Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July 15, 2009
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
August 31–September 6
Bá A Ṣe Lè Rí Ìṣúra Tá A Rọra Fi Pa Mọ́ Sínú Kristi
OJÚ ÌWÉ 3
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 121, 105
September 7-13
Ẹ̀yin Ìdílé Kristẹni Ẹ Máa Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù!
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 205, 158
September 14-20
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù Máa Kọ́ni Pẹ̀lú Ìfẹ́
OJÚ ÌWÉ 15
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 156, 215
September 21-27
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù Máa Fìgboyà Wàásù
OJÚ ÌWÉ 19
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 92, 148
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 OJÚ ÌWÉ 3 sí 7
Jèhófà ké sí gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé kí wọ́n wá ìṣúra tí kò láfiwé tá a rọra fi pa mọ́ sínú Kristi. Kí làwọn ìṣúra yìí? Báwo la ṣe lè rí wọn? Àǹfààní wo ni wọ́n máa ṣe fún wa? Àpilẹ̀kọ yìí á ràn wá lọ́wọ́ láti rí ìdáhùn.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 2 OJÚ ÌWÉ 7 sí 11
Láti ìgbà ìṣẹ̀dá ni Jésù ti nífẹ̀ẹ́ tó jinlẹ̀ sí ire ẹ̀dá èèyàn. Àpilẹ̀kọ yìí jíròrò báwọn ẹ̀kọ́ Jésù àti àpẹẹrẹ tó fi lélẹ̀ nígbà tó wà lórí ilẹ̀ ayé ṣe lè ran gbogbo wa lọ́wọ́ láti ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú ìdílé wa.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 àti 4 OJÚ ÌWÉ 15 sí 23
Kí ló mú kí Jésù jẹ́ olùkọ́ tí ọ̀rọ̀ rẹ̀ wọni lọ́kàn? Ohun tó fà á ni pé, ó nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ó nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn, ó sì nífẹ̀ẹ́ sí ohun tó wàásù. Ìfẹ́ ló mú kó fìgboyà wàásù nígbà táwọn èèyàn ń ta kò ó. Àpilẹ̀kọ yìí máa jíròrò bá a ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù, táwa náà á fi jẹ́ olùkọ́ tó nífẹ̀ẹ́, tó sì ń fìgboyà wàásù.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ǹjẹ́ Ò Ń Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ ‘Ọ̀nà Ìfẹ́ Títayọ Ré Kọjá’?
OJÚ ÌWÉ 12
Àádọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn Ni Mo Bẹ̀rẹ̀ Sí Í ‘Rántí Ẹlẹ́dàá Mi Atóbilọ́lá’
OJÚ ÌWÉ 24
Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Ń Mú Ìtẹ̀síwájú Wá
OJÚ ÌWÉ 28
Máa Fi Ìmoore Hàn Kó O sì Máa Fúnni Tọkàntọkàn
OJÚ ÌWÉ 29
Irúgbìn Òtítọ́ Dé Àwọn Ibi Jíjìnnà Réré
OJÚ ÌWÉ 32