Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 15, 2010
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
April 5-11
‘Máa Sọ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Láìṣojo’
OJÚ ÌWÉ 5
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 33, 92
April 12-18
Máa Lo “Idà Ẹ̀mí” Lọ́nà Tó Jáfáfá
OJÚ ÌWÉ 10
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 96, 113
April 19-25
“Ẹ̀mí àti Ìyàwó Ń Bá A Nìṣó ní Sísọ Pé: ‘Máa Bọ̀!’”
OJÚ ÌWÉ 14
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 47, 134
April 26–May 2
Ẹ Káàbọ̀ sí Ọ̀nà Ìgbésí Ayé Tó Dára Jù Lọ!
OJÚ ÌWÉ 24
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 94, 65
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá a Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1 sí 3 OJÚ ÌWÉ 5 sí 18
Àwọn àpilẹ̀kọ yìí jíròrò ipa tí ẹ̀mí mímọ́ ń kó nínú iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa. Wọ́n jẹ́ ká rí bí ẹ̀mí Ọlọ́run tó ń darí wa ṣe ń ràn wá lọ́wọ́ láti sọ̀rọ̀ láìṣojo, ká kọ́ni lọ́nà tó jáfáfá, ká sì máa wàásù déédéé.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 24 sí 28
Ṣíṣe ìfẹ́ Jèhófà àti títẹ́tí sí Jésù ni ọ̀nà ìgbésí ayé tó dára jù lọ. Àpilẹ̀kọ yìí jẹ́ ká rí àwọn ìbùkún táwọn tó ya ara wọn sí mímọ́ fún Ọlọ́run tí wọ́n sì ṣèrìbọmi ń gbádùn. Ó tún ṣàlàyé ohun tá a gbọ́dọ̀ ṣe tá ò fi ní yẹsẹ̀ kúrò nínú òtítọ́.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ǹjẹ́ O Ka Jèhófà sí Bàbá Rẹ? 3
Máa Dènà Ìpolongo Èké Sátánì 19
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé 22
“Ẹ̀tọ́ Àwọn Ọmọdé Láti Mọ Ọlọ́run” 29
Ìwé Táá Jẹ́ Káwọn Ọ̀dọ́ Rántí Ẹlẹ́dàá Wọn 30