Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
June 15, 2008
Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
August 4-10
Àwọn Ohun Tá A Gbọ́dọ̀ Máa Sá Fún
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 139, 146
August 11-17
Àwọn Ànímọ́ Tá A Gbọ́dọ̀ Máa Lépa
OJÚ ÌWÉ 11
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 42, 54
August 18-24
OJÚ ÌWÉ 18
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 47, 2
August 25-31
Má Ṣe Jẹ́ Kí ‘Ìfẹ́ Tó O Ní Lákọ̀ọ́kọ́’ Jó Rẹ̀yìn
OJÚ ÌWÉ 22
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 201, 132
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá a Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 7 sí 15
Ó dájú pé Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ wa. Ohun tó jẹ́ ká mọ èyí ni pé, ó sọ ohun mẹ́rin tó yẹ káwọn Kristẹni máa sá fún. Kí làwọn ohun náà, báwo la sì ṣe lè máa sá fún wọn? Bákan náà, Bíbélì sọ ànímọ́ méje tá a gbọ́dọ̀ máa lépa. Kí làwọn ànímọ́ náà, báwo la sì ṣe lè máa lépa wọn?
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 18 sí 22
Ẹ̀mí tinú-mi-ni-màá-ṣe ló kúnnú ayé báyìí. Nítorí náà, báwo la ṣe lè dẹni tó ń fi ojú tó tọ́ wo títẹ̀lé àṣẹ, ní pàtàkì jù lọ àṣẹ Jèhófà? Àpilẹ̀kọ yìí yóò jẹ́ ká mọ bí a ó ṣe ṣe èyí àti bá ò ṣe ní fàyè gba ẹ̀mí tinú-mi-ni-màá-ṣe tí Sátánì ń gbìn sáwọn èèyàn lọ́kàn.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 22 sí 26
Àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí yóò jẹ́ ká lè ṣàyẹ̀wò ìdí tá a fi tẹ́wọ́ gba òtítọ́, tá a sì wá dẹni tó nífẹ̀ẹ́ Jèhófà. Ó tún sọ àwọn ohun tẹ́ni kan lè ṣe láti sọ ìfẹ́ tó kọ́kọ́ ní fún Jèhófà àti fún òtítọ́ dọ̀tun, tó bá ṣẹlẹ̀ pé ìfẹ́ yẹn ti lọ sílẹ̀.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
A Lè Jẹ́ Alágbára Láìfi Àìlera Wa Pè
OJÚ ÌWÉ 3
Ǹjẹ́ O Ti Múra Tán Láti Gbèjà Ìgbàgbọ́ Rẹ?
OJÚ ÌWÉ 16
Ṣé Iná Ọ̀run Àpáàdì Ni Jésù Ní Lọ́kàn?
OJÚ ÌWÉ 27
OJÚ ÌWÉ 28
Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè—Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Róòmù
OJÚ ÌWÉ 29
Ọgbọ́n Táwọn Kan Dá sí Ìṣòro Wọn
OJÚ ÌWÉ 32