Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 15, 2009
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
April 6-12
Bí Ọ̀rọ̀ Jésù Ṣe Lè Sọni Di Aláyọ̀
OJÚ ÌWÉ 6
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 57, 36
April 13-19
Máa Tẹ̀ Lé Ọ̀rọ̀ Jésù Nínú Ìwà àti Ìṣe Rẹ
OJÚ ÌWÉ 10
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 106, 132
April 20-26
Ǹjẹ́ O Máa Ń Tẹ̀ Lé Ọ̀rọ̀ Jésù Tó O Bá Ń Gbàdúrà?
OJÚ ÌWÉ 15
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 88, 161
April 27–May 3
Wọ́n “Ń Tọ Ọ̀dọ́ Àgùntàn Náà Lẹ́yìn Ṣáá”
OJÚ ÌWÉ 24
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 213, 53
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 sí 3 OJÚ ÌWÉ 6 sí 19
Nígbà tí Jésù parí “àsọjáde” rẹ̀ nínú Ìwàásù Lórí Òkè, “ìyọrísí rẹ̀ ni pé háà ń ṣe ogunlọ́gọ̀ sí ọ̀nà ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀.” (Mát. 7:28) Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun tó mú kí ẹnu ya àwọn tó gbọ́ ìwàásù yẹn, kó o sì rí bí àwọn ọ̀rọ̀ tó sọ ṣe lè sọ ọ́ di aláyọ̀ àti bó o ṣe lè máa tẹ̀ lé àwọn ọ̀rọ̀ rẹ̀ nínú ìwà àti ìṣe rẹ, àti nínú àdúrà rẹ.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 24 sí 28
Kristi ti yan “ẹrú olóòótọ́ àti olóye” sípò “lórí gbogbo àwọn nǹkan ìní rẹ̀.” (Mát. 24:45-47) Àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé àwọn ìdí tó fi yẹ ká fọkàn tán ẹrú náà àti ọ̀nà tá a lè gbà fi hàn pé a fọkàn tán an.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè—Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ìṣípayá—Apá Kejì
OJÚ ÌWÉ 3
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kó O Máa Rin Kinkin Mọ́ Ohun Tó Bá Ṣáà Ti Wù Ọ́?
OJÚ ÌWÉ 19
A Rọ Àwọn Míṣọ́nnárì Pé Kí Wọ́n Dà Bíi Jeremáyà
OJÚ ÌWÉ 22
Ìsìnkú Kristẹni—Kó Wà Níwọ̀ntúnwọ̀nsì, Kó Lọ́wọ̀, Kó Dára Lójú Ọlọ́run
OJÚ ÌWÉ 29