November 1 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ẹ̀kọ́ Èké Kan Ló Ń Fa Òmíràn Ẹ̀kọ́ Èké Kìíní: Ẹ̀mí Èèyàn Kì Í Kú Ẹ̀kọ́ Èké Kejì: Àwọn Èèyàn Burúkú Ń Joró Ní Ọ̀run Àpáàdì Ẹ̀kọ́ Èké Kẹta: Gbogbo Èèyàn Rere Ló Ń Lọ Sí Ọ̀run Ẹ̀kọ́ Èké Kẹrin: Ọlọ́run Jẹ́ Mẹ́talọ́kan Ẹ̀kọ́ Èké Karùn-ún: Màríà Ni Ìyá Ọlọ́run Ẹ̀kọ́ Èké Kẹfà: Ọlọ́run Fọwọ́ Sí Lílo Ère Àti Àwòrán Nínú Ìjọsìn Bí Ọkọ Tàbí Aya Rẹ Bá Nílò Àbójútó Àrà Ọ̀tọ̀ Ìtàn Tó Gbàfiyèsí Nípa Bí Bíbélì Kò Ṣe Pa Run Ǹjẹ́ O Mọ̀? Nípa Ìgbésí Ayé Ìdílé Bí Wọ́n Ṣe Pàdánù Párádísè Ṣé Ẹlẹ́sìn Pùròtẹ́sítáǹtì Ni Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà? Ṣó Pọn Dandan Kó O Kọ́ Èdè Hébérù àti Gíríìkì? Ìhìn Rere Ní Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta Èdè Bíbélì Máa Ń Sọni Dèèyàn Rere Jèhófà Fún Wa Lómìnira Láti Yan Ohun Tó Wù Wá Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá?