ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w09 11/15 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
  • OHun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
w09 11/15 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

November 15, 2009

Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:

December 28–January 3

Kí Ni Àdúrà Rẹ Ń Sọ Nípa Rẹ?

OJÚ ÌWÉ 3

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 161, 45

January 4-10

Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Láti Mú Kí Àdúrà Rẹ Sunwọ̀n Sí I

OJÚ ÌWÉ 7

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 188, 88

January 11-17

Mọyì Ojúṣe Rẹ Nínú Ìjọ

OJÚ ÌWÉ 13

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 213, 55

January 18-24

Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Tó O Ní Fáwọn Ará Máa Pọ̀ Sí I

OJÚ ÌWÉ 20

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 200, 115

January 25-31

Bá A Ṣe Lè Máa Hùwà Tó Bójú Mu Gẹ́gẹ́ Bí Òjíṣẹ́ Ọlọ́run

OJÚ ÌWÉ 24

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 34, 86

OHun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11

Àpilẹ̀kọ kìíní fún ìkẹ́kọ̀ọ́ yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣàyẹ̀wò bó o ṣe ń gbàdúrà sí Jèhófà. Àpilẹ̀kọ kejì lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti mọ àwọn ọ̀nà tó o lè gbà mú kí àdúrà rẹ sunwọ̀n sí i torí pé ó máa mú kó o fara balẹ̀ ṣàyẹ̀wò àwọn àdúrà kan nínú Bíbélì, èyí táwọn kan fi tọrọ nǹkan àti èyí tí wọ́n fi yin Ọlọ́run tí wọ́n sì fi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 13 sí 17

Olúkúlùkù àwa Kristẹni ló ní ojúṣe àti àyè tirẹ̀ nínú ètò tí Jèhófà ṣe fún ìjọsìn tòótọ́. Àpilẹ̀kọ yìí jíròrò oríṣiríṣi ọ̀nà tá a lè gbà fi hàn pé a mọyì ojúṣe wa nínú ìjọ Ọlọ́run.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 àti 5 OJÚ ÌWÉ 20 sí 29

Ó ṣe pàtàkì pé ká máa lo ìfẹ́ ará kí ìṣọ̀kan bàa lè máa wà nínú ìjọ. Tá a bá sì ń hùwà tó bójú mu, ó máa ṣàǹfààní fún wa lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa. Àwọn àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí sọ bá a ṣe lè kógo já nínú apá méjèèjì yìí ní ìgbésí ayé wa.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

OJÚ ÌWÉ 12

Fífúnni Ní Nǹkan Látọkàn Wá

OJÚ ÌWÉ 18

Ọmọdébìnrin Tó Jẹ́ Ọ̀làwọ́

OJÚ ÌWÉ 29

Máa Ṣìkẹ́ Àwọn Arákùnrin àti Arábìnrin Rẹ Tó Jẹ́ Adití!

OJÚ ÌWÉ 30

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́