Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 1, 2008
Ṣó Yẹ Kó O Máa Bẹ̀rù Ọ̀run Àpáàdì?
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
4 Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Gan-an Sẹ́ni Tó Bá Kú?
5 Kí Ni Jésù Fi Kọ́ni Nípa Ọ̀run Àpáàdì?
8 Báwo Ni Mímọ Òtítọ́ Nípa Ọ̀run Àpáàdì Ṣe Lè Nípa Lórí Rẹ?
10 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ó Fẹ́ràn Ìdájọ́ Òdodo
14 Ìdí Tí Wọ́n Fi Pe Tonílé Tàlejò
16 Ohun Tá A Kọ́ Lọ́dọ̀ Jésù—Nípa Ìrètí Tó Wà Fáwọn Òkú
18 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Bí Tọkọtaya Ṣe Lè Máa Ṣera Wọn Lọ́kan
22 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
24 Ṣé “Ọlọ́run” Ni Ọ̀rọ̀ Náà àbí Ọ̀rọ̀ Náà Jẹ́ “ọlọ́run kan”?
25 “Àwọn Ọkọ̀ Òkun Táṣíṣì” Mú Ọ̀làjú Dé
29 Ṣé orí Àpáta Lò Ń Kọ́lé sí àbí orí Iyanrìn?
Ṣáwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Tú Ìgbéyàwó Ká?
OJÚ ÌWÉ 11
Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Ọ̀rọ̀ Bẹ́yìn Yọ!
OJÚ ÌWÉ 23