Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July 15, 2008
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
September 1-7
Kí Nìdí Tí Iṣẹ́ Ìwàásù Ilé-dé-Ilé Fi Ṣe Pàtàkì Nísinsìnyí?
OJÚ ÌWÉ 3
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 32, 162
September 8-14
Bá A Ṣe Lè Borí Ìṣòro Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù Ilé-dé-Ilé
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 53, 92
September 15-21
OJÚ ÌWÉ 12
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 133, 211
September 22-28
Ìwọ Kò Mọ Ibi Tí Yóò Ti Ṣàṣeyọrí!
OJÚ ÌWÉ 17
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 148, 192
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá a Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11
Ibi gbogbo láyé ni wọ́n ti mọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọ iṣẹ́ ìwàásù ilé-dé-ilé. Nínú àpilẹ̀kọ méjì tó tẹ̀ léra yìí, a óò jíròrò ìdí tá a fi ń lo ọ̀nà ìwàásù yìí lọ́nà tó gbòòrò bẹ́ẹ̀ àti bá a ṣe ń borí àwọn ìṣòro tá à ń bá pàdé lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù ilé-dé-ilé.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 àti 4 OJÚ ÌWÉ 12 sí 21
Àwọn àpilẹ̀kọ yìí dá lórí àwọn àpèjúwe márùn-ún tó ń gbé ìgbàgbọ́ ẹni ró, tí Jésù sọ. Àwọn àlàyé kan nípa rẹ̀ máa ṣàtúnṣe sí òye wa àtẹ̀yìnwá. Àwọn àpilẹ̀kọ yìí máa túbọ̀ jẹ́ ká mọyì agbára ẹ̀mí Ọlọ́run, a ó sì kẹ́kọ̀ọ́ látinú àpèjúwe márùn-ún tó jẹ́ ká rí bí onírúurú ọ̀nà tá a gbà ń wàásù ṣe ń mú ìbísí wá.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Àyà Ò Fò Wá Torí Jèhófà Wà Pẹ̀lú Wa
OJÚ ÌWÉ 22
Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè—Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Kọ́ríńtì Kìíní àti Ìkejì
OJÚ ÌWÉ 26
Láti Lè Máa Láyọ̀, Ohun Tọ́wọ́ Rẹ Lè Tẹ̀ Ni Kó O Fi Ṣe Àfojúsùn Rẹ
OJÚ ÌWÉ 29