Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
December 15, 2009
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
February 1-7
Jẹ́ Kí Ìlọsíwájú Rẹ Máa Fara Hàn Kedere
OJÚ ÌWÉ 11
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 123, 43
February 8-14
Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìṣòro Ba Ayọ̀ Rẹ Jẹ́
OJÚ ÌWÉ 15
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 19, 130
February 15-21
Mèsáyà! Ọ̀nà Ìgbàlà Tí Ọlọ́run Pèsè
OJÚ ÌWÉ 20
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 105, 205
February 22-28
OJÚ ÌWÉ 24
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 35, 89
OHun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 11 sí 19
Gbogbo àwa Kristẹni, lọ́kùnrin, lóbìnrin, lọ́mọdé, lágbà la lè mú kí ìlọsíwájú wa nípa tẹ̀mí máa fara hàn kedere. Àwọn àpilẹ̀kọ yìí jíròrò bá a ṣe lè ṣe é. A tún máa ṣàgbéyẹ̀wò bí a ó ṣe máa ṣe nígbà ìṣòro tí ayọ̀ wa kò fi ní bà jẹ́.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 20 sí 24
Ọ̀pọ̀ ẹ̀rí ló wà nínú Bíbélì tó fi hàn pé Jésù ni Mèsáyà tí Ọlọ́run ṣèlérí. Jèhófà rán Ọmọ rẹ̀ wá sáyé láti wá mú gbogbo ẹ̀gàn tó wà lórí orúkọ Ọlọ́run kúrò, kó tún fi hàn pé ó tọ́ bí Jèhófà ṣe jẹ́ Ọba Aláṣẹ kó sì wá ra àwọn tó bá jẹ́ onígbọràn lára ọmọ aráyé pa dà lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú. Àwọn nǹkan tá a rí yìí yẹ kó nípa lórí iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 24 sí 28
Báwo la ṣe lè dẹni tó ní ìfẹ́ Jèhófà àti Jésù? Báwo ni ìfẹ́ ṣe máa ń fara da ohun gbogbo? Ọ̀nà wo la lè gbà sọ pé ìfẹ́ kì í kùnà láé? Àpilẹ̀kọ yìí, tá a gbé karí ẹsẹ Ìwé Mímọ́ ọdún 2010, yóò dáhùn àwọn ìbéèrè yìí.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
OJÚ ÌWÉ 3
Ǹjẹ́ O Lè Ré Kọjá Lọ sí Makedóníà?
OJÚ ÌWÉ 4
O Lè Máa Láyọ̀ Nínú Iṣẹ́ Ọlọ́run Bí Ọwọ́ Rẹ Tiẹ̀ Dí
OJÚ ÌWÉ 8
Bí Bíbélì Ṣe Dé Erékùṣù Madagásíkà
OJÚ ÌWÉ 29
Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2009
OJÚ ÌWÉ 32