Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
June 15, 2009
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
August 3-9
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 31, 118
August 10-16
OJÚ ÌWÉ 11
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 30, 181
August 17-23
OJÚ ÌWÉ 16
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 192, 170
August 24-30
Olùṣòtítọ́ Ìríjú Náà àti Ìgbìmọ̀ Olùdarí Rẹ̀
OJÚ ÌWÉ 20
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 51, 114
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 7 sí 15
Àwọn ọba Júdà mẹ́rin kan wà tí wọ́n dá yàtọ̀ fún bí wọ́n ṣe fìtara ṣètìlẹ́yìn fún ìjọsìn tòótọ́. Kí la lè rí kọ́ lára wọn tó bá dọ̀rọ̀ bá a ṣe ń fìtara sin Jèhófà? A máa gbádùn àwọn àpilẹ̀kọ yìí gan-an ni, wọ́n sì máa tọ́ wa sọ́nà.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 16 sí 20
Ojoojúmọ́ la máa ń bára wa nínú àwọn ipò kan tó ti máa ń dà bíi pé kéèyàn sọ ohun tí kì í ṣòótọ́ ló rọrùn jù, tó sì dáa jù. Ìgbà míì sì wà tó máa ń dà bíi pé téèyàn bá parọ́ ló máa fi onítọ̀hún hàn gẹ́gẹ́ bí ẹni tó lójú àánú. Kí nìdí táwọn Kristẹni tòótọ́ fi gbọ́dọ̀ yẹra fún ohunkóhun tó lè mú kí wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀? Kí ló sì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ lórí kókó yìí?
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 20 sí 24
Àwọn èèyàn Ọlọ́run máa ń bọ̀wọ̀ fún ẹgbẹ́ ẹrú olóòótọ́ àti olóye gan-an ni. Àmọ́, kí ni ìyàtọ̀ tó wà láàárín ẹgbẹ́ yẹn lápapọ̀ àti Ìgbìmọ̀ Olùdarí? Kí sì ni Ìwé Mímọ́ jẹ́ ká mọ̀ nípa bí Jèhófà ṣe ń pèsè oúnjẹ tẹ̀mí fún wa lóde òní? Bákan náà, ojú wo ló yẹ ká máa fi wo àwọn tó ń jẹ ohun ìṣàpẹẹrẹ lákòókò Ìrántí Ikú Kristi? Àpilẹ̀kọ yìí tànmọ́lẹ̀ sáwọn ìbéèrè yìí.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Kí Ni Mo Lè San Pa Dà fún Jèhófà?
OJÚ ÌWÉ 3
Bó O Ṣe Lè Láyọ̀ Láìlọ́kọ Tàbí Aya
OJÚ ÌWÉ 25
Fífaṣẹ́lénilọ́wọ́—Kí Nìdí Tó Fi Ṣe Pàtàkì Báwo Ló sì Ṣe Yẹ Ká Ṣe É?
OJÚ ÌWÉ 28
OJÚ ÌWÉ 32