ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w08 2/15 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
  • Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
w08 2/15 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

February 15, 2008

Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:

March 17-23, 2008

Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Wà Níwájú Rẹ Nígbà Gbogbo

OJÚ ÌWÉ 3

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 37, 26

March 24-30, 2008

Máa Rìn ní Ọ̀nà Jèhófà

OJÚ ÌWÉ 7

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 138, 57

March 31, 2008–April 6, 2008

Jésù Kristi​—⁠Míṣọ́nnárì Tó Ta Yọ

OJÚ ÌWÉ 12

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 172, 72

April 7-13, 2008

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Míṣọ́nnárì Tó Ta Yọ

OJÚ ÌWÉ 16

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 211, 209

April 14-20, 2008

Wíwàníhìn-⁠ín Kristi​​—⁠Báwo Ló Ṣe Yé Ọ Sí?

OJÚ ÌWÉ 21

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 168, 21

Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11

Ṣíṣàṣàrò lórí àwọn ìtàn inú Bíbélì máa ń fún ìgbàgbọ́ wa lókun. Tá a bá ń wo Jèhófà níwájú wa nígbà gbogbo, ó máa dáhùn àwọn àdúrà wa. Àmọ́, a ní láti máa ṣègbọràn sí Ọlọ́run ká sì máa gbẹ́kẹ̀ lé e. Rírìn ní ọ̀nà rẹ̀ máa mú ká jẹ́ ẹni tó ṣeé fọkàn tán, onírẹ̀lẹ̀, onígboyà àtẹni tó ń fi ọ̀ràn àwọn ẹlòmíì sọ́kàn.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 àti 4 OJÚ ÌWÉ 12 sí 20

Jésù Kristi ni Míṣọ́nnárì tó ju gbogbo míṣọ́nnárì lọ. Kọ́ nípa bó ṣe gba ìdálẹ́kọ̀ọ́, bó ṣe kọ́ àwọn míì lẹ́kọ̀ọ́ àtohun tó mú káwọn èèyàn fẹ́ràn rẹ̀. Kọ́ nípa bá a ṣe lè fara wé Jésù àti bá a ṣe lè máa kọ́ àwọn èèyàn lọ́nà tí ìhìn rere náà á fi wọ̀ wọ́n lọ́kàn.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 5 OJÚ ÌWÉ 21 sí 25

Wàá rí ìdí tá a fi lè sọ pé àkókò gígùn ni ìgbà wíwàníhìn Kristi. Ṣàgbéyẹ̀wò àwọn ẹ̀rí tá a rí látinú Ìwé Mímọ́ tó jẹ́ ká mọ àwọn tí Jésù pè ní “ìran yìí.” (Mát. 24:34) Wàá sì rí ìdí tí kò fi ṣeé ṣe láti ṣírò bí “ìran yìí” ṣe máa gùn tó.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:

Fi Àṣìṣe Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́gbọ́n

OJÚ ÌWÉ 26

Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè​—⁠Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Máàkù

OJÚ ÌWÉ 28

Wọ́n Rọ Àwọn Tó Kẹ́kọ̀ọ́ Yege Nílé Ẹ̀kọ́ Gílíádì Pé Kí Wọ́n “Máa Walẹ̀ Jìn”

OJÚ ÌWÉ 31

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́