Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 1, 2009
Kí Ni Ẹ̀mí Mímọ́?
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Kí Nìdí Tí Èrò Àwọn Èèyàn Kò Fi Ṣọ̀kan Lórí Ẹ̀mí Mímọ́?
6 Ẹ̀mí Mímọ́ Jẹ́ Agbára Tó O Nílò Nígbèésí Ayé Rẹ
10 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Kí Ni Jèhófà Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?
11 Ṣó Ṣeé Ṣe Láti Nígbàgbọ́ Nínú Ẹlẹ́dàá?
16 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Ṣémù Rí Ìwà Ìbàjẹ́ Tó Wà Láyé Ṣáájú àti Lẹ́yìn Ìkún-Omi
18 Kí Nìdí Tí Ìwé Àfọwọ́kọ Vatican Fi Ṣeyebíye?
25 Iṣẹ́ Ẹja Pípa Lórí Òkun Gálílì
28 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—Ó Gbógun Ti Ìbẹ̀rù àti Iyèméjì
OJÚ ÌWÉ 21
Ṣó Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Máa Jagun?
OJÚ ÌWÉ 29