Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
March 15, 2010
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
May 3-9
A Batisí Wọn ní Orúkọ Baba, Ọmọ àti Ẹ̀mí Mímọ́
OJÚ ÌWÉ 10
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 58, 59
May 10-16
Máa Rìn Nípa Ẹ̀mí Kó O sì Mú Ẹ̀jẹ́ Ìyàsímímọ́ Rẹ Ṣẹ
OJÚ ÌWÉ 14
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 63, 51
May 17-23
“Àwọn Olódodo Yóò Máa Tàn Yòò Bí Oòrùn”
OJÚ ÌWÉ 19
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 108, 30
May 24-30
OJÚ ÌWÉ 24
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 99, 125
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá a Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 10 sí 18 ▴
Àwọn àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí máa ràn wá lọ́wọ́ láti lóye bó ti ṣe pàtàkì tó pé ká ṣèrìbọmi “ní orúkọ Baba àti ti Ọmọ àti ti ẹ̀mí mímọ́.” (Mát. 28:19) Wàá rí àwọn ohun tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè máa mú ẹ̀jẹ́ ìyàsímímọ́ rẹ ṣẹ nínú àwọn àpilẹ̀kọ náà.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3 àti 4 OJÚ ÌWÉ 19 sí 28
Nínú àkàwé Jésù nípa àlìkámà àti àwọn èpò, ó ṣàpèjúwe ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí “àwọn ọmọ ìjọba náà” lọ́jọ́ iwájú. Kí ni àlìkámà àti àwọn èpò ṣàpẹẹrẹ? Báwo ni àkàwé yìí ṣe ń ní ìmúṣẹ lọ́jọ́ wa? Ṣé àwọn ẹni àmì òróró nìkan ni àkàwé yìí kàn?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Bá Ò Ṣe Ní Pàdánù Ojúure Ọlọ́run Bí Ìyípadà Bá Tiẹ̀ Dé Bá Wa 3
Máàkù ‘Wúlò fún Iṣẹ́ Ìránṣẹ́’ 6
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé 28
Ní ‘Ọkàn-Àyà Tó Mọ́’ ní Àwọn Àkókò Líle Koko Yìí 30
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Nípasẹ̀ ìyọ̀ọ̀da ibi ìkóhun-ìṣẹ̀ǹbáyé-sí ìlú Ísírẹ́lì, ní Jerúsálẹ́mù