Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April 1, 2008
Kí Ni Amágẹ́dọ́nì?
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 “Ogun Tó Máa Fòpin sí Gbogbo Ogun”
5 Amágẹ́dọ́nì—Ogun Ọlọ́run Tó Máa Fòpin sí Gbogbo Ogun
9 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ẹni Tó Mọyì Wa Gan-an
17 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn —Ó Ń Ṣọ́nà, Ó sì Ní Sùúrù
21 Àwọn Ará Ilẹ̀ Lìdíà Ayé Ọjọ́un Ṣe Ohun Kan Tó Là Wá Lóye
24 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Tímótì Ti Ṣe tán, Ó sì Wù Ú Láti Sin Jèhófà
26 Ohun Tó Yẹ Ká Mọ̀ Nípa Gbígba Ara Olúwa
32 Ta Lẹni Tó Kúnjú Ìwọ̀n Láti Ṣàkóso Aráyé?
Ǹjẹ́ Ilẹ̀ Ayé Wa Yìí Yóò Pa Run?
OJÚ ÌWÉ 10
Ọmọ Títọ́ Láyé Táwọn Èèyàn Ti Ń Ṣèyí Tó Wù Wọ́n
OJÚ ÌWÉ 13
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
NASA/The Visible Earth (http://visibleearth.nasa.gov/)