Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
June 1, 2008
Ohun Tó Mú Kí Ọlọ́run Gba Nóà Là Ìdí Tó Fi kàn Wá
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Ìkún-Omi Ìgbà Ayé Nóà—Òótọ́ Pọ́ńbélé Ni, Kì Í Ṣe Ìtàn Àròsọ
4 Ohun Tó Mú Kí Nóà Rójú Rere Ọlọ́run—Ìdí Tó Fi Kàn Wá
12 Omi Tó Ń Tú Yàà Sókè Láti Fúnni Ní Ìyè Àìnípẹ̀kun
16 Lẹ́tà Kan Láti Ilẹ̀ Ọsirélíà
22 Ṣé “Orúkọ Tá Ò Gbọ́dọ̀ Pè” Ni?
23 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ẹni Tó Máa Ń Dárí Jini
24 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Ọmọbìnrin Kan Ran Ọkọ Ọ̀gá Rẹ̀ Lọ́wọ́
26 Ọmọbìnrin Kan Tó Ṣe Bí Ọmọdébìnrin Ilẹ̀ Ísírẹ́lì Àtijọ́
27 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
28 Ayọ̀ Mi Ò Lópin Bí Mo Ti Ń Ṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run
Ṣé Bó Ṣe Wù Wá La Ṣe Lè Sin Ọlọ́run?
OJÚ ÌWÉ 9
Lo Ẹ̀mí Ìtọpinpin Rẹ Lọ́nà Tó Tọ́
OJÚ ÌWÉ 18