìwé 31-32

Jọ̀wọ́ Dara Pọ̀ Mọ́ Wa Fún Ìṣẹ̀lẹ̀ Àkànṣe kan Ní Saturday, April 11, 1998

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ fi ayọ̀ ké sí ọ láti wá bá wọn ṣèrántí ẹ̀bùn tí Ọlọ́run fi fúnni, Jésù Kristi Ọmọ rẹ̀. Ẹ̀bùn yìí ni ó ṣí ọ̀nà ìrètí gbígbádùn ìyè àìnípẹ̀kun sílẹ̀ fún aráyé.​—⁠Jòhánù 3:⁠16.

Ní ọdún yìí, a óò ṣe Ìṣe Ìrántí ikú Jésù ní Saturday, April 11, lẹ́yìn tí oòrùn bá wọ̀. Ọjọ́ náà ṣe rẹ́gí pẹ̀lú Nísàn 14 ti kàlẹ́ńdà òṣùpá inú Bíbélì. Jọ̀wọ́ wádìí lọ́dọ̀ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tí ń bẹ ládùúgbò rẹ láti mọ ibi tí a óò ti ṣe é àti àkókò náà gan-⁠an tí yóò wáyé.

O ha ti gbọ́ nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí tí ó wáyé ní àwọn ọjọ́ tí Jésù lò kẹ́yìn lórí ilẹ̀ ayé bí?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́