ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w09 8/15 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
  • Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
w09 8/15 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

August 15, 2009

Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:

September 28–October 4

Ọlọ́run Ló Fún Aráyé Ní Ìrètí Ìyè Àìnípẹ̀kun Lórí Ilẹ̀ Ayé

OJÚ ÌWÉ 3

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 76, 222

October 5-11

Ṣé Ìyè Àìnípẹ̀kun Lórí Ilẹ̀ Ayé Jẹ́ Ìrètí Tó Wà Fáwọn Kristẹni?

OJÚ ÌWÉ 7

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 187, 15

October 12-18

Bí Ìrètí Ìyè Àìnípẹ̀kun Lórí Ilẹ̀ Ayé Ṣe Pa Dà Wá Sójú Táyé

OJÚ ÌWÉ 12

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 4, 220

October 19-25

‘Ẹ Dúró Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run’

OJÚ ÌWÉ 18

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 114, 85

Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 sí 3 OJÚ ÌWÉ 3 sí 16

Àwọn àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé ohun tí Ìwé Mímọ́ sọ nípa ìrètí ìyè àìnípẹ̀kun lórí ilẹ̀ ayé. Àwọn àpilẹ̀kọ yìí á jẹ́ kí ìrètí tó fìyàtọ̀ sáàárín àwa Kristẹni tòótọ́ àtàwọn oníṣọ́ọ̀ṣì yìí túbọ̀ dá ọ lójú. Ìgbàgbọ́ rẹ yóò lágbára sí i, èyí á sì jẹ́ kó o máa láyọ̀ nígbà gbogbo, á sì tún jẹ́ kó o nígboyà láti sọ̀rọ̀ nípa ìrètí tó o ní fáwọn ẹlòmíì.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 18 sí 22

Àpilẹ̀kọ yìí jíròrò ọ̀nà mẹ́ta tá a lè gbà dúró nínú ìfẹ́ Ọlọ́run. (Júúdà 21) A lè ṣe bẹ́ẹ̀ nípa (1) nínífẹ̀ẹ́ àwọn tí Jèhófà fẹ́ràn, (2) bíbọ̀wọ̀ fáwọn aláṣẹ àti (3) sísapá láti wà ní mímọ́ lójú Jèhófà.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:

Ó Rí Àwọn Ìṣúra Tó Wà ní Ìpamọ́

OJÚ ÌWÉ 16

Ǹjẹ́ O Rántí?

OJÚ ÌWÉ 23

‘Jèhófà Ti Mú Kí Ojú Rẹ̀ Tàn sí Wọn Lára’

OJÚ ÌWÉ 24

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọkàn Rẹ Pínyà ní “Ọjọ́ Ìhìn Rere” Yìí

OJÚ ÌWÉ 28

Ṣé O Ti Sìn Nígbà Kan Rí? Ǹjẹ́ O Tún Lè Sìn Lẹ́ẹ̀kan Sí I?

OJÚ ÌWÉ 30

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́