ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w09 11/1 ojú ìwé 32
  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
w09 11/1 ojú ìwé 32

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

◼ Ṣé òótọ́ ni pé gbogbo èèyàn rere ló ń lọ sí ọ̀run? Wo ojú ìwé 6.

◼ Ṣé òótọ́ ni pé Màríà ni “Ìyá Ọlọ́run”? Wo ojú ìwé 8.

◼ Kí ni èrò Ọlọ́run nípa lílo ère àti àwòrán nínú ìjọsìn? Wo ojú ìwé 9.

◼ Kí ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí ọkọ tàbí aya rẹ bá ń ṣàìsàn tàbí tó fara pa? Wo ojú ìwé 10 sí 12.

◼ Ṣé àwọn ọ̀rọ̀ tó wà nínú Bíbélì ti yí pa dà ni? Wo ojú ìwé 13 àti 14.

◼ Kí ni ẹnì kọ̀ọ̀kan nínú ìdílé lè ṣe láti mú kí ìdílé jẹ́ aláyọ̀? Wo ojú ìwé 16 àti 17.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́