Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April 1, 2009
Kí Ló Túmọ̀ sí Láti Di Àtúnbí?
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Ṣé Dandan Ni Kéèyàn Di Àtúnbí Kó Tó Lè Nígbàlà?
5 Báwo Ló Ṣe Ṣe Pàtàkì Tó Láti Di Àtúnbí?
5 Ṣéèyàn Fúnra Ẹ̀ Ló Máa Pinnu Póun Fẹ́ Di Àtúnbí?
7 Kí Nìdí Táwọn Kan Fi Ní Láti Di Àtúnbí?
8 Báwo Lèèyàn Ṣe Lè Di Àtúnbí?
10 Kí Ni Dídi Àtúnbí Máa Jẹ́ Kó Ṣeé Ṣe?
11 Ìwọ̀nba Làwọn Tó Máa Ṣàkóso, Ọ̀pọ̀ Ló Máa Jàǹfààní
13 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
20 Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Yè Lédè Tó Ń Kú Lọ
24 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Ẹgbẹ́ Búburú Ò Jẹ́ Kí Jèhóáṣì Sin Jèhófà Mọ́
27 Ṣé Ààwẹ̀ Gbígbà Ló Máa Jẹ́ Kó O Sún Mọ́ Ọlọ́run?
30 Àwọn Aláṣẹ Ìjọ Kátólíìkì Fẹ́ Pa Orúkọ Ọlọ́run Rẹ́
32 Àkànṣe Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—Ó Kọ́ Béèyàn Ṣe Lè Jẹ́ Aláàánú
OJÚ ÌWÉ 14
Sún Mọ́ Ọlọ́run—Bàbá Àwọn Ọmọ Aláìníbaba
OJÚ ÌWÉ 31