Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
December 1, 2009
Máa Fòpin Sí Gbogbo Ìjìyà! Nígbà Wo? Báwo Sì Ni?
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 “Yóò Ti Pẹ́ Tó . . . Tí Èmi Yóò Fi Kígbe fún Ìrànlọ́wọ́?”
4 Báwo La Ṣe Mọ̀ Pé Lóòótọ́ Ni Ọlọ́run Bìkítà fún Wa?
5 Ojútùú Tó Kárí Ayé sí Ìṣòro Tó Kárí Ayé
8 “Àkókò Tí A Yàn Kalẹ̀” Ti Sún Mọ́lé
9 Bí Àwọn Èèyàn Ṣe Rí Ìtùnú Gbà Lẹ́yìn Ìpakúpa Tó Wáyé Lọ́gbà Iléèwé Kan
16 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
17 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ó Fẹ́ Ká Ṣàṣeyọrí
18 Lẹ́tà Láti Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà
24 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Jeremáyà Kò Jáwọ́ Nínú Ṣíṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run
26 Ọwọ́ Tí Dáfídì Ọba Fi Mú Orin Kíkọ
OJÚ ÌWÉ 13
Ṣó Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Máa Ṣayẹyẹ Ọdún Tuntun?
OJÚ ÌWÉ 20