ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w09 3/15 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
  • OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
w09 3/15 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

March 15, 2009

Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:

May 4-10

Tẹjú Mọ́ Èrè Náà

OJÚ ÌWE 11

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 222, 15

May 11-17

‘Ẹ Wà Lójúfò’

OJÚ ÌWE 15

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 199, 129

May 18-24

Ẹ Jẹ́ Kí Gbogbo Wa Jọ Yin Jèhófà

OJÚ ÌWE 20

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 136, 169

May 25-31

Àwọn Olódodo Yóò Máa Yin Ọlọ́run Títí Láé

OJÚ ÌWE 24

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 48, 165

OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 11 sí 19

Àpilẹ̀kọ méjèèjì rán wa létí ìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká tẹjú mọ́ èrè tí Ọlọ́run nawọ́ rẹ̀ sí wa. Bá a ó ṣe máa gbé àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ gbankọgbì tó wà níwájú yẹ̀ wò, yóò fún wa níṣìírí láti wà lójúfò.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 àti 4 OJÚ ÌWÉ 20 sí 28

Àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí jíròrò Sáàmù 111 àti 112 tó tan mọ́ra. Kíyè sí i pé ńṣe ni Sáàmù 111 yin Jèhófà fún àwọn iṣẹ́ àrà rẹ̀ àtàwọn ànímọ́ rẹ̀. Sáàmù 112 sì jẹ́ ká rí bó ṣe yẹ káwọn iṣẹ́ àrà Jèhófà máa mú wa bẹ̀rù láti ṣe ohun tó máa bí Jèhófà nínú, ó sì tún jẹ́ ká mọ bí àwa náà ṣe lé ní àwọn ànímọ́ rẹ̀ tó fani mọ́ra.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:

“Áńgẹ́lì Jèhófà Dó Yí Àwọn Tí Ó Bẹ̀rù Rẹ̀ Ká”

OJÚ ÌWÉ 3

Ìwọ Kò Gbọ́dọ̀ Gbàgbé Jèhófà

OJÚ ÌWÉ 6

Báwo Lo Ṣe Lè Máa Fi Ìfaradà Ṣe Iṣẹ́ Ìwàásù Lọ?

OJÚ ÌWÉ 29

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

OJÚ ÌWÉ 32

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́