Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 1, 2009
Àṣírí Tú Ẹ̀kọ́ Èké Mẹ́fà Tí Wọ́n Mú Wọnú Ìsìn Kristẹn
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Ẹ̀kọ́ Èké Kan Ló Ń Fa Òmíràn
4 Ẹ̀kọ́ Èké Kìíní: Ẹ̀mí Èèyàn Kì Í Kú
5 Ẹ̀kọ́ Èké Kejì: Àwọn Èèyàn Burúkú Ń Joró Ní Ọ̀run Àpáàdì
6 Ẹ̀kọ́ Èké Kẹta: Gbogbo Èèyàn Rere Ló Ń Lọ sí Ọ̀run
7 Ẹ̀kọ́ Èké Kẹrin: Ọlọ́run Jẹ́ Mẹ́talọ́kan
8 Ẹ̀kọ́ Èké Karùn-ún: Màríà Ni Ìyá Ọlọ́run
9 Ẹ̀kọ́ Èké Kẹfà: Ọlọ́run Fọwọ́ Sí Lílo Ère Àti Àwòrán Nínú Ìjọsìn
13 Ìtàn Tó Gbàfiyèsí Nípa Bí Bíbélì Kò Ṣe Pa Run
15 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
16 Ohun Tá A Kọ́ Lọ́dọ̀ Jésù—Nípa Ìgbésí Ayé Ìdílé
18 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Bí Wọ́n Ṣe Pàdánù Párádísè
20 Ṣó Pọn Dandan Kó O Kọ́ Èdè Hébérù àti Gíríìkì?
24 Ìhìn Rere Ní Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta Èdè
26 Bíbélì Máa Ń Sọni Dèèyàn Rere
31 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Jèhófà Fún Wa Lómìnira Láti Yan Ohun Tó Wù Wá
Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Bí Ọkọ Tàbí Aya Rẹ Bá Nílò Àbójútó Àrà Ọ̀tọ̀
OJÚ ÌWÉ 10