Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July 1, 2008
Nígbà Tí Èèyàn Ẹni Bá Kú—Báwo La Ṣe Lè Borí Ẹ̀dùn Ọkàn Wa?
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Bó Ṣe Máa Ń Dunni Tó Nígbà Téèyàn Ẹni Bá Kú
4 Bó O Ṣe Lè Borí Ẹ̀dùn Ọkàn Tí Ikú Fà
10 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Kò Jìnnà sí Ẹnì Kọ̀ọ̀kan Wa”
11 Ṣé Ohun Tó Ò Ń Gbèrò Kò Ta Ko Ìfẹ́ Ọlọ́run?
18 Ran Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Kó Lè Borí Ẹ̀dùn Ọkàn Tí Ikú Fà
21 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
23 Àwọn Ohun Ìṣẹ̀ǹbáyé Ìlú Teli Árádì Ń Jẹ́rìí sí Bíbélì
30 Ǹjẹ́ Ó Dára Kéèyàn Máa Lo Orúkọ Ọlọ́run?
31 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Ẹ̀gbọ́n Bínú sí Àbúrò
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—“Wò Ó! Ẹrúbìnrin Jèhófà!”
OJÚ ÌWÉ 14
OJÚ ÌWÉ 26