Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April 15, 2009
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
June 1-7
OJÚ ÌWÉ 3
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 197, 41
June 8-14
Ìwà Títọ́ Rẹ Ń Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 160, 138
June 15-21
Àwọn Ìṣẹ̀dá Jèhófà Ń Fi Ọgbọ́n Rẹ̀ Hàn
OJÚ ÌWÉ 15
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 79, 84
June 22-28
Bá A Ṣe Lè Mọyì Jésù Tó Jẹ́ Mósè Títóbi Jù
OJÚ ÌWÉ 24
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 205, 150
June 29–July 5
Bá A Ṣe Lè Mọyì Jésù Tó Jẹ́ Dáfídì àti Sólómọ́nì Títóbi Jù
OJÚ ÌWÉ 28
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 168, 209
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá a Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11
Àwọn àpilẹ̀kọ yìí jíròrò ìdí tí Jèhófà fi gbà kí Sátánì mú oríṣiríṣi àdánwò bá Jóòbù àti ohun tó ran Jóòbù lọ́wọ́ láti pa ìwà títọ́ rẹ̀ mọ́. Wọ́n tún ṣàlàyé bí àwa náà ṣe lè dà bíi Jóòbù, ká jẹ́ adúróṣinṣin, ká sì tipa bẹ́ẹ̀ mú ọkàn Jèhófà yọ̀.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 15 sí 19
Àwọn ìṣẹ̀dá Jèhófà jẹ́ ká rí onírúurú ànímọ́ rẹ̀. Tá a bá ń ṣàṣàrò lórí ohun tó dá, a óò rí ọ̀pọ̀ ẹ̀kọ́ ṣíṣeyebíye kọ́. Gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ, a ó jíròrò ohun mẹ́rin tí Jèhófà dá àti ẹ̀kọ́ tá a lè rí kọ́ lára wọn nínú àpilẹ̀kọ yìí.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 àti 5 OJÚ ÌWÉ 24 sí 32
Àwọn ìtàn Bíbélì nípa àwọn olóòótọ́ èèyàn tó ti gbé ṣáájú kí Jésù tó wá sáyé jẹ́ ká rí àwọn ọ̀nà pàtàkì kan tí ìgbésí ayé àwọn ẹni náà àti ti Jésù fi jọra. Nínú àpilẹ̀kọ méjì yìí, a óò jíròrò nípa Mósè, Dáfídì àti Sólómọ́nì, a ó sì rí bí ìtàn ìgbésí ayé wọn ṣe lè jẹ́ ká túbọ̀ mọrírì ipa tí Jésù kó nínú mímú ìfẹ́ Ọlọ́run ṣẹ.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé—Ṣé ọmọ inú oyún tó kú sínú ìyá rẹ̀ máa ní àjíǹde?
OJÚ ÌWÉ 12
OJÚ ÌWÉ 14
Ṣé O Lè Lọ Sìn Níbi Tí Wọ́n Ti Nílò Oníwàásù Púpọ̀ Sí I?
OJÚ ÌWÉ 20