Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 1, 2009
Báwo Lo Ṣe Lè Mọ Ìsìn Tòótọ́?
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Ṣé Gbogbo Ìsìn ni Ìsìn Tòótọ́?
5 Ìsìn Tòótọ́ Ń Kọ́ni Láti Máa Fọwọ́ Pàtàkì Mú Ìlànà Ọlọ́run
6 Ìsìn Tòótọ́ Ń Kọ́ni Láti Máa Fọwọ́ Pàtàkì Mú Ìlànà Ọlọ́run
8 Ìsìn Tòótọ́ Ń Kọ́ni Láti Máa Bọ̀wọ̀ fún Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
13 Ṣó O Máa Ń Jẹ́ Kí Ọlọ́run Bá Ẹ Sọ̀rọ̀ Lójoojúmọ́?
24 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Ráhábù Fi Ohun Tó Gbọ́ Sọ́kàn
26 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Ọlọ́kàn Tútù
27 Bíbélì Máa Ń Sọni Dèèyàn Rere
30 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé—Èló Ni Kí N Fi Ṣètọrẹ fún Iṣẹ́ Ọlọ́run?
31 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Máa Ṣọ́wó Ná
OJÚ ÌWÉ 10
Ohun Tá A Kọ́ Lọ́dọ̀ Jésù—Nípa Ọjọ́ Ọ̀la Aráyé
OJÚ ÌWÉ 22