Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 15, 2009
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
November 30–December 6
‘Ẹ Jẹ́ Kí Iná Ẹ̀mí Máa Jó Nínú Yín’
OJÚ ÌWÉ 3
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 191, 177
December 7-13
“Ẹ Jẹ́ Ẹlẹ́mìí Àlàáfíà Pẹ̀lú Gbogbo Ènìyàn”
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 159, 206
December 14-20
OJÚ ÌWÉ 13
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 224, 217
December 21-27
Bá A Ṣe Lè Máa Ṣe Ọ̀rẹ́ Nínú Ayé Aláìnífẹ̀ẹ́ Yìí
OJÚ ÌWÉ 17
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 173, 155
OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11
Àwọn àpilẹ̀kọ yìí jíròrò Róòmù 12 lẹ́sẹẹsẹ bí àwọn ẹ̀kọ́ tó wà nínú rẹ̀ ṣe tẹ̀ léra. A máa ṣàgbéyẹ̀wò ohun tó túmọ̀ sí láti jẹ́ “kí iná ẹ̀mí máa jó nínú” ẹni àti bí a ṣe lè fi ara wa fún Ọlọ́run gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ààyè. A tún máa kọ́ nípa bá a ṣe lè jẹ́ ẹlẹ́mìí àlàáfíà nínú ilé àti nínú ìjọ, a ó sì rí àwọn ọ̀nà tá a lè gbà fi ire ṣẹ́gun ibi.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 àti 4 OJÚ ÌWÉ 13 sí 21
Báwo lèèyàn ṣe lè jẹ́ ọ̀rẹ́ àtàtà? Àwọn àpilẹ̀kọ yìí yóò jẹ́ ká rí bí Jésù ṣe fi àpẹẹrẹ tó dára lélẹ̀ lórí ọ̀ràn yìí àti báwọn Kristẹni ọ̀rúndún kìíní ṣe tẹ̀ lé àpẹẹrẹ rẹ̀. Àwọn àpilẹ̀kọ náà yóò tún ṣàlàyé ìdí tó fi ṣàǹfààní fún wa láti yan àwọn ọ̀rẹ́ tó máa gbé wa ró tí àjọṣe àárín wa sì máa lágbára àti bá a ṣe lè yan irú àwọn ọ̀rẹ́ bẹ́ẹ̀ lónìí.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
OJÚ ÌWÉ 12
Bí Àpéjọ Mẹ́ta Ṣe Yí Ìgbésí Ayé Mi Pa Dà
OJÚ ÌWÉ 22
Ṣé O ‘Ta Gbòǹgbò Tó O sì Fìdí Múlẹ̀ Lórí Ìpìlẹ̀ Náà’?
OJÚ ÌWÉ 26
Ìjọsìn Ìdílé Ṣe Pàtàkì fún Ìgbàlà Ìdílé Wa!
OJÚ ÌWÉ 29
Ǹjẹ́ O Ti Ya Àkókò Kan Sọ́tọ̀ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?
OJÚ ÌWÉ 32