ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w08 12/15 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
  • OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
w08 12/15 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

December 15, 2008

Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:

February 2-8

Ìdí Tó Fi Yẹ Kó O Pa Ìwà Títọ́ Rẹ Mọ́

OJÚ ÌWÉ 3

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 10, 160

February 9-15

Ṣé Wàá Pa Ìwà Títọ́ Rẹ Mọ́?

OJÚ ÌWÉ 7

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 26, 29

February 16-22

Mímọyì Ipa Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀ Tí Jésù Kó Nínú Mímú Ìfẹ́ Ọlọ́run Ṣẹ

OJÚ ÌWÉ 12

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 205, 105

February 23–March 1

Wọ́n Pinnu Láti Jẹ́rìí Kúnnákúnná sí Ìhìn Rere

OJÚ ÌWÉ 16

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 6, 193

OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11

Kí ni ìwà títọ́? Kí nìdí tí ìwà títọ́ fi ṣe pàtàkì tó bẹ́ẹ̀? Báwo la ṣe lè ní ìwà títọ́, kí la sì lè ṣe tí kò fi ní bọ́ mọ́ wa lọ́wọ́? Ṣó ṣeé ṣe kẹ́ni tó ti sọ ìwà títọ́ nù tún rí i pa dà? Ìdáhùn sáwọn ìbéèrè wọ̀nyí àtàwọn míì tó fara pẹ́ ẹ wà nínú àwọn àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 12 sí 16

Ipa tó ṣàrà ọ̀tọ̀ ni Jésù kó nínú mímú ìfẹ́ Ọlọ́run ṣẹ. Àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé àwọn orúkọ oyè mẹ́fà tó ṣẹ mọ́ Jésù lára. Àwọn orúkọ oyè wọ̀nyí sì jẹ́ ká mọ̀ pé ẹni àrà ọ̀tọ̀ ni Jésù. A tún máa kẹ́kọ̀ọ́ látinú ohun tí Jésù máa ń ṣe láti bójú tó ojúṣe àrà ọ̀tọ̀ tó ní.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 16 sí 20

Tá a bá ṣàyẹ̀wò ohun tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ fáwọn alàgbà ìjọ tó wà ní Éfésù, bó ṣe wà nínú ìwé Ìṣe orí 20, ó máa ràn wá lọ́wọ́ láti rí ohun tó ṣe kó bàa lè jẹ́rìí kúnnákúnná. A tún máa rí ẹ̀kọ́ kọ́ nípa ohun tá a lè ṣe láti jẹ́rìí kúnnákúnná sí ìhìn rere àti ìdí tó fi yẹ ká ṣe bẹ́ẹ̀.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:

Àwọn Wàláà Ayé Àtijọ́ àti Bíbélì

OJÚ ÌWÉ 21

Mo Ti Rí Báwọn Èèyàn Ọlọ́run Ṣe Ń Pọ̀ Sí I Lórílẹ̀-Èdè Kòríà

OJÚ ÌWÉ 23

Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè—Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jòhánù Kìíní, Jòhánù Kejì, Jòhánù Kẹta àti Ìwé Júúdà

OJÚ ÌWÉ 27

Ǹjẹ́ O Rántí?

OJÚ ÌWÉ 30

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ Ọdún 2008

OJÚ ÌWÉ 31

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

OJÚ ÌWÉ 32

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́